₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,326,208 members, 8,425,474 topics. Date: Friday, 12 June 2026 at 03:06 PM

Toggle theme

Sakius10's Posts

Nairaland ForumSakius10's ProfileSakius10's Posts

1 (of 1 pages)

CultureRe: .. by sakius10: 11:39pm On Jan 30, 2016
Sidiq80:
Baba healthfirst eku ise takun o,eledua agbe yin,ejo moni fesi iwa na .ejo elo ni owo re
baba Eku ise takutaku ti ese ni ori ikoniyi ooooo, ef
unmi ni ogun kanako todaju
CultureRe: .. by sakius10: 1:15pm On Jan 17, 2016
Victorolami:
E seun gan baba healthfirst, awon tolaye yio ma tiyin leyin.... Sugbon mio Mon oruko arakunrin ti oun mu won rin irin ajo yii... ati wipe won ti kuro ni Nigeria ni odo wa nibi won si ti wani DESERT ni orile ede Niger... Ejowo se kosi oun tele bami fii GBE omobinrin yii kuro larin won si ilu towa ni Nigeria nibi... Ojo yin yio dale ooo... Ejowo eran mi lowo.
baba edakun eki fi esi si iberemi ,baba mofi awon toni aye beyi
CultureRe: .. by sakius10: 11:27pm On Jan 16, 2016
autoboy20:
Eseun baba, se mo le ri ata ile na ra ni odo awon elewe omo?
baba mo kin yin lori ise takutaku ti e se lori ikoni yi o,aji nde ara amaje yi o,baba edaku ogun aworo ti ale ri mon lele ilu shop ni mofe ati ogun kalonko todaju,koni tan nibiti eti mu lagbara edumare oo
CultureRe: .. by sakius10: 8:05pm On Jan 14, 2016
[quote author=frenchboy post=41975060]Ko ye mi...ao lu lori.ao gbele...ese pupo[/quote aworo ti aleri mon nu shop ni mofe baba
CultureRe: .. by sakius10: 4:32pm On Jan 14, 2016
healthFirst:
ao po mon ose dudu...wiwe ni.
Baba eku ataro o,efun mi ni ogun arimanle aworo Ti ale ri si shoop ati kanako ti o daju

1 (of 1 pages)