Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,158,552 members, 7,837,112 topics. Date: Wednesday, 22 May 2024 at 05:12 PM

Shomar's Posts

Nairaland Forum / Shomar's Profile / Shomar's Posts

(1) (2) (of 2 pages)

Culture / Re: .. by Shomar: 11:30am On Dec 29, 2015
Inu mi dun bi mo se wo gbogbo ohun ti o wa lori ikani yi. O wu mi lati fi kun, sugbon mi o ri ohun ti ko si nibi. A mo enikeni le bere ohun ti o ba je tuntun to fe. Mo se ileri pe awon baba ma gbami laye lati fun yin. Iba eyin baba teni ile awo yi o o o. Eyin na ni mo ni ke gbami laye.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by Shomar: 5:56am On Dec 23, 2015
Mokinyin baba. A ku oginitin yi. E dakun mofi Olohun beyin, e ba mi gbo alaye yi, ki e si fun mi ni ise re.
Iyawo ore mi loko awon omo oremi sa kuro nile toni ohun o fe ore mi mo. E jor. Ajo ti yio fi da awon omo yan pada ni an wa.
Culture / Re: .. by Shomar: 12:53pm On Dec 22, 2015
E jor. Eyin Baba mejeeji. Kaduna ati health. E jor sir.
Ti obinrin ba gbe omo wa sa kuro lodo wa, a jo wo la le se. E dakun, e fi se anu fun wa.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by Shomar: 6:44am On Dec 20, 2015
ayokomi1010:
OGUN AROBOKU OKUNRIN TI KOLE BA OBINRIN SUN
AO toju egbo Ajara,ao ge wewe sinu igo kan,ao jo eyin adie ibile 7 si,ao da opolopo omi agbon si,lehin OJO keta ao ma Mu.
Egbo sao,iyere,sugar onikoro die,ao gun papo ao mafi Mu eko gbigbona.
E se sir. E jor, Ajara yen se ohun nani won pe ni Ajarere? Ekeji, botile je pe oruko ilu mi ni Egbo keji n je, iyen Egbo Sao. Kini oruko re mi? Abi sayo ni?
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by Shomar: 6:40am On Dec 20, 2015
E ku ise lopolopo. A jin de ara yio ma je. Amin. Koni su yin se.. Se ao fi omi bo igbin yen ni abi ao yo ni tutu be. Boya ama fo ikarahun ni.
Culture / Re: .. by Shomar: 6:17am On Dec 20, 2015
E jor, ise wo ni alefi jo omo ninu egbe towa?
Culture / Re: .. by Shomar: 3:11pm On Dec 19, 2015
KolaBELIEVE:
ejowo, se ale lo N200 ati N500 fun basiri lekeleke yi?
Eyi ti eyan bani lagbara noni. Amo fun emi o, #1,000 ati #500 ni ma mun.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by Shomar: 8:41am On Dec 19, 2015
ayokomi1010:
OGUN IWOSAN LAGUNLAGUN
ao toju epo igi padoro,odidi atare mejo,orogbo mejo,ako kanhun,ata ijosin,iyere,iyo isebe,ao gun ni agunmu,eko gbigbona niki eniti lagunlagun tabi kokoro inu eje baja,mafi lo kotun gbodo se mo,pelu ase olorun,iba eyin agba o
Baba, E seun gan. Se pandoro ni e tumo si?
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by Shomar: 3:00pm On Dec 18, 2015
Gege bi Oruko yin. Ayo koni won ni ile yin. E jor sir. E fun wa ni ogun lagunlagun todaju.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by Shomar: 11:34pm On Dec 17, 2015
ayokomi1010:
OSOLE OWO NLA
ao toju odidi okete kan ,opolopo ewe ewuro,tagiri odidi kan,Gbogbo owo tane,odidi atare kan,ao jo po ,ao mafi eyin adie ibile je lekan lojumo
gege bi o se ye mi, se ebu die lao ma bu fi din eyin kokan lojojumo abi ni idakureku?

1 Like

Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by Shomar: 9:16pm On Dec 17, 2015
ayokomi1010:
OGUN Ti AFI MADE ONI JALABI MOLE
ao wa ewe omisimisi,ao gun mo ose ao fi ito ti aba ko to laro po,ati ito enuwa toje ti owuro kutu,lehin ti a po tan ,ao ma bu fun Awon to wa sodowa ki o mafiwe,Gbogbo Igba tiwa nikan ni won mari ro..
Baba. E seun fun ise yi.
2)eiyele kan ao la ni aya,ao ko ewe abo 9 si,ati ewe amunimuye die,okun sokoto wa,odidi atare kan,ao jopo,kama funwon lo die die.

1 Like 2 Shares

Culture / Re: .. by Shomar: 11:55am On Dec 17, 2015
healthFirst:
Pls if you are just visiting this thread for the first time but you'd like to either comment or contribute in any way, kindly read the first page about the rules.

No translating the Ogun in English Language
No Phone numbers

In addition, any Oogun Owo, Osole are not allowed and do not post any unverified Oogun.

We do not want anything that would affect the health and spiritual lives of the users. We have noticed some contributors who have being posting incomplete charms but we have warned them to stay away from the thread. What we want is quality and effective Oogun. The only contributor who has being posting reliable Oogun is KadunaSouth but others are just empty trash. Incomplete Oogun have negative impact on people; apart from the fact that it won't work, it'd also waste their money.

Pls adhere strictly to these rules. Thanks.
[img]

[/img]

E FORI JIN MI.

1 Like

Culture / Re: .. by Shomar: 9:47pm On Dec 16, 2015
fbabs:

Kinni o nje Ori Apanri ati oko ataare .
E SEUN
fbabs:

Kinni o nje Ori Apanri ati oko ataare .
E SEUN
fbabs:

Kinni o nje Ori Apanri ati oko ataare .
E SEUN
lizard ati one set out of three set of aligator peper.

2 Likes

Culture / Re: .. by Shomar: 11:44pm On Dec 15, 2015
healthFirst:

Beeni
BABA, lagunlagun nko?
Culture / Re: .. by Shomar: 9:15pm On Dec 15, 2015
healthFirst:
115

EYONU FUN ENIKENI
Ileke itun,
Ileke ifa,
Irun abe obinrin,
Ewe eeyo
Ewe ata ijosi
Iiye agbe,
Iye aluko,
Iko Odide,
Egungun agbari ologbo die,
Awo ijimere

A o jo won papo, a o sun awo ewure ninu ina, a o ha edu ara re sinu ise ti ajo yen, a o wa lo gbogbo re papo, a o da sinu konjo kekere kan, a o fi ori, epo ati lofinda bintu tabi Miss paris sinu re pelu, a o fi iyerosun te ifa OgbeWonrin.

OFORE:
Siju womi, abifa gbuuru, siju womi la npe ifa, abifa gburu la npe esu odara, itun loni ki e fi enu rere tun mi se, ifa loni ki won fenu rere fami mora, ogbo loni ki won mu temi gbo,oro mi ka sai yo won ninu gerere, bi epo bafoju kan oorun ayo gerere, bi adi ba foju kan oorun ayo gerere , bi ori ba foju kan oorun ayo gerere bi awo ba fi oju kanna woranworan agun, bi oloko ba joko bi olobo ba debe a fi aye gba, Orisa sanu agbe o se aso re laro, orisa sanu aluko ose aso re losun, Ao se iwure fun ohun ti a fe.
Ipara abi?

2 Likes

Culture / Re: .. by Shomar: 11:58am On Dec 15, 2015
E fun wa ni ogun Lagunlagun todaju dada
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by Shomar: 11:49pm On Dec 13, 2015
[sup][/sup][color=#000099] Se e ti ti ile yi pa ni?
Culture / Re: .. by Shomar: 9:05pm On Dec 11, 2015
healthFirst:

Opolopo Awure lo ti wa lori abala yi sugbon te ba fe awon Aworo Nla tabi Afaro Nla, e kan si wa lori e-mail.
E Seun Baba. Amo mio ni e-mail yin lowo.
Culture / Re: .. by Shomar: 12:59pm On Dec 09, 2015
E jor sir. Ti customer wa koni fiwa sile. Ajoo wo la le se.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by Shomar: 12:53pm On Dec 09, 2015
Owo ati aponle ni mofi kiyin. E jor sir, ti awon customer wa ko ni fi lo. Tafi mun customer. Efun wa sir.[s][/s]
Culture / Re: .. by Shomar: 7:15pm On Dec 08, 2015
[font=Lucida Sans Unicode][/font]ajatuka ?
Culture / Re: .. by Shomar: 8:05pm On Dec 07, 2015
[color=#990000][/color]moseba awon to laye o. Iba baba, iba yeye. Eyin baba wa mejeeji, Baba health ati Baba kaduna. Ko ni su yin, beeni ko ni reyin. E jor sir. Efi EYONUN OLUGBARE tawa lore. Ti eniyan ba wa ni ibi ise ti won fe pin post kan ti yio fi je teyan. E sanu wa.
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by Shomar: 11:00pm On Dec 05, 2015
ayokomi1010:
OGUN EBE AWON AGBA
obi pupa kan,funfun kan,ewe ata ijosi,ao gun Mo ose ao mawe.
(²) igbin kan,odu ori ewe ahunekun,epo obo,ao gun dada ao fi ose po ao ko sinu aso funfun,wiwe ni odaju
E jor. Kilo nje ''ODU ORI EWE AHUNEKUN''?

2 Likes 1 Share

Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by Shomar: 12:05pm On Dec 05, 2015
[i][/i]Baba, eku ise, edumare yio ma ran yin lowo. E jor sir. Ajegun ati ebe awon agba ni emi nfe.
Culture / Re: .. by Shomar: 11:01am On Dec 05, 2015
[/quote][i][quote author=healthFirst post=40696185]
E seun Baba fun idahun si ibere yi toripe emi na ti bere irufe ibere yi. Siwaju si. Yoruba bo, won ni AGBATAN LA'GBO LE. E jo sir. Irufe IMULE ati EBE wo ni e ma fun wa lati se. Odua a gbe wa si rere o o o
Culture / Re: .. by Shomar: 10:55am On Dec 05, 2015
[color=#000099][/color]
healthFirst:

E lo ma koko lo Ajeegun na ki e to se oogun kankan. Sugbon to ba je wipe awon agba ni o je ki oogun je fun yin, e need lati se Etutu fun won pelu Imule Agba, bi beeko, eo kan ma lo Oogun lasan ni, ko ni sise.
healthFirst:

E lo ma koko lo Ajeegun na ki e to se oogun kankan. Sugbon to ba je wipe awon agba ni o je ki oogun je fun yin, e need lati se Etutu fun won pelu Imule Agba, bi beeko, eo kan ma lo Oogun lasan ni, ko ni sise.
healthFirst:

E lo ma koko lo Ajeegun na ki e to se oogun kankan. Sugbon to ba je wipe awon agba ni o je ki oogun je fun yin, e need lati se Etutu fun won pelu Imule Agba, bi beeko, eo kan ma lo Oogun lasan ni, ko ni sise.

E seun Baba fun idahun si ibere yi toripe emi na ti bere irufe ibere yi. Siwaju si. Yoruba bo, won ni AGBATAN LA'GBO LE. E jo sir. Irufe IMULE ati EBE wo ni e ma fun wa lati se. Odua a gbe wa si rere o o o
Culture / Re: .. by Shomar: 9:42pm On Dec 03, 2015
Moki gbogbo ile o. E jo o o. Oruko miran wo ni won tun ma npe EWE AJE?
Culture / Re: .. by Shomar: 9:26pm On Dec 02, 2015
Mori ba ri ba. Moriba yin. Ajegun lo wa lokan mi ju. Baba, e jo wo, e fun mi. Ebe ni mo be.
Culture / Re: .. by Shomar: 9:07pm On Dec 02, 2015
E jo sir. E gba oro mi ro. Ajegun to lami laka ni mo fe.
Culture / Re: .. by Shomar: 9:06pm On Dec 02, 2015
burticious:

E jowo ,repercussion wo lo wa leyin ise yii , se ko ni pa awon omo mi lara
burticious:

E jowo ,repercussion wo lo wa leyin ise yii , se ko ni pa awon omo mi lara
burticious:

E jowo ,repercussion wo lo wa leyin ise yii , se ko ni pa awon omo mi lara
.
E jo sir. E gba oro mi ro. Ajegun to lami laka ni mo fe.
Culture / Re: .. by Shomar: 2:10pm On Dec 01, 2015
E jowo.Aye nda mu mi gidi gan.Ti mo ba se ogun fun rami, tabi won se fun mi, tabi eyan kan sa ogun simi, koda ko je ti aburu, kosì eyi to dahun lara mi mo. Moti se opolopo Ajegun ati Eyonu. Sugbon bakan na ni. Sir. Mo nwa eyi ti mafi pade awon AGBA.
Culture / Re: .. by Shomar: 2:09pm On Dec 01, 2015
E jowo. Aye nda mu mi gidi gan. Ti mo ba se ogun fun rami, tabi won se fun mi, tabi eyan kan sa ogun simi, koda ko je ti aburu, kosì eyi to dahun lara mi mo. Moti se opolopo Ajegun ati Eyonu. Sugbon bakan na ni. Sir. Mo nwa eyi ti mafi pade awon AGBA.

(1) (2) (of 2 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 45
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.