₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,329,452 members, 8,440,667 topics. Date: Tuesday, 07 July 2026 at 11:39 AM

Toggle theme

Shynersmart's Posts

Nairaland ForumShynersmart's ProfileShynersmart's Posts

1 (of 1 pages)

CultureRe: .. by Shynersmart: 11:55pm On Jan 24, 2016
Aku asiko yi oooo,iba agba ile,iba awo,iba omode ooo,iba ogbere ile ooo
Ejowo mofe bere itoni sona fun ebi mi kan nio,oti ba iya lajosepo koto ba omo iya na pade,oro ife won si ko,nigba ti iya yi ri ebi mi na,oloun fi owo si oro ife won,sungbon ebi mi na nberu lati ba omo iyana lajo sepo nitori wipe oti ba iya re ni ajosepo seyin.ibere mi ni wipe se ole ba omo iya na lojoseepo,se koni dena ore mo ,se koni fa ajalu sinu aye re...agba koni tan lori ile yi ooooo, Ase

1 (of 1 pages)