Tafari's Posts
Nairaland Forum › Tafari's Profile › Tafari's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 ... 10 11 12 13 14 15 16 17 18 (of 49 pages)
[quote author=cute-ass link=topic=10055.msg1210860#msg1210860 date=1182072939] ![]() |
baale oko ilu. bawo ni oro wa? |
kitaun:why me? I need your support to make it a success. do you have any hidden agenda with her? ![]() |
kitaun:work in progress! with you on my side, all things are possible. ![]() |
let`s talk on YIM |
pleasant personality ![]() |
iyaafin ikamefa, e ba mi ba baale soro ki won gba mi laye ati da ile ise igbalode sile ni ilu wa yii. |
iyaafin ikamefa, e kabo o. se daadaa ni ewa |
not only girls, everybody runs after money! |
arabirin desolaa, ile ise oti lile yii yio se anfani fun ilu wa. gege bi pilani mi, iwo ni yio je finance manager. e ma je ki a so ifa yio nu o. ao kilo fun awon odo wa ki won ma se mu oti lile ni aro ati osan. ale nikan ni a o gba won laye. itaafin desola timi leyin mase timi loju. |
baale, oko ilu, mo fe ki e ro oro yii daadaa. anfani nla nbe nibi kia da ile ise oti lile sile: ekinni, eyi yio pese ise fun awon omo wa ti ko ni ise. ekeji, oti mumu a ma pa ironu re nigba gbogbo, eyi yio din iku ojiji ku ni aarin wa. eketa, ao ni anfani lati ma ata oti naa si oke okun ekeerin, idagba soke ati okiki yio ba ilu wa yi. eyin ara ilu, se eyi ko daa bi? e je ka fi owo so owo po ki ilu wa kole gun oke odo. |
who is this otuwe? |
what position did you apply for? |
baale, oko ilu, ori idobale ni mo wa o. mo ngba ni ero lati da ile ise ipoti( oti lile) sile ni ilu wa yi. nje ma ri ile ti mafi da ile ise na sile. mo nilo to piloti ile aadota. ile ise mi yio gba awon omo ilu wa yi si ise. inu gbogbo ara ilu yio si dun. kini e ri si eyi baale? |
@ creamish, i dont understand your conclusion ![]() |
ok. |
ika, JAH loves you! |
baale mo ti yo oro owo ati moto kuro nibe. Inu mi dun wipe e ti gbe ilu iwo ri. e ba mi ba awon ijoye to ku soro, ki won da mi po mo ara won. itesiwaju ilu wa yi ni mo wa ni gbogbo igba. orunmila a gbe wa o ![]() |
i dont post pix in public forum. |
Baale, ki ara o le o. awon olori ni aafin nko. emi ola yin o gun o. Baale, e mi ni oye ilu yii to si. omo oodua tokantokan ni mi. ilu iwo ( olodo oba, omo atenigbola, atenigbore.) ni ibi ti mo ti wa. awon owe yin yii lee pupo. e ba mi daa ogbon si. e o gbadun mi pupo. ko da, moto yin tin duro de yin ni iwaju aafin bayi. e ma je ki oju ki oti mi o. awo ni o ngbe awo ni igbonwo. |
si desorlah, falana gbo ti e , tara eni la ngbo. |
i am an handsome young man. enough pepper for you. just give me a trial. |
Alagba Tafari, idunu nla ni o n je fun mi lati ri wipe oye ilu wa yii n wu iwo na . O si ti di dandan ki o ri oye je. Mo ti ba awon oloye ilu to ku soro nipa igbese nla yi, won si ti fi enu ko wipe kii a se idanwo fun o. Ti o ba ti we yan kainkain , o daju wipe kosewu legberun eko o. IDANWO FUN TAFARI: A. Pari owe yi: 1. Ailora ogongo, 2. Datoro,datoro, datoro, agba ti o da toro, 3. Idi ni iku igbin,, 4. Onibaje ko won,, 5. A kii bara eni tan ,, B. Omo ilu wo ni o? C. Fun wa ni ila maarun pere ninu oriki orile ilu tabi iseda ebi yin. Ogbeni Tafari , awon ibeere jekojeko yi ni mo nilo esi fun , lehin eyi o di dandan ki o joye ni Ilu Yoruba yi. Baale, oko ilu, se daada ni ede wa. gege bi mo se so fun yin, eniyan pataki ni mi ni awujo. mo ni owo, okiki ati ogun.awon ibere ti e nbere yii ko to si mi. e je ki nfun yin ni owo (egberun lona millionu naira) lati ra oye naa. Mo se ileri wipe ma ko aafin miran fun yin. ma si ra moto ayokele meta pelu. baale oko ilu, e gba mi towo tese. ilu wa yii a toro bi omi ati owuro pon o. e se pupo. |
damsol:what do you know? tell me now! |
i am sure you are the one. creamish, my heart desires you. come on let us make our dream come true. |
what is your discipline? |
si baale, ki ara o le o. ki ade pe lori, ki bata pe lese. mo fe je okan lara awon ijoye yin. owo ati ogun wa. gbajumo si wa pelu. e ma gbadun mi repete. |
of course legs. i saw you, creamish. ![]() how do u fulfil the dream? |
desorlah:As for me, i am cool! and u? |
Creamish:i saw you in my dream. JAH told me you are mine ![]() |
nikynike:You are! ![]() |
@ creamish, your bros is here! |
1 2 3 4 5 6 7 8 ... 10 11 12 13 14 15 16 17 18 (of 49 pages)



