Temitope1990's Posts
Nairaland Forum › Temitope1990's Profile › Temitope1990's Posts
1 (of 1 pages)
I have complete Umidigi A5 Pro with new follocome screen and battery. If you need it. With motherboard dm. 08144856122 Akungba Akoko, Ondo State Nigera |
Please I need a printer �️ |
الحمد لله منزل الكتاب، هدى وذكرى لأولي الألباب، والصلاة والسلام على نبينا محمد المفضل على البشر بجوامع الخطاب، وعلى آله والأصحاب. وأشهد أن لا إله إلا الله وحده لا شريك له، وأشهد أن محمداً عبده ورسوله شهادة تنجي صاحبها يوم الحساب. Mi maa pa awọn eniyan lasẹ dara-dara ki a si maa kọ aburu sise fun wọn jẹ ọna kan Pataki ti afi nmọ Musulumi gidi. Kódà, ijọsin (ibaadah) kan pataki ni o jẹ funraarẹ, ti o si man se afihan awọn arole Annabi taara (Alfa) lori ilẹ. Sugbọn ohun ti ko jẹ ki awọn eniyan mọ pataki eleyi ni esu ti on tan ọmọniyan jẹ, pẹlu irufẹ adua tabi nafila kan ti ko fidi mulẹ ninu ẹsin ti wọn yoo si mura sii kankan ti wọn yoo si gbagbe mi maa pa awọn eniyan lasẹ dara-dara, ki a si maa kọ aburu sise fun wọn Ninu ohun ti otilẹ waa bani lọkan jẹ niti pupọ ninu awọn ọdọ Musulumi loni ti wọn kewu ti wọn sin ri aburu ati itapa si ofin Ọlọhun lorisirisi lawujọ, sugbọn ti wọn fi ọwọ lẹran ti wọn nwo iran. Nigbati aburu naa ba waa gbilẹ tan wọn yoo maa wa se kayeefi!. Oluwa Ọba ti Ọla Rẹ ga sọ pe "Ẹyin ọmọleyin Annabi Muhammad r ni ẹ dara julọ ninu ijọ ti a mu jade fun ọmọniyan; ti ẹ ma n pa awọn eniyan lasẹ dara-dara, ti ẹ sin kọ aburu sise fun wọn. كُنْتُمْ خَيْرَ أُمَّةٍ أُخْرِجَتْ لِلنَّاسِ تَأْمُرُونَ بِالْمَعْرُوفِ وَتَنْهَوْنَ عَنِ الْمُنْكَرِ [آل عمران : 110][color=#990000][/color]
|
1 (of 1 pages)