Unilevel's Posts
Nairaland Forum › Unilevel's Profile › Unilevel's Posts
1 (of 1 pages)
kadunasouth:Ibeere lori ose aseta ti a lo tako tabo edan fun yen. Bawo ni ao se lo ose ti o wa ninu igba yen? E se pupo. |
kadunasouth:Se irun ori eni naa ni tabi ti enikeni? Se bara nii tabi tagiri? E se pupo. |
Aboru aboye fun gbogbo Awo ti o wa lori ikanni yii, Ewe ati egbo a maa je fun gbogbo wa ooo, Ase. Igba irumole a gbe wa ooo, Ase! Inu mi dun pelu ise takun-takun ti e nse lati gbe ise ati asa Yoruba laruge. IFA yio gbe wa o. Sugbon mo nfi asiko yii pe yin si ori itakun Facebook ni awujo Ifatomiwa Sankinloju (IFA TEMPLE) ki a tunbo maa gbiyanju lati gbe ASA ati ISE YORUBA laruge. Ki a tun maa je anfani ewe ati egbo bakanna. Facebook group: Ifatomiwa Sankinloju (IFA TEMPLE) |
Please unban *bayuskam |
naijacutee:Do you have functioning paypal account? How can I verify my paypal account as Nigeria without limit or ban? Kindly assist me. |
1 (of 1 pages)