Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,165,404 members, 7,861,140 topics. Date: Saturday, 15 June 2024 at 02:51 AM

Victorolami's Posts

Nairaland Forum / Victorolami's Profile / Victorolami's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by Victorolami: 1:25pm On Jan 17, 2016
E seun gan baba healthfirst, awon tolaye yio ma tiyin leyin.... Sugbon mio Mon oruko arakunrin ti oun mu won rin irin ajo yii... ati wipe won ti kuro ni Nigeria ni odo wa nibi won si ti wani DESERT ni orile ede Niger... Ejowo se kosi oun tele bami fii GBE omobinrin yii kuro larin won si ilu towa ni Nigeria nibi... Ojo yin yio dale ooo... Ejowo eran mi lowo.
Culture / Re: .. by Victorolami: 11:10am On Jan 17, 2016
E seun gan baba healthfirst, awon tolaye yio ma tiyin leyin.... Sugbon mio Mon oruko arakunrin ti oun mu won rin irin ajo yii... ati wipe won ti kuro ni Nigeria ni odo wa nibi won si ti wani DESERT ni orile ede Niger... Ejowo se kosi oun tele bami fii GBE omobinrin yii kuro larin won si ilu towa ni Nigeria nibi... Ojo yin yio dale ooo... Ejowo eran mi lowo.
Culture / Re: .. by Victorolami: 11:40pm On Jan 16, 2016
E seun gan baba, awon tolaye yio ma tiyin leyin.... Sugbon mi o Mon oruko arakunrin ti oun mu won rin irin ajo yii... ati wipe won ti kuro ni Nigeria ni odo wa nibi won si ti wani DESERT ni orile ede Niger... Ejowo se kosi oun tele bami fii GBE omobinrin yii kuro larin won si ilu towa ni Nigeria nibi... Ojo yin yio dale ooo.
Culture / Re: .. by Victorolami: 7:18pm On Jan 16, 2016
Baba Healthfirst Ati Baba Kaduna South Egbami ooo.... Oni omobirin kan ti ati nfe arawa bi odun marun bayi... laipe yi ni awon obi re fale awon kan lowo lati murin irin ajo losi ilu Spain tiko sii gba ilana toto... omobirin yii ko mon pe awon ti won ko awon obirin losi ile okere lati loma fi won se owo asewo lon kosi lowo... won siti dey Sahara Desert bayii....Ije oni ise ti e lese funmi lati GBE omobirin yii kuro ni ibi towa bayii si ilu bi Ibadan tabi Eko,,, ti yio file pada wale... tori awon obi re gan tin kaba mon bayii Lori igbese ti won GBE... ejowo esanu mi, tori moni ife omobirin yii gidigidi.
Culture / Re: .. by Victorolami: 3:39pm On Nov 10, 2015
Aboruboye ooo... Ejowo mofe ki efun mi ni ogun idi ton yoo nipase jedijedi at ogun jedi ti oo daju.
Culture / Re: .. by Victorolami: 12:04am On Nov 10, 2015
Aboruboye ooo... Ejowo mofe ki efun mi ni ogun idi ton yoo nipase jedijedi at ogun jedi to gbona.

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 12
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.