Weblessyou's Posts
Nairaland Forum › Weblessyou's Profile › Weblessyou's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 (of 14 pages)
. |
den go start your station or stop watchin tv |
. |
kaka |
iya oshogbo |
. |
. |
' |
. |
. |
![]() |
Omode gbon, agba gbon la fi da Ile-ife Ogbon ologbon---la nfin sogbon Ore ko si mon---ka ri eni ba rin loku Amuni nje amuni---ewo ni o ni bo nibe Ore dun la n ba ara eni jeko---ti ile oge to oge je Anroju je eko obun---obun pon eko e kere Ija lode---lorin dowe Oun se mi, oun gba mi---ati se ndupe lowo eni to n se ni, to n tun gba ni Eni rii nkan hee to fe ku pelu e---owo eni to ti sonu nko? Agba ki wa loja---ki ori omo tun wo. |
Oun to ba gbin---ni iwo yio ka Opipa mi pa ara re---o ni oun pa aja Oni re---ni yio fi ola re han Eni ta oja eepe---yio gba owo okuta Esan a ke lori gbogbo---onise ibi Ma fi oni ba ola re je--- ika ko pe, rere lo pe Jawo ninu gbogbo---ise ibi Ko i ti peju---fun atunse To ba ko iwaju sio ta a, to ba ko eyin sio ta a---to ba ku iwo nikan tun ero ara re pa a Eni a wi fun---oba je ko gbo. |
![]() |
Bi omode ba shubu---Aa wo iwaju Agba to jin si koto---Oko ara yoku logbon Eni se ika tan to yi odo bori---bi oba aye ko rio 'torun wo o Iyan ogun odun--- A ma jo ni lowo Osika gba gbe ola--- o gbagbe ojo ikeyin Eni gbin ebu ika sile---omo re a je nibe Ika yio ba onika---rere a ba eni rere Ojo gbogbo ni tole--- ojo kan ni ti olo un. |
@idowuogbo oda aaro arabinrin To ba di idaji a o ma ba ere wa lo ni iwon-tun-wonsi(moderation) E gbinyanju lati ma fi awon oope si aye won, EMA SE FESI SI ORO WON. Awon omode n ka tiredi wonyi O. Fun ojo ola won, odaaro o! |
ore mi, bi eleshe ban tan o, iwo ma se gba. |
mo sure e ni fe kan ba ojo ola yin je |
@idowuogbo quote , Awon taiye and ati kenny, Buhahahahahahahahaha! Omo Yoruba atata . He he ee, Aun-ti idowuogbo(WE ARE PUSHING IDOWUOGBO) chei! Kin ma gbagbe, idogbe ati alaba n ko, se won ti jeun? my sis, can u remember this rhyme or never sang it b4? Sokoto pepe is a nicker, eja dindin is a fish, omi garri is water, e.g omi agbon. Funnily funny |
d tin be say, d tv stations dat u watch mostly n r easily accessible to you, na dem u hate most.
ur tv no get infrared remote? A beg switch to something else. . we often hear dem sayin "DONT TOUCH THE DIAL" n "PLEASE STAY TUNED" Listen to radio, read books, move around, do your own stuff. Sha I got d point u guys re trying to make. NTA remains d worst tv station for many reason, they wont even allowed thier local channels to do their own stuff, they must subsequently joined most of the network program aired by NTA plus. What's their problem? Equipment or Management. |
@Idowuogbo Buroda, ema binu si mi jare Taiyewo ati Kehhinde ko |
@Idowuogbo Buroda, ema binu si mi jare Taiyewo ati Kehhinde ko |
since 1962 |
Alo o o o |
@birdman Ma binu mo ti gbagbe pe ile emu lawa. Tshweeeee mi mon eni to foro lo e Mama douglas, more please! |
Eyin ni omo aji fi ojojumo ko poster, omo aji fi ojojumo ka tiredi. |
@rahjan, idowuogbo, tpiah, ifuk Eyin ni omo ilu Nairalandi, eyin ni omo ada erin pa osonu, eyin ni omo afi ogbon ologbon so gbon, eyin ni omo amu igboro dun, aji lala osho, aji fi ojojumon dara bi egbin, eyin lomo a visit nairaland lati fogbon kun ogbon ati lati mo kun mo, ati laughter kun laughter. |
Odun melo lo gba lowo mi gan naa |
@Obodo E jowo, iyato wo lo wa larin owe, alo àpamo àti àlo àpāgbè |
@Obodo Baba agbalagbi, e gbi yanju. San lan rin -aje ni muni pekoro Bi onirese ko ba fin igba mo- eyi to ti fin ko ni parun |
No be sachet water? It's been anointed, no need to reg. Rather, They should take all necessary measure laid down by nafdac before anointing, atleast to puri*fire . abi God go register for nafdac bfore sendin down rain ni ke? |
. |
