Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,165,360 members, 7,860,987 topics. Date: Friday, 14 June 2024 at 08:17 PM

YoungAbiodun1's Posts

Nairaland Forum / YoungAbiodun1's Profile / YoungAbiodun1's Posts

(1) (of 1 pages)

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by YoungAbiodun1(m): 9:55am On Mar 10, 2017
Modupe gidi gan fun idawun yin lori ibeere mi iyen (ogun fun ara tin wu)eseun gan an ni.Uhn,ajanaku koja mori nkan firi,taa ba rerin kaso wipee arerin.Ise takun takun le n se lori ikanni yii.Mo gbaa ladura wipe ki olorun oba tun bo maa se alekun ore ati ibukun fun un yin.Ejo,eniti ara re un wu yi,won ti lo ogun lorisirisi fun un sugbon ti o jasi wipe ti enina ba ti yagbe fun iye ojo die,ti arare si ti lole toba ya arare a tun bere sini maa wu pada paapa julo ikun re lo maa un wu ju ai eni imale gbe.Inu mi adun gidi gan an ti ogun ti e fun mi yi ba je ti arare kosi wu pada mon.IBA AWON TO LAYE,IBA YIN OOO
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by YoungAbiodun1(m): 1:27pm On Jan 28, 2017
Ki agba yin dale o.Ejo ogun wo ni eyan ma lo si ara to ban wu ti won lo ogun si ti eni na ti ya gbogbo re danu sugbon ti ara nan tun wu pada

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.