₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,325,437 members, 8,422,004 topics. Date: Sunday, 07 June 2026 at 01:34 PM

Toggle theme

Zaudi's Posts

Nairaland ForumZaudi's ProfileZaudi's Posts

1 (of 1 pages)

CultureRe: .. by Zaudi(m): 10:11am On Feb 10, 2016
Ejowo,Bawo ni won se maa n diru egbe fun elegbe omo
Dating And Meet-up ZoneI Wanna Take Over by Zaudi(op): 12:00am On Feb 10, 2016
HI 2 landers
i wooed a girl,have knw her b4,so when i told her,she decline says she cant dump her present bf because wen d time come to tie d knot,if am d lucky guy will d latter happy or vise vasa,we used to talk on phone,so if it take up to 4days without call/text she surely call,if txt her she will call nd said i appreciate ur message.wotz ur advice/trick?
CultureRe: .. by Zaudi(m): 11:33pm On Feb 09, 2016
copy and paste ogun wo ni mose?e so kia mo
CultureRe: .. by Zaudi(m): 11:27pm On Feb 09, 2016
Mio se copy nd paste lati post oogun tabi lati gboriyin lori ise elomiran sugbon lati fise refrence nkan ti mon so,e je kia maa sesuru latigbora wa ye
CultureRe: .. by Zaudi(m): 5:19pm On Feb 08, 2016
aku irole eyin baba ati gbogbo ile,ejowo mo n fe iferan ti awon obinrin yoo maa nife eyan
CultureRe: .. by Zaudi(m): 9:29am On Feb 07, 2016
healthFirst:
OHUNFA OLUBARA (CUSTOMER)
Kanhin kanhin iyekiye ao jo pelu odidi ataare kan ao ro sinu Ado kan ao lo efun mon ao jipo daradara ao toju re pamo sinu ile ise waa ti
Olubara(Customer) bati dide lori ibi ti o joko si, ao mu, ao ta bintin si ori aga tabi ori eni to ba dide.

Iba Awon Agba.
se kahin kanhin ti afi n we ni baba?
CultureRe: .. by Zaudi(m): 11:50pm On Feb 06, 2016
Ejowo efun mi ni oogun ti won yoo fi maa bun eyan ni nkan,
ati awure owo toje aseje,agba yin yoo pe lori le
CultureRe: .. by Zaudi(m): 11:45pm On Feb 06, 2016
healthFirst:
Beeni, ohun na ni Rerinkomi, Pakududu, Igbe Elede, Imi Esu, ati beebe lo.
healthFirst:
modupe pupo
Beeni, ohun na ni Rerinkomi, Pakududu, Igbe Elede, Imi Esu, ati beebe lo.
healthFirst:
Beeni, ohun na ni Rerinkomi, Pakududu, Igbe Elede, Imi Esu, ati beebe lo.
CultureRe: .. by Zaudi(m): 11:23pm On Feb 06, 2016
BABA OGUN IFERAN OBINRIN TI O DAJU TI O LE MUYE OBINRIN TI WON BA TI FOJU KO YAN....EMI NA NI OWO TI ODAMI LOJU DEBI PE TI WON BA FE FI OWO KAN YAN WON MAA YAGBE[/quote]ore tobadaju jekin jan faani re
CultureRe: .. by Zaudi(m): 11:16pm On Feb 06, 2016
ejowo se ewe rerin komi naa ni an pe ni imi esu??
CultureRe: .. by Zaudi(m): 11:12pm On Feb 06, 2016
eejowo se ewe rerin komi naa ni an pe ni imi esu??
CultureRe: .. by Zaudi(m): 11:08pm On Feb 06, 2016
Iwe Iwulo Ewe ti wa fun tita...e gbiyanju ki e ni lowo...die omokunrin ko to inkan. Eni yara logun n gbe. Ejowo baba se ewe rerinkomi naa ni won npe ni imi esu?eseun maama reti esi

1 (of 1 pages)