Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,194,368 members, 7,954,493 topics. Date: Friday, 20 September 2024 at 08:23 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1842012 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (31) (32) (33) (34) (35) (36) (37) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by kadunasouth(m): 3:00pm On Nov 23, 2015 |
bwayomide: Ewe olomuyinrin 3 Likes |
Re: .. by lawani: 3:19pm On Nov 23, 2015 |
E ku ise opolo o. Olodumare a ma ran yin lowo o. Ase Edumare. |
Re: .. by lawani: 4:09pm On Nov 23, 2015 |
Baba, m o ni ibeere kan ti m o fe beere ti e ba ni idahun is. E jowo kini itumo ala (mi mi) ti o jeyo ninu Obatala ati Orisaala. M o m o wipe ala (do do) tumo s i funfun, ala (do mi) tumo s I dream ni ede Geesi. Sugbon emi ko m o itumo ala (mi mi) ti owa ninu orisaala ati Obatala. M o ro wipe nla (big) ni tele sugbon ko da mi loju m o bayi. E se pupo. Ibeere yi ko je m o ohun ti okun oro yi da le lori sugbon inu mi yio dun ti e ba le la mi loye. E seun. |
Re: .. by Shomar: 4:44pm On Nov 23, 2015 |
E jowo. E fun mi ni ogun Agbara. Teyan nfi le koju awon enibi. Email mi niyi ajayioyewoles@gmail.com. Gbogbo ogun tebanfe, e le bimi. Ma se tinbani. |
Re: .. by mondaylyno(m): 8:23pm On Nov 23, 2015 |
E jowo. E fun mi ni ogun Agbara.
Teyan nfi le koju awon enibi. Email mi
niyi Mondaylyno335@gmail.com.
Gbogbo ogun tebanfe, e le bimi. Ma
se tinbani. |
Re: .. by kadunasouth(m): 10:39pm On Nov 23, 2015 |
bwayomide:Ni oke oya niwan ti mani feriganmu kuwara nilorin wa ma ni feriganmu sugbon abeokuta ni west wan aman peni olomuyinrin, ewe olomunyinrin oni bi seed kinkin lara 2 Likes 2 Shares |
Re: .. by keyguy59(m): 11:47pm On Nov 23, 2015 |
ASIRI NLA TI MO RI NINU IWE EGBGI AWON BABA MI.........NI AYE ATIJO BI OBINRIN LO ILE OKO....AWON BABA WA YIO FI MO BOYA IBALE RE YI WA NI BEE....KI OKUNRIN NA TO FE.......SUGBON BI OMO OBINRIN NA BA JEWO FUN BABA RE....OGBON AGBA WA TI WON YIO FI DAA IBALE NA PADA...............DANWO KI O FUN ILE LAABO RE BI OTI RI ...................Ogun ti ibale fin pada Sara obinrin( to regain virginity> Ewe ege were, owu Elena, lilopo, ao fipa ara eyin adie, ao fi owu Elena yi eyin adie na, ao fi aso osu ti obinrin na lo lowolowo we lawetan, ao mulo sinu okiti ogan, ti okiti ogan yi babo, ibale(virginity ) yio padabo Sibe. ...................ASIRI NLA NI EYI OOOO... 3 Likes 1 Share |
Re: .. by keyguy59(m): 11:53pm On Nov 23, 2015 |
<OGUN KI OBINRIN MABI ABIKU MO>
Egbo sapo, egbo peregun, ako eyele, ose, igba
olomori, ao ha ara awon egbo yen, ao gun mo ose
dudu, ao la eyele yen laya, a ko ose yen sinu aya
eyele yen, ao wa gbe sinu igba olomori yen, obinrin
tabi omo tobi naa yio mafiwe. Ofore :- Ododun ni sapo nwu ewe, ososo ni peregun
nse ofo iyare, ako eyele kini isimi, gbogbo eni toba
nse oun buburu simi koma ni isimi. 1 Like |
Re: .. by keyguy59(m): 12:33am On Nov 24, 2015 |
olorun ni oda owun gbogbo.......iba oooo....:........,.aye yi alo ni ojo kan......aye bo wa wo ewu enaa....aye bo wa sa.........aye bo wa fa ya ke de re.........iwa ibi o pee laye.....reeree lo yee ka ma se.........itori ojo ti aba ku.......ini tori ojo ti a ba file saso bo ra....owun lo di fa fun baba lawo to lo sogun aiku....egbo baba hearthfirst inje eni kan wa ti o niku saa..........eje ka ma ran ti atunbotan...........baba hearthfirst.........ese mi oooooooo mo ti te ate ji se si yin......ese wun ooooooooo |
Re: .. by Nobody: 5:23am On Nov 24, 2015 |
ineedhelpfast: E kan si mi lori e-mail tabi ke call mi. Time and space have no control over the spiritual but the other way round. No secret is hidden from Esu laalu. |
Re: .. by Nobody: 5:26am On Nov 24, 2015 |
keyguy59: Kini a fi se yin? E ma binu si mi o, E jebure, Awo Olugbebe... Mi o ti ri e-mail yin o...bya ke tun send. |
Re: .. by Lionhearted: 6:19am On Nov 24, 2015 |
keyguy59:Bawo mo sele kan si yin? |
Re: .. by keyguy59(m): 10:18am On Nov 24, 2015 |
awo kin binu si awo.....baba hearthfirst.......emi ni mo bee re fun ogun kan lowo yen lo ri email...... |
Re: .. by simlek: 11:59am On Nov 24, 2015 |
Àgò onílé o, onílé mo kágò o, Ewúré tó wolé tíò kágò deran àmú b'ofá, Ìran àgùntàn bòlòjò tó wolé tíò kágò deran àmú s'ètùtù. Áá júwaáse o, Àgbà ò sì níí tán l'órílè, bí àgbà ò bá tán l'órílè, Àá f'oláa won rìn, Àá sì fi yan fa-nda. Mo kí alàgbà ''Healthfirst, kàdúnásouth, keyguy59 etc'' àti gbogbo omo egbé ìkànnì yí lápapò, kò níí bàjé o, (Àse èdùmàrè). 1 Like |
Re: .. by simlek: 12:27pm On Nov 24, 2015 |
keyguy59:Ekú isé takuntakun l'órí ìtàkùn yí o. |
Re: .. by kayponpy20: 1:27pm On Nov 24, 2015 |
Ejowo oruko wo ni atunle mo Asunwon oyinbo si,Ajuse funwa o |
Re: .. by ineedhelpfast: 3:16pm On Nov 24, 2015 |
Mail sent, kindly reply me. Thanks, healthFirst: |
Re: .. by ineedhelpfast: 3:24pm On Nov 24, 2015 |
Kini eyin tun fin shere bi omo ejo yi? I ve gone to numerous alawos, pabo ni gbogbo e jasi, mo tun waste owoni. i had to gba kamu. olosanyin ti ko ba tun rami lowo so fun wa pe awon o kin mu ole but won fi ishele naa she akoba funmi ni lenu ise. Deep down in my heart, i feel cheated, cos for anyone to steal such a huge amt and go scot free is d height of wickedness. i hope to get REAL help on this thread sha. Bosville: |
Re: .. by Bosville(m): 5:03pm On Nov 24, 2015 |
ineedhelpfast:Odo awon alawo te lo, iru awon ajo wo lo se funyin gan?? |
Re: .. by keyguy59(m): 7:56pm On Nov 24, 2015 |
se ri gbogbo ile.....eni ti won ji owo re yi...ti won ba ni kin so....ko le ri owo re mo....awon babalawo ako ma gba owo lowo re ni.....tori oti koja ojo meje......ka ni ko ti koja ojo meje ni...ise kan wa ti mole se si ti oni towun yio gbe owo na wa fun ara re... Sugbon oti koja......ema fi si adura..... |
Re: .. by sammyjay76(m): 9:38pm On Nov 24, 2015 |
Eku dede asiko yi o gbogbo ile... ejowo eba wa fi Ogun apa o ka to daju sita ATI oGUN TI A LE SI MO TI WON BA GBE NKAN BURUKU SI ARA OBINRIN. ILU TI MO WA OPOLOPO NKAN NI WON SE FI GBA IYAWO ENIYAN, BI KI WON FI ERO, TABI MAGUN S LARA , TI OKO BA LU KI IYAWO LE JE TI WON. Ejowo apa ota oni ka gbogbo wa o. Amin ASE. |
Re: .. by rubber: 10:08am On Nov 25, 2015 |
healthFirst: Ejowo baba kini gbolohun yi duro fun? |
Re: .. by Ifadamilola30: 6:31pm On Nov 25, 2015 |
MOJUBA OLODUMARE!!! IBA Osanyin!! Orunmila, IBA!! Esu odara, IBA!! Eyin Iyami Eleye, IBA!! IBA agba, IBA Omode!! Moki gbogbo ile oo!! IBA gbogbo Eyin Awo oo!! Moki awon Ogberi pelu.!! IBA baba Healthfirst, baba Kanosouth, keyguy59, ati gbogbo eyin Awo ire/Onisegun ti e finnu-findo ti e si fowosowopo lati ko Ise lorisirisi sita lori thread yii..!! E ku ise takuntakun!! Orunmila a gbewa ooo. Gbogbo eni to ba fi tie sile to ngbo teni eleni, Odaju wipe OLODUMARE yio gbo tiwon na!! 1 Like |
Re: .. by Ifadamilola30: 6:34pm On Nov 25, 2015 |
Re: .. by Ifadamilola30: 7:01pm On Nov 25, 2015 |
Baba Healthfirst, baba Kanosouth ati eyin Awo te wa nibi, e dakun awon aafani wo lowa ninu ki enia KO-FA, (Ki enia wo igbodu, ko si ni ifa ti a ma bo ninu ile Re) IFA KIKO! .. Awon aafani wo lo ro mon... |
Re: .. by Nobody: 7:45pm On Nov 25, 2015 |
ineedhelpfast: I haven't seen it. 1 Like |
Re: .. by ayokomi1010(m): 12:29am On Nov 26, 2015 |
E karo oooo,baba,ati Gbogbo omo odua,Igba akoko mi re Lori ikanni yi o,ama ju wa se o |
Re: .. by ayokomi1010(m): 12:40am On Nov 26, 2015 |
Ogun Adodun Nla.ao toju aiyan kan ao lo ni enu ona wa ao wa fi ori po,ao ma fi wo nkan omokunrin wa ti a ba ti fe ba Obinrin ni ajosepo,be na ni Obinrin na le lo fun OKUNRIN ki o Sa ti fi pa oju ara re saju ki OKUNRIN to ba ni ajosepo,Adodun yi ni agbara pupo,Iba eyin agba oooooo,ewe ama je o. 2 Likes 1 Share |
Re: .. by ayokomi1010(m): 3:04am On Nov 26, 2015 |
OGUN OSOLE AWORO WO OWO Ao toju alangba tako tabo,owo eyo kudi 16,ao wa ya enu ako alangba na ao ko owo kudi 9 si ninu,ao ko meje sinu abo alangba na,ao wa fi ako tele inu ikoko ao gbe abo le,bi igbati won Jo se asepo ao wa fi igi nla die si egbe osi,odidi atare ni egbe otun,ao Jo papo,ao ni ro po rara ti a fi jo tan o,ao lo kunna Dada ao ma fi oti lo laro laro,opo ero ama wa si odo eni pelu owo nla. pelu ogo Olorun yio ri be odaju Dada,iba eyin agbalagba o 2 Likes |
Re: .. by Ifadamilola30: 7:31am On Nov 26, 2015 |
Re: .. by Ifadamilola30: 7:32am On Nov 26, 2015 |
ayokomi1010: Ewe a ma je oo!! E dakun se a ma gbe olo ti a o fi lo ise na si Enu Ona wa ni?? Abi ao lo ni ilele enu Ona wa ni?? |
Re: .. by ayokomi1010(m): 10:33am On Nov 26, 2015 |
[quote author=Ifadamilola30 ,ti aba fe lo Ogun adodun na,ale lo ni ori simenti tabi Ki a gbe olo lo enu ona 1 Like |
(1) (2) (3) ... (31) (32) (33) (34) (35) (36) (37) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 41 |