Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,143,435 members, 7,781,271 topics. Date: Friday, 29 March 2024 at 11:32 AM

.. - Culture (7) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1823553 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Mayorz200: 9:59am On May 23, 2015
E jowo baba kilo n je e, Enukopire gege bi e ti se alaye ninu oogun aran. E jowo se ewe ni sir
Re: .. by Nobody: 10:29am On May 23, 2015
Mayorz200:
E jowo baba kilo n je e, Enukopire gege bi e ti se alaye ninu oogun aran. E jowo se ewe ni sir

Enukopire wa lodo awon elewe omo...eka igi ni.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 10:31am On May 23, 2015
talktofemi:
Eku ise o,

Nje ogun wa fun eniti ki gboran daadaa? Eniyan mi kan ni lo re,

E joo e se alaye daada...ki lo se eni na ti ko le fi gboran daada mo? se bi a se bi niyen tabi aisan to sese wa si lara ni? tabi eti yen wu ni tabi kokoro wo eti yen?

Alaye ekunrere je dandan. Ki a ma ba fi oogun ori fifo wo inu rirun.

2 Likes

Re: .. by sammyjay76(m): 12:34pm On May 23, 2015
healthFirst:

Oogun re wa daada sugbon mo fi eleyi sita nitoripe a ti lo ri to sise daada.
ESEUN GAN O, AJINDE ARA YIO MA JE. O. LEKAN SI LORI OOGUN SICKLE CELL YI...... EJOWO BA MI SE ALAYE IYE IGBA TI A LE LO OOGUN NAA DA, ABI TITI LKO NI?
EJEJI, ESO RERE TI E DARUKO NAA, E SE ALAYE DIDAMO DARADARA, SE RENRENni? ABiI RERE?
EDAKUN TI OOGUN MIRAN TABI ONA MIRAN BAWO LATI DEERO AISAN YI PATAPATA E BA WA FI SITA.
E O NI SUBU DANU O, EDA GBOGBO AWON ENIYAN TI WON RI OREOFE NIPA IWULO EWE ATI EGBO YI AFI IRE AJENJETAN FUN AYE YIN.
ESEUN PUIPO.
Re: .. by Nobody: 2:13pm On May 23, 2015
sammyjay76:

Ao ma lo titi ti ara alaisan na yio fi ya tan patapata. Eso Rere ni Eso to wa lori Igi Rere...o yato si Renren...e beere lowo awon elewe omo

Awon Oogun re miran wa sugbon se e mo wipe kii se gbogbo Oogun la le fi sori afefe.

1 Like

Re: .. by Nobody: 4:04pm On May 23, 2015
..

1 Like

Re: .. by sammyjay76(m): 4:21pm On May 23, 2015
E ku ise o, edumare oba oke a ma fun yin se o....
Ejowo e fun wa ni ogun ti eniyan o ni le fi ko arun lara obinrin tabi okunrin, boya magun, eroo, ati awon arun miran.

Ati oogun ti a fi n so ile eni tabi ayika wa di eewo fun emi buburu tabi awon nkan aransi.

A ma jhu yin se ooooo...... Amin.
Re: .. by kadunasouth(m): 10:16pm On May 24, 2015
healthFirst:

Beeni, gbogbo e la nilati lo leekan

Thanx ese pupo

1 Like

Re: .. by kadunasouth(m): 10:56pm On May 24, 2015
[quote author=healthFirst post=33648850]20 OOGUN AWOKA TABI EJE DUDU

A. Egbo Orogbo at Alugbokita, Erinje, ao fi ekan ori(Omi Ogi) se won po...ao ma yo mu diedie.

B. Egbo Saposapo,Ewe Dagunro,Erinje, Ose dudu die, ao se won lagbo, ao ma yo mu diedie.

D. Ewe Ese Adiye, Erinje...ao se po pelu omi...ao ma fi we ibe.

Edakun kilonje erinje atipe oruko miran wo lalepe fun awon elewe omo

2 Likes

Re: .. by Nobody: 12:49pm On May 25, 2015
[quote author=kadunasouth post=34065343][/quote]

oruko ti mo mo niyen...e beere lowo awon elewe omo.
Re: .. by Lionhearted: 1:05pm On May 25, 2015
healthFirst:

E lo se ayewo lodo awon dokita ki e wa fun wa labo.

Ki eni naa lo Oogun yi ki o to lo fun ayewo

GBOGBO NISE (ANTI BiOtIC)
Egungun ara iganna (wall) ao yo die ni ibe ao ra atare aobo epo ara re ao wa jo epo yen papo mo egungun ara iganna ti abajo tan ao fi sin gbere kokan si orike rike arawa eyi to ba seku ao fi te ifa ejiogbe ao wasope gbogbo arunkarun ati owo kowo tin be lara mi oso lofi simi lara ni,aje ni eji ogbe bami gbe gbogbo re kuro ao wada si epo pupa ao mala

Ejowo kini egungun ara iganna? Se igi ni?

Ati pe kilon je orike rike? Kini itumo tefa eji ogbe?

Se eriru na ni eeru(ash)?

Ema binu awon ibere won yi baba. Mo Fe koye mi daadaa ni o kin to lo ra awon eroja wonyi loni.

1 Like

Re: .. by Lionhearted: 2:19pm On May 25, 2015
healthFirst:

E je ki eni na lo Gbogbonise yen...ng o tun fi omiran sita fun yin.
A nduro fun omiran ti e so.
Re: .. by Nobody: 3:12pm On May 25, 2015
Lionhearted:

A nduro fun omiran ti e so.

E je ki eni na lo Gbogbonise yen ki e wa fun mi labo.
Re: .. by Nobody: 3:18pm On May 25, 2015
Lionhearted:

Ejowo kini egungun ara iganna? Se igi ni?

Ati pe kilon je orike rike? Kini itumo tefa eji ogbe?

Se eriru na ni eeru(ash)?

Ema binu awon ibere won yi baba. Mo Fe koye mi daadaa ni o kin to lo ra awon eroja wonyi loni.

Gbogbo ibeere wonyi tumo si wipe e kii se omo Yoruba.

Orikerike ara ni gbogbo eya ara to sepo...awon bi Ejika, Isepo Apa, Isepo Ese, orun ese, Orun owo, Igunpa ati beebe lo.

Eriru yato si Eeru...Eriru je eso ori igi, Eeru ni ajoku igi idana.

Tefa Ejiogbe tumo si wipe ka fi ika te Ifa Ejiogbe sori Iyerosun tabi Ebu Oogun.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 3:20pm On May 25, 2015
sammyjay76:
E ku ise o, edumare oba oke a ma fun yin se o....
Ejowo e fun wa ni ogun ti eniyan o ni le fi ko arun lara obinrin tabi okunrin, boya magun, eroo, ati awon arun miran.

Ati oogun ti a fi n so ile eni tabi ayika wa di eewo fun emi buburu tabi awon nkan aransi.

A ma jhu yin se ooooo...... Amin.

Awon Oogun to lagbara niwonyi...e kan simi lori apo ifiwe ranse binaryteck@gmail.com
Re: .. by Lionhearted: 3:43pm On May 25, 2015
healthFirst:

Gbogbo ibeere wonyi tumo si wipe e kii se omo Yoruba.

Orikerike ara ni gbogbo eya ara to sepo...awon bi Ejika, Isepo Apa, Isepo Ese, orun ese, Orun owo, Igunpa ati beebe lo.

Eriru yato si Eeru...Eriru je eso ori igi, Eeru ni ajoku igi idana.

Tefa Ejiogbe tumo si wipe ka fi ika te Ifa Ejiogbe sori Iyerosun tabi Ebu Oogun.

Omo bibi ile yoruba ni mi sugbon idale ni abi mi si, ibe si ni moti kawe dagba.

Eseun alaye ye yin.

Ni pa ti tefa ejiogbe: iyerosun tabi Ebu Oogun tumo si?

2 Likes

Re: .. by OROSUNBOLB(m): 9:07pm On May 25, 2015
healthFirst:
27 OGUN TI OWU ALANTAKUN BA N KO ENIYAN LARA
Oku opolo kan ao ki igi bo lati enu ti yoo wole dada ti yoo ha mon ninu dada ao wa mun ao ma fi ko gbogbo jankariwo inu ile titi afi ni leri ara opolo yen mo ti aba ti se bayen tan ao gbodo fi owo kan mon, ao fi ada ge igi yen mo ao wa fi igi gbe sinu agbada ao jo pelu odidi atare kan sugbon ako gbodo fi owo kan ti oba ti jo tan na... ao wa lo epo obo ti yio kuna daada bi atike, ao wa da mo igba yen ni a to le fowo kan.

E joo e je ki ayika wa je mimo...awon kan wa to je wipe nitori idoti ayika won po ni Alantakun se ma n ta okun si ibi ti won n gba ti won le so wipe ise aye ni. Sugbon bi o ba je aarin igboro ni owu alantakun ti ma n ko wa lara nigba gbogbo, Oogun re to daju ni eleyi.

E ku ise o Baba. E jowo bawo ni ao se lo Ogun yi o ? E seun o,ewe a ma je o.

3 Likes 1 Share

Re: .. by sammyjay76(m): 9:22pm On May 25, 2015
healthFirst:

Awon Oogun to lagbara niwonyi...e kan simi lori apo ifiwe ranse binaryteck@gmail.com
Mo ti fi atejse kan ranse si yin lori email yin naa, e yewo ki e le ri......

Ngo ma reti idahun yn ni ekun rere.
E pe fun wa ooooo. Amin.
Re: .. by Nobody: 2:17pm On May 26, 2015
..

2 Likes

Re: .. by Nobody: 2:17pm On May 26, 2015
sammyjay76:

Mo ti fi atejse kan ranse si yin lori email yin naa, e yewo ki e le ri......

Ngo ma reti idahun yn ni ekun rere.
E pe fun wa ooooo. Amin.

Mo ti fi idahun ranse.
Re: .. by sammyjay76(m): 3:16pm On May 26, 2015
healthFirst:

Mo ti fi idahun ranse.
Mo kiyin o,
E dakun esi awon ibere mi ti e so wipe e t f ranse naa, mi o ri nnu email mi rara.

E jowo bami fi ranse si email mi naa lekan si.....sajolive6@gmail.com

E jowo eseun ooooo.
MO TI WA RI NI ISINYI, KO DA O SE SE WOLE LOWO LAIE NI......
ESEUN GAN MA TUN FI ESI RANSE LAIE YI.....
ESEUN GAN.
Re: .. by Nobody: 3:43pm On May 26, 2015
sammyjay76:

Mo kiyin o,
E dakun esi awon ibere mi ti e so wipe e t f ranse naa, mi o ri nnu email mi rara.

E jowo bami fi ranse si email mi naa lekan si.....sajolive6@gmail.com

E jowo eseun ooooo.
MO TI WA RI NI ISINYI, KO DA O SE SE WOLE LOWO LAIE NI......
ESEUN GAN MA TUN FI ESI RANSE LAIE YI.....
ESEUN GAN.

O dara.
Re: .. by scholes0(m): 4:46pm On May 26, 2015
E ku ise naa o... Oba eledua a maa fun yin se, Oogun yin a maa je!
E jowo, nje e le so fun mi ni awon nkan elo fun ogun afose? ati awon eto ti maa fi jo won po mo ara won?
Ti e ba fe gba adiresi mi lori ero ayelujara, ki a fi ranse si mi ni gbonkele, iyen naa da.
Re: .. by powell24ay: 2:09am On May 27, 2015
Ejoo, ewo ni o ye ki a se ninu eyonu tabi awure bi a ba fe lowo repete lai si pe eniyan seku?
Re: .. by Nobody: 10:07am On May 27, 2015
OROSUNBOLB:

E ku ise o Baba. E jowo bawo ni ao se lo Ogun yi o ? E seun o,ewe a ma je o.

Ao ma fi para

2 Likes

Re: .. by Nobody: 12:02pm On May 27, 2015
..

1 Like

Re: .. by Nobody: 12:04pm On May 27, 2015
scholes0:
E ku ise naa o... Oba eledua a maa fun yin se, Oogun yin a maa je!
E jowo, nje e le so fun mi ni awon nkan elo fun ogun afose? ati awon eto ti maa fi jo won po mo ara won?
Ti e ba fe gba adiresi mi lori ero ayelujara, ki a fi ranse si mi ni gbonkele, iyen naa da.

Afose Epe tabi Iwure?
Re: .. by Nobody: 12:06pm On May 27, 2015
powell24ay:
Ejoo, ewo ni o ye ki a se ninu eyonu tabi awure bi a ba fe lowo repete lai si pe eniyan seku?

Eyonu ni agba Awure...bi awon agba ba yonu si wa ni Oogun Awure yio to sise.

Mejeeji lo wulo fun nini owo ati ola sugbon Eyonu lo gbudo saaju.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 12:26pm On May 27, 2015
..

1 Like

Re: .. by powell24ay: 12:27pm On May 27, 2015
E se o baba. Agba yin a kale o. A oo maa ri yin ba.
Re: .. by Nobody: 12:56pm On May 27, 2015
x..

1 Like

Re: .. by Nobody: 1:57pm On May 27, 2015
...

3 Likes

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 35
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.