Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,366 members, 7,815,783 topics. Date: Thursday, 02 May 2024 at 06:16 PM

.. - Culture (80) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1828516 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (77) (78) (79) (80) (81) (82) (83) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by skolat1: 11:49pm On Jun 28, 2016
Eku lse takun takun
Re: .. by skolat1: 3:38pm On Jun 29, 2016
Ejoo se orogbo as in bitter cola?
Re: .. by MrMaggie: 12:44am On Jul 01, 2016
Aboru Aboye Ni Ile Ifa Oooo!
Ejowo ki ni iwulo ASO AGBA, ki is ni itumo ki eniyan ma ri ni agbegbe eniyan bi yara?.

BI BA ORI ENI SO ORO(NI GBOLOHUN).
Eko obi Abata(obi oloju merin) meji sinu ike(bowl) ti omi kekere wa ninu re, epa eyokan ninu obi na. Ki esi ko obi ti epa yi pelu owo kan, ki ebu omi die si ile(ori cement abi tile) ki esi wipe "Ile Mope" 3x, ki efi obi na kan ori yin lemete ki esi wipe "Ori Mope" 3x, e ba soro ki esi da obi na. To ba yan, meji abi meta ako oju si oke.

E jowo mi o ki n se onifa ooooo, sugbon omo odo agba ni mi.

Mo se iba Agba ooooo!
Re: .. by Zenlife: 8:02pm On Jul 01, 2016
dominicson:

Perhaps you need to pay her dowry again!

But this time to Osumare. It is always found at the riverside. When it is found, the simple ritual is made there, saying: Osumare, Osumare, Osumare, lati ijo alaye ti d'aye ni iwo Osumare ti n se oko odo, ko si si enikankan ti n ba o du. Lati oni yii lo enikeni ko gbodo ba mi du (your wife's name), be it her parents, her work, her boss, her anything. Mo ti mu owo ori re(do) wa fun iwo Osumare loni o, emi nikan ni kin ma ba se loko-laya o, ife t'emi nikan ni ki o ma gbile ninu re, oro mi nikan ni ki o ma wo o l'eti." You will then take one of the moneys paid to osumare, give to your wife to buy you something with it.

@ Domnicson
Bless your kindred heart sir.
Please what is Osumare? And what will be the indicator to let me know I found Osumare?
How much should be paid and how?

Your prompt response is anticipated.
Thank you sir.
Re: .. by emtar(m): 2:34am On Jul 02, 2016
[color=#990000][/color] Sir baba, i here request to give cure guide to someone that always cover with "spider-web". What to do by that person to cure it? God bless u. E seun baba.
Re: .. by dominicson: 10:01am On Jul 05, 2016
Zenlife:

@ Domnicson
Bless your kindred heart sir.
Please what is Osumare? And what will be the indicator to let me know I found Osumare?
How much should be paid and how?

Your prompt response is anticipated.
Thank you sir.

Things like this are always abused. But I will find a way of answering you privately. Best Regards
Re: .. by dominicson: 10:11am On Jul 05, 2016
emtar:
[color=#990000][/color] Sir baba, i here request to give cure guide to someone that always cover with "spider-web". What to do by that person to cure it? God bless u. E seun baba.

Brother, cases like this had been treated in this past on this thread. You will do yourself a lot of good if you 'scroll' back. And if truly you mean what you stated by "...always cover...", if it is not an exaggeration, I will advise you don't waste them, but convert them into what they truly are 'okun ola/thread of wealth'. Regards.
Re: .. by Legendbaba1(m): 8:56am On Jul 06, 2016
BABA KEPE I NEED HELP ABOUT STAPHYLOCOCCUS PLS HELP ME
Re: .. by Zenlife: 12:04pm On Jul 07, 2016
dominicson:

Brother, cases like this had been treated in this past on this thread. You will do yourself a lot of good if you 'scroll' back. And if truly you mean what you stated by "...always cover...", if it is not an exaggeration, I will advise you don't waste them, but convert them into what they truly are 'okun ola/thread of wealth'. Regards.

That's a twist as cobwebs generally denotes negativity. Kindly explain this premise sir.
Re: .. by samadexkay: 2:18pm On Jul 07, 2016
E ku ise takuntakun ni ikanni yi,iranse Olorun Olodumare ni gbogbo yin lagbara Olorun eo ni sise,bi e se nti awon eniyan sile nipa on te ni imo re eyin ati awon ebi yin gbogbo o ni wonu ide aye o.
Re: .. by samadexkay: 3:32pm On Jul 07, 2016
Eyin onimimo lori eto ni ikanni yi,e jowo e gba mi e rami kale nitori Eledumare,e jowo ti obirin ba pari nkan osu re tan,ti omi tun wa sese nwa ti omi yen si nrun,e jowo kini mo le lo fun iru eni be,e jowo ati on ti mole lo fun iju to ti di olo,Eledua o ni pada lehin eyin agba to ti ga,ko sini dojuti awa omode to nbo lehin.
IBA OLORUN,IBA EYIN AGBA.
Re: .. by tabithababy(f): 4:55pm On Jul 07, 2016
MrMaggie:
Aboru Aboye Ni Ile Ifa Oooo!
Ejowo ki ni iwulo ASO AGBA, ki is ni itumo ki eniyan ma ri ni agbegbe eniyan bi yara?.

BI BA ORI ENI SO ORO(NI GBOLOHUN).
Eko obi Abata(obi oloju merin) meji sinu ike(bowl) ti omi kekere wa ninu re, epa eyokan ninu obi na. Ki esi ko obi ti epa yi pelu owo kan, ki ebu omi die si ile(ori cement abi tile) ki esi wipe "Ile Mope" 3x, ki efi obi na kan ori yin lemete ki esi wipe "Ori Mope" 3x, e ba soro ki esi da obi na. To ba yan, meji abi meta ako oju si oke.

E jowo mi o ki n se onifa ooooo, sugbon omo odo agba ni mi.

Mo se iba Agba ooooo!
. E ku ise o baba. E jowo baba , se a maa so gbolohun oun ti afe beere si inu obi ti apa ti owa ni owo waa? Ati wipe owo otun abi owo alafia ni a ma ko obi ti a paa si? Ti eyokan ba ko oju soke nko abi ti gbogbo mererin ba da oju de ile ? Ki ni itumo re sir. E se pupo
Re: .. by dominicson: 10:33pm On Jul 07, 2016
Zenlife:

That's a twist as cobwebs generally denotes negativity. Kindly explain this premise sir.

The same way we were told black denotes negativity and evil, when in reality it is the black part of the eye that sees, when in reality there can never be light without the dark, like when we were in the womb. One is prelude to the other. Nothing is bad, nothing is good!

In its simplest frame, ti ogun(warfare) tabi owo(hand) ba ti po ju lara, ti a ba n gbiyanju, kii tete yo. Nitori wipe die die ni owo naa yoo ma kuro. Sugbon ti a ba se akiyesi pe o ba ri bayi, a ma da ogbon ki ibi yi pada ki o di ire, instead ti a se ma fi asiko kan ja ogun, ki a se se to wa ma wa ire, long process ni eyi. So, make better use of the very stones the enemies throw at you.

2 Likes

Re: .. by Zenlife: 12:04am On Jul 08, 2016

Nice perspective, how practicable though?
Re: .. by dominicson: 4:16pm On Jul 08, 2016
Zenlife:

Nice perspective, how practicable though?

Easy, very.
Re: .. by MrMaggie: 5:38pm On Jul 08, 2016
tabithababy:
. E ku ise o baba. E jowo baba , se a maa so gbolohun oun ti afe beere si inu obi ti apa ti owa ni owo waa? Ati wipe owo otun abi owo alafia ni a ma ko obi ti a paa si? Ti eyokan ba ko oju soke nko abi ti gbogbo mererin ba da oju de ile ? Ki ni itumo re sir. E se pupo

Ema bere nka ti efe ni owo ori yi ni(fun apare, boya e need owo fun nkan nkan abi e fe isegun lori nkan nkan), adara ki eko obi na is owo otun(right hand). Ti eyokan ba koju si oke, abi gbogbo loda oju dele. Otumo si pe nkan te bere si ko ri be, ki enina lo bo ori re.
Re: .. by MrMaggie: 5:49pm On Jul 08, 2016
Ifankaleluya:
Awure
Iha epo,
Ejinrin were,
Aso Eegun,
Odidi atare kan
Ao jo po, a o ma fi sa ori
Ofo re: iha ni sariya ina, ejinrin ni sariya iti, tomode-tagba ni se aariya egun, tewe-tagba ni ko ma fi owo sariya mi.
Aboru, Aboye, Abosise.

Eku Ise Takun Takun, Oluwa O ni Piyin Ni pa ooo, ejowo ki ni iwulo "Aso Agba" ati ki ni itunmo ki eniyan ma ri ni agbegbe re bi iyara(room)?. Yato si eleyi, ki ni itunmo ki Eye ya egbe si nkan ini eniyan(car) ni oru mojumo ti enina se ebe agba(make a sacrifice) ?... Ese ma dupepe, ti e ba le lami ni oye lori awon nkan wonyi.

1 Like

Re: .. by MrMaggie: 6:01pm On Jul 08, 2016
dominicson:

Things like this are always abused. But I will find a way of answering you privately. Best Regards

Eku Ise Takun Takun, Oluwa O ni Piyin Ni pa ooo, ejowo ki ni iwulo "Aso Agba" ati ki ni itunmo ki eniyan ma ri ni agbegbe re bi iyara(room)?. Yato si eleyi, ki ni itunmo ki Eye ya egbe si nkan ini eniyan(car) ni oru mojumo ni eyin igba ti enina se ebe agba(make a sacrifice) ?... Ese ma dupepe, ti e ba le lami ni oye lori awon nkan wonyi.
Re: .. by samadexkay: 7:09pm On Jul 08, 2016
Eyin agbalagba ti Eledua gbe ise idande omo araye le lowo e jowo e mo salai fesi si oro mi,awon to nile o ni fise isese yi bu yin,e jowo e gboro mi ro nitori IFA ti Eledua ran sile aye,yo ma ju yin se o.
Mo seba agba
Re: .. by dominicson: 7:25pm On Jul 08, 2016
MrMaggie:

Eku Ise Takun Takun, Oluwa O ni Piyin Ni pa ooo, ejowo ki ni iwulo "Aso Agba" ati ki ni itunmo ki eniyan ma ri ni agbegbe re bi iyara(room)?. Yato si eleyi, ki ni itunmo ki Eye ya egbe si nkan ini eniyan(car) ni oru mojumo ni eyin igba ti enina se ebe agba(make a sacrifice) ?... Ese ma dupepe, ti e ba le lami ni oye lori awon nkan wonyi.
Re: .. by samadexkay: 8:40am On Jul 09, 2016
Ifankaleluya:
Apete ti a ma n fi sara to sise ibon, Ada, Okuta, Apola or whatever,

Ti a ba se Apete yi tan, ti o ba wa lara wa, ti won ba yin ibon(gun) mo wa, eni ti o yin ibon yen yio si di Aka(re mi)(Adete) lesekese.

Ao lo re wa ewe-ina pupa, ewe-esisi, Ahun, ewe-airagba, Aso-aka. Oruka ti ko wo omi iyekiye. E je kin da enu duro nibi tori awon oni-ise ibi.

Baba ifankaleluya whatsapp number mi niyi :-07080319823,
Email mi :- adesamkay1@gmail.com
E jowo mo fe ka soro labe aso
IBA OLORUN IBA AGBALAGBA

Re: .. by emtar(m): 10:11pm On Jul 09, 2016
dominicson:

Brother, cases like this had been treated in this past on this thread. You will do yourself a lot of good if you 'scroll' back. And if truly you mean what you stated by "...always cover...", if it is not an exaggeration, I will advise you don't waste them, but convert them into what they truly are 'okun ola/thread of wealth'. Regards.
baba ejowo e bami se alaye bi a se le remove it totally or how to turn it to okun ola/ thread of wealth. E se gan ni baba
Re: .. by emtar(m): 10:15pm On Jul 09, 2016
dominicson:

Brother, cases like this had been treated in this past on this thread. You will do yourself a lot of good if you 'scroll' back. And if truly you mean what you stated by "...always cover...", if it is not an exaggeration, I will advise you don't waste them, but convert them into what they truly are 'okun ola/thread of wealth'. Regards.
thank for d advice baba. Pls help for d solution on how to turn it to wealth or how to bared it totally. Thanks baba
Re: .. by emtar(m): 11:30pm On Jul 09, 2016
walexy30:

E SE PUPO
baba thank ooooo. Sir kindly tell us how to turn the cobweb on d body to thread of wealth? Stay blessed baba
Re: .. by emtar(m): 12:38am On Jul 10, 2016
OROSUNBOLB:

E ku ise o Baba. E jowo bawo ni ao se lo Ogun yi o ? E seun o,ewe a ma je o.
sir how do we now finish the preparation of this egbogi and how do we now use it ? Stay blessed baba
Re: .. by Legendbaba1(m): 3:25am On Jul 10, 2016
BABA KEPE pls help me what can I use for Staphylococcus to cure it. BABA EKU ISE OOO OLOHUN AWA PELU YII AMIN EJO WO E FUN MI NI OGUN STAPHYLOCOCCUS AMA JUSE FUN YI AMIN ASE
Re: .. by OROSUNBOLB(m): 8:24am On Jul 10, 2016
emtar:
sir how do we now finish the preparation of this egbogi and how do we now use it ? Stay blessed baba

You're obviously not Yoruba or you chose to go against the Op's instruction. He stated clearly that communication as regard this subject must be in Yoruba language. So who are you trying to impress with your 'Queen's English'?

Strictly Yoruba please !
Re: .. by emtar(m): 4:57pm On Jul 12, 2016
Zenlife:

That's a twist as cobwebs generally denotes negativity. Kindly explain this premise sir.
Baba, e ku agbaa le ati iranwo yin ooo. Ewe ati egbo a maa je ooo. Ejowo, e bami pari akotan ayipada manjala ti enia maa nfi ara nko ni ile ati lode gbamgba nigbogbo igba. Ajuseee. Ase waaaaaa
Re: .. by dominicson: 4:05am On Jul 13, 2016
Eewo! Taboos/eewo are not superstitions, and shouldn't be taken for such. They are real. Although, most of our social and cultural taboos were invented to make our societies sane, hygienic and ensure good neighbourliness. For instance, taboos like: a ko gbodo fi owo(hand) ko ile ti a gba jo danu; a ko gbodo ji ri epo egusi tabi ki a te mole ni owuro; a ko gbodo rin koja labe akaso, have no natural consequences, unless enforced by the elders. No need asking why. But taboos like: a ko gbodo pe metala jehun ni oju kanna tabi ninu awo kanna; obirin ko gbodo fi oju kan oro; onisango ko gbodo je sese; alagbede ko gbodo je ire; olobatala ko gbodo mu emu, beeni won ko gbodo ru eku, have natural consequences if violated. Yoruba tun gba gbo wipe eniti o ba gbe aake sinu oorun, ori fifo ni yoo pa onitoun; ti enia ba si gbe e sinu ojo(rain), ara(thunder) ni ma n san pa iru won. Consequences like these are bound to occur if you knowingly violates these taboos. Sugbon o, aimo kii pa omo-olomo.

However, the case is a bit different with taboos that go with charms, and those that are personal taboos. If a man breaks his personal taboos, knowingly or otherwise, he makes life difficult for himself. And here it should be stressed that ignorance is not an excuse. Yes, for we incarnate just because there are yet things we need to learn. Self-knowledge. Know thyself! Purpose of our existence. A man must seek to know his personal taboos(do's and don'ts). You should know what you shouldn't wear(colour), what you shouldn't eat(food), where you shouldn't live, and so on, and on the other hand, what you should do, eat, wear; who you should marry, day of the week you should cut/do your hair...

Charms' taboos too are similar in term of severe consequences. Most charms have taboo, except you don't know it! The very reason some charms are not effective, or so they seem. However it is only charms' taboos with catastrophic consequences that were mostly stressed by our forebears, while those that do not cause more harm than reducing the potency of charms were mostly ignored.

And ordinarily, due to human nature, man lusts or longs for the forbidden. So it happens that when you take/use a powerful charm, there will naturally be an urge to break its taboo(but if you know what such taboo is you will be able to check this urge), and also when you use a powerful oshole you will feel like making out, even though you could win an oscar for abstinence.

If you don't know the concomitant taboo of a charm, please don't do it. And if you know you cannot observe/follow the taboo of a particular charm please don't use it. Very many of life's challenges/problems we resort to charms to solve are caused by violating/breaking taboos (personal taboo especially) and can easily be solved by retracing our steps, observing our personal taboos and not violating charms' taboo.

Ela boru, Ela boye, Ela bosise!

2 Likes

Re: .. by Raydos: 5:32pm On Jul 13, 2016
Jadonjack:
Ejowo, mo nilo ogun ikiya.. Aya mi man tete jah ju
ole ni arakunrin yi sha, kilo n ja e l'aya? cheesy
Re: .. by samadexkay: 8:59pm On Jul 13, 2016
dominicson:
Imule 4:

Olongbo nla kan, owo eyo ogoji(ailu), ewe oriji oojo, atare kan. A o jo papo, ao te ebu yii ni ogbe meji/eji ogbe, a o ro itan/ofo/gbolohun/psalm re si, a o ro sinu ato/seere/ado.

Psalm:

Iweku-ni-iweku, iweja-ni-iweja, a difa fun okanlenirinwo n'ijo ti won lo re yan ipin l'odo Oodua. Won pin aje(wealth) fun Olubini, won pin okun(re do) fun Olurada, won pin ide fun Osun, won pin oje fun Orisa-nla, won pin irin dudu fun ogun, won pin igba omi fun Agbonmeregun, won pin ile(land) fun Oba l'ode Oyo(do mi), won pin isekuse fun Esu Odara. Asotito bo s'ile, o gba aje lowo Olubini, o gba okun lowo Olurada, o gba ide lowo Osun, o gba oje lowo Orisa-nla, o gba irin dudu lowo Ogun, o gba igba omi lowo Agbonmeregun, o gba ile lowo Oba l'ode Oyo. Won wa ni ki Esu o mu isekuse owo re wa, Esu ni ki won o fi ti oun ji oun. Won ni ee ti ri? O ni se bi oba ni eyin, ologinni ni oun. Ati ile, ati ona ni oba fi n ji ologinni, eyin alaye, e wa fi adun aye gbogbo ji mi. Orijin lo ni ki e fi gbogbo ire ti n be ni ode isalaye ji mi. Nitoripe apejin(do do do) ni ti ogoji, e fi ire nla nla ji mi, e fi asise mi gbogbo ji mi o.

Re: .. by dominicson: 9:15pm On Jul 13, 2016
emtar:
thank for d advice baba. Pls help for d solution on how to turn it to wealth or how to bared it totally. Thanks baba

Drop your number, it is already on 'Isese Lagba', our whatsapp group. I will add you. Typing is not that easy. Regards

2 Likes

(1) (2) (3) ... (77) (78) (79) (80) (81) (82) (83) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 59
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.