Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,194,260 members, 7,953,995 topics. Date: Friday, 20 September 2024 at 10:29 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (201568 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) ... (100) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 1:28pm On Feb 18, 2009 |
Ogaga4Luv: He said yu shuldnt bother visiting a doctor, bkuz yur disease has no remedy! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by toffee2lov: 1:58pm On Feb 18, 2009 |
kini o nsele nibiyi na abi se efe so forum yi di ti awon omo-wole, iya re buekun ni? abi ti eyin mejeji bafe bara yin se isekuse se e ko ni phone tabi e-mail ti ele fi barayin soro ni? Abi se ekolojuti ni? OGA FUN YIN OOOOOOOOOOOOOOOO |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by lauryngal(f): 2:06pm On Feb 18, 2009 |
ma da awon meje ji lohun, mo nfe ki e mo npe awon ko ara won je. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 2:13pm On Feb 18, 2009 |
Farotika, Sha ma wo mi. Emi ni won pe ni Ase ale gege ni eni ti ko ri obinrin ri. Se o ye o. Ologbon lo ma ye. Omaran ni yo mo idi re. Debosky, O ye wa. E ku ise oh. A mo riri Ise lantu lantu ti en se ni abe Ennyluv, Se e nro oko nibe ni abi e n gbe kanga? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ogaga4Luv(m): 2:29pm On Feb 18, 2009 |
Dammm. . . . Debosky,you are insulting me with your flaming words,KILOSHELE?,KILORUNKUNRE?.,by the way,do you have jim carey in the area you live in?.eh. . .eh!!,that black Papaz cap you put on may be the case Bleep. , hey baby. . .,thanks for the Link and hoping to learn the YORUBA langua here with you guyz$$$. OshiezÖ_gizo!,One_Love |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ben13: 2:39pm On Feb 18, 2009 |
yoruba |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 6:37pm On Feb 18, 2009 |
dayokanu: Emi ke? Iwo ni Oko Ennyluv, nitori naa, iwo ni o n'ise lantu lantu labe aya e owon. Ise ti mo n'se ni pe ki n'fi iso ati igi kan ibusun titun fun iwo ati Ennyluv. Nigba ti e n'sere ife ni ijosi ni e fi idi nla wo ibusun ti e n'lo tele. Mo ti kilo fun iwo ati ennyluv pe ki e lo se ise agbara (exercise) die ki ara yin le fuye sii. Oju n'fa aso ya, ese n'ja bata, idi nla ennyluv n'wo ibusun |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Sauron1: 7:40pm On Feb 18, 2009 |
debosky: U need deliverance. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by TOYOSI20(f): 8:13pm On Feb 18, 2009 |
farotika: Ewo wa ni ti yin nibe nisin, why take panadol for anutha mans headache. . . oda ipe gbefila yin ti fe ma poju oo, Bro Farotika, e je lo wa toyin se, Mon dure de yin oo, im ready for your mouth too, emi gan gan bad mouth Ogaga4Luv: Ahhh oda motigbo oo, but it aint really a nice word sha , keep tuned on to the thread, u'll learn if u are willing Good luck to u oo!!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ogaga4Luv(m): 8:36pm On Feb 18, 2009 |
Peace! ,im here to learn please. . . Dont!,Dont kick me off! , Nice there are some experts of YORUBA in the "Mad_House",merry meet!. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by TOYOSI20(f): 8:41pm On Feb 18, 2009 |
Nahhhh, it aint even like that, no ones kicking u out oo , u are most welcome like i said earlier on, "ekabo so ri eto wa", means welcome aboard!!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ogaga4Luv(m): 12:08am On Feb 19, 2009 |
thank you TOYOSI, now im convinced with ya kind words.Bless_be! But pls one more thing,help me to talk to Debosky in Yoruba ,it seems i knew him back then in Eko O . TOYOSI20: |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ogaga4Luv(m): 12:17am On Feb 19, 2009 |
i think my ball & socket joint may be deceiving me ever since.,Deboskyy!!!!!!!!!!. :oi knew you!! back then @ Eko.,i really have to clearify this from you.,here is you Photo as an Evidience you look fammilliar and if i have mistaken somewhere,i Apologise., debosky:
|
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 12:19am On Feb 19, 2009 |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ogaga4Luv(m): 12:23am On Feb 19, 2009 |
Whats so Funny?,why are you shocked and Shining your eyes? ikamefa: |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 12:36am On Feb 19, 2009 |
ma binu oh, na that japanese coat dey flabberwhelm me sorry! carry go jare ! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 1:49am On Feb 19, 2009 |
Ewo bi ori Debosky se tobi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 3:10am On Feb 19, 2009 |
Debosky, A gbo wipe ere fisi fayo ti iwo n ba Ennyluv se ni o fa gbogbo yapan yarin yen. E wo bi deboski she ku ori nikan o ti se irannu jina |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:22am On Feb 19, 2009 |
dayokanu: Mo ti gbo o. Sa ma je ki obinrin abeyinto lasan lasan ma da e riba ribo Si debo, O to ojo meta ati abo, se tori obinrin naa lo se sa fun awa tie. O ga o. Wahala ti obinrin ma da sile, owo won o ni ka |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:51am On Feb 19, 2009 |
TOYOSI20: Se emi ni omo kekere yi nba soro kunba kungbe Pekele pekele, arugbo je gbese tani o san Se o ro pe dayo orobinrin dori ni o nba soro ni Wobi aburo, o o le fi emi sako o. Ti o ba de soro to koja enu e, ma fi nkan ti agba fi ju omode lo won e Olodo nla. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 10:09am On Feb 19, 2009 |
Ogaga4Luv: Yeepa Se debo ni eyinju e dabi ti ojola yi. O ga ooooooo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 10:20am On Feb 19, 2009 |
dayokanu: Olorun a dariji bobo yen o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 10:26am On Feb 19, 2009 |
Farotika ati Dayokanu E ronupiwada o! Eye ba oruko mi je ninu ilu nairaland yii o. Emi o tii f'enu kan obirin, lai tie so pe ki n'ma sere fisi fayo. Omo Wooli ni mo je, mo si wa ni ile eko lati di Wooli lojo iwaju. Ejowo e ba mi kilo fun ogbeni ogaga yii o, oda bi n'pe ogogoro ti da opolo e ru patapata. Aworan mi ko ni ogbeni yen gbe yo, oruko mi ki n'se ojuyobo Mio mo ogbeni yii, mio si ni nkankan se pelu e rii l'Eko tabi ni oke okun. Nitori naa, ti mo ba tun gbo iru iro yen, mo ba binu gaan ni. Ibinu mi ko de ni dara. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by TOYOSI20(f): 12:43am On Feb 20, 2009 |
farotika: Ummmmm. . . .nigbati eti wa bumi tan abi . . . . . .e le she nka kan jare, e wo arugbo naa lon ma san gbese won, abi kitun ni sef?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 4:16am On Feb 20, 2009 |
Eni won tori e na mi, Ni n o pada fe ni oro emi ati Toyosi. Omotoyosi, Ma ko oju mi si Oorun ale. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 4:24pm On Feb 20, 2009 |
Abi ori gbogbo yin fe fokasibe ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by glorina: 5:12pm On Feb 20, 2009 |
Mo ki gbogbo yin. bawo ni? se e wa pa? Asiko igbadun ni mo wa yi. Eni keni ti o ba fe ba mi gbadun e ko jekin mo o. Emi yi o ma reti yin. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ogaga4Luv(m): 9:10pm On Feb 20, 2009 |
alright then, Odàro-O!!,ekàbo,Ekushe,ekunrin,gbogbolaye,eniobo,Otijeghe,Ohoro oo oo ikamefa: |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Jcob(m): 10:17pm On Feb 20, 2009 |
Nkan tan bawi fun ogbon ni ogbon ngbo, nkan tan bawi fogba logba ngba. Lati isin lo ki ori Dayokanu wa si ile nitori oti je efo ati eja aro lati owo Toyosi. Ife si n daaa laamu. Chamo ori iwo naa fokasibe. . . .olenu gan. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 10:31pm On Feb 20, 2009 |
Jcob:se chamotex ni wa nbu be yen? rotfl farotika:Farotika, o ma ti pe. ojo meta! Sugbon se aburo mi lo nbu be yen? sho ara e ooooooooo. . . . Bawo ni Miss.M |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Jcob(m): 11:02pm On Feb 20, 2009 |
Iyen nipe Nike gbo yoruba to yii. Mo gbedi fun e o. Bawo ni gbogbo nkan. Se daadaa ni? Awon Broda nko? Bami ki Aburo re ni NL. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 11:14pm On Feb 20, 2009 |
Ogaga4Luv: right back at cha oh! eyi ta ba wi fo gbo, logbo n gbo eyi ta ba wi fo gba logba n gba kose! kose! ni ti ilakose! tuaaaaaaaaaaaaaaaaaaaah! " " |
(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) ... (100)
Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations) / HAUSALAND: Teach Me Hausa
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 44 |