Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,757 members, 7,817,092 topics. Date: Saturday, 04 May 2024 at 04:45 AM

Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira (5453 Views)

Lilo Ewe Ati Egbo Fun Iwosan, Itusile Ati Aseyori / LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI / Ibadan Omo Ajorosun: Ohun To Ye Ke E Mo Nipa Ilu Ibadan (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (Reply) (Go Down)

Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 7:21pm On May 17, 2015
Brent: Ipa pin fun ni 70USD nitori ko koja ibe ni ose yi. yio bere si nta gidi gan ni ose to nbo. Ta a lati isin yi lo.
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 10:47am On May 18, 2015
Brent: Bi o ti le je pe Saudi Arabia ati awon ore re nya ina fun Esinkokoku Yemen ti o si mu Brenti fo soke l'oru mojumo. Ta a gidi gan ni gbogbo igba ti o ba fo s'oke. Fi TP re si 62.58USD. Owo ba de.

Sugbon fun ojo pipe die ni bi i ose kan lati ko ere re.

GBPUSD: E je ki o se retracement lo si 1.5810; lehin igba yen ti ko ba tayo 1.5814 ni ose yi, o ya e ta a danu. sugbon e ni suuru ki o se retracement lo si 1.5814 titi di ojo Eti (Friday).
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 6:39pm On May 18, 2015
AUDUSD: Wa yio, e ja ka Raa (Buy) ni 0.7980; nitori o ma retrace ibi ti o de l'ose to ko ja ti nse 0.8162.

Ti ko ba le ko ja re titi ojo eti (Friday), a le bere si ntaa lati ose to nbo lo.

Pivot point ose yi je 0.8023.
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 6:44pm On May 18, 2015
USDJPY: O GA O, oga Ade yi ma ko jale ko ma fe re koja 119.92. Sise lo npin ken lati re koja re. O dabi enipe oti re ija fun pair yio.

Ti a ba wo o titi ale eni yi, ti ko ba re koja re (119.92), e taa danu ki e pawo sapo joor.
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by scholes0(m): 7:02pm On May 18, 2015
Gbogbo nkan ti e ko wonyii, fi han wipe, imo ede yoruba yin jinle gan!
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 9:17pm On May 18, 2015
scholes0:
Gbogbo nkan ti e ko wonyii, fi han wipe, imo ede yoruba yin jinle gan!

E se gan
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 8:04pm On May 20, 2015
EURUSD: Ta a ni 1.1140 TP 1.1070 titi di aro ola fun ere 70 pips.
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 8:11pm On May 20, 2015
GBPUSD: TA A NI 1.5575 TP@ 1.5460
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 8:23pm On May 20, 2015
Brent Crude ti o wa nipamo ni Amerika wa sile ni iwon 2.674m bareli. Eyi tumo si pe Amerika ko ra brenti crude l'ose to ko ja.

Ipa ti eleyi ma ni lori iye crude ni wipe yi o ja wale nitori kosi Demand lati Amerika L'ose to koja.

Wa yio, e ta a ni $65; ki e si fi ere yin si (TP) $57

1 Like 2 Shares

Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 7:38pm On May 23, 2015
GBPUSD, EURUSD, AUDUSD. Wayi ti awon pairs yi kuna lati re koja 5814, 1.1472 (61.8% fib) ati 8168: e ta won ni gbogbo igba ti won ba fo soke (sell the rallies).

Brenti: E taa ni gbogbo igba ti o ba fo soke.
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Ishilove: 9:20pm On May 23, 2015
Eku o raje cheesy
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 12:12am On May 24, 2015
Ishilove:
Eku o raje cheesy
'Eku oro aje'
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Ishilove: 6:22am On May 24, 2015
laykorn:

'Eku oro aje'
Ese pupo grin
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Ishilove: 6:24am On May 24, 2015
walexy30:
Brent Crude ti o wa nipamo ni Amerika wa sile ni iwon 2.674m bareli. Eyi tumo si pe Amerika ko ra brenti crude l'ose to ko ja.

Ipa ti eleyi ma ni lori iye crude ni wipe yi o ja wale nitori kosi Demand lati Amerika L'ose to koja.

Wa yio, e ta a ni $65; ki e si fi ere yin si (TP) $57
Se 'demand' ni ede Yooba? Ma ko si ede igeesi. Ko ni ede Yooba patapata angry
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 7:15am On May 24, 2015
Ishilove:

Se 'demand' ni ede Yooba? Ma ko si ede igeesi. Ko ni ede Yooba patapata angry

Demand tumo si ibeere fun oja
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Ishilove: 3:00pm On May 24, 2015
walexy30:

Demand tumo si ibeere fun oja
Mo ti gbo.
Eku oro aje cheesy
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 8:57pm On May 26, 2015
EURUSD, GBPUSD: Wayi, egbaradi fun correction lo si oke. charti ojo (daily chart) ti nfi ataju han (oversold).

Nitorina, e ko ere yin lori sell orders yin nisinyi; ki e je ko fo soke ki etun ta won gidi gan.
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 6:36am On May 27, 2015
GBPUSD, EURUSD: E ra won nisinyi ni 15418 ati 10910 nitori correction yi wa nipo.

E fa gile tita yin. pivots won niyi 1.5405 ati 1.0907
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Ishilove: 2:01pm On May 27, 2015
I for like know wetin this bobo dey yarn us o.... I know it's about forex...

Those ultra Yorubas on the forum like OduaVanguard, MayorOfLagos and co should take a break from tribal bashing and come and translate this op's post...
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by scholes0(m): 3:22pm On May 27, 2015
Ishilove:
I for like know wetin this bobo dey yarn us o.... I know it's about forex...

Those ultra Yorubas on the forum like OduaVanguard, MayorOfLagos and co should take a break from tribal bashing and come and translate this op's post...

Kini nkan naa ni pato, ti o wu e lati mo nipa, tabi to o fe ki n salaye fun e?

meaning: What is it exactly, that you would like to know, or explain to you?
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Ishilove: 3:24pm On May 27, 2015
scholes0:


Kini nnkan naa pato, ti o ma wu e lati mo, tabi to o fe ki n salaye fun e?

meaning: What is it exactly, that you would like to know, or explain to you?
Everything grin
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by scholes0(m): 3:27pm On May 27, 2015
Ishilove:

Everything grin

O fe mo nipa gbogbo nkan to ore mi nibi nso abi?
O daa naa, O n soro nipa tita ati rira, agaga ni ori isowo oja gbanjo, ni ori ero isowo.

meaning: You want to know abut everything which my friend here is talking about?
Okay then, He is talking about buying and selling, especially on the trade of auction commodities.
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 10:52pm On May 27, 2015
EURUSD: Iroyin ayo ranpe ti o seyo ni Greece mi oja logbologbo; bi o se fo soke lo ja wale ti o si tun fo soke pada (strong volatility).

RSI (Relative strength index) wa ni isale patapata lori charti 4 hours. Nitorina, so ara fun tita pair yi.
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 6:46pm On May 28, 2015
GBPUSD: E ta a ni 1.5312 TP 1.5075.
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 10:19pm On May 31, 2015
EURUSD: E taa ni 1.1000; E fi ere yin si 1.0075 titi osu pari. O duro fun 925 pips.
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 5:24pm On Jun 01, 2015
Brenti: Kandu meji gunrege (Double tops) fe yo jade ni charti ojo; 65.67 ni ibi ti o ni apere leni. E bere si nta a lati isinyi lo.
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 10:49am On Jun 02, 2015
GBPUSD: E TAA NI 1.5252 NISINYI
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 4:43am On Jun 04, 2015
USDCAD: Ra a ni 1.2450 Tp: 1.2640
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 4:48am On Jun 04, 2015
Desktop, bawo ni
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 4:40pm On Jun 04, 2015
USDCAD: E ko ere yin nisinyi ni 1.2488.
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 2:20pm On Jun 05, 2015
NZDUSD: RA A NI 0.7040 nisinyi
Re: Forexi Ati Comoditi: Imoran Nipa Tita Ati Rira by Nobody: 2:21pm On Jun 05, 2015
Ijoba Amerika pe se ise 280,000 (NFP) l'osu ti o ko ja. eyi mu ki dollar duro sinsin gan ni eni.

(1) (2) (3) (Reply)

‘olojo’ Festival: Ooni Goes Into Seven-day Seclusion / Bini Is A Lost Tribe Of Isreal / Kedu Onye Nwere Ike Ikowa Ebe Ndi Igbo Siri Puta

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 27
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.