Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,154,742 members, 7,824,142 topics. Date: Saturday, 11 May 2024 at 12:24 AM

Iwulo Moringa Fun Agoara Wa - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Iwulo Moringa Fun Agoara Wa (5289 Views)

Asiri Ogun Awon Baba Wa / Ogun Awon Bàba Wa / Mi O Le Wa Je Ki Awujo Ero Ayelujara Ma Dari Igbesi Aye Mi - Kate Henshaw (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Iwulo Moringa Fun Agoara Wa by 08101646045atwp(m): 2:18pm On Jan 29, 2016
Kini iwulo moringa fun alafia ara wa?
Re: Iwulo Moringa Fun Agoara Wa by 08101646045atwp(m): 12:14am On Feb 02, 2016
Moringa je igi kekere kan, toje pe Ti eniyan banro nu nipa iwosan tabi aisan ba nse Ni, tawa nronu nipa iwosan aki ronu lo si moringa rara, opolopo losi gbin si inu compound sugbon ti won omon iwulore rara, ti aba nsoro nipa Moringa, Ninu iwadi wa ati ajoro wa, oje koye wape ase Olorun po larare ninu iwe exodus 15:22-27 fi honpe igi yi Ni Olorun toka si fun awon Iranse re, Ni bai ao ma mun diedie wa ninu awon aisan ti onko oju ijasi Ni ago ara.
. BI ATI NPINLE MORINGA NI LILO
AO ja ewe moriga ao to tutu dada, ao san nu ninu Omi tomon, ao sa si ibiti oorun koti nipaa rara ti ofi ma gbe, toba gbe, ao lo ti yio kun na daadaa, ao mafi si inu gbogbo onjije wa, asile po mu,sugbon leyin osukan, kolagbara mo. Odara pupo fun ago ara wa,
Awon aisan ti nkoju ati bi ao se malo koju awon aisan kookan, ati idanu si ibeere nipa bawo laselelo fun irufe awon aisan ti ankoju Ni ago ara wa edele ba baba moringa soro Ni idako nko, Ni ori ero P.Arojah08101646045@gmail.com or owhatsapp fun idaun si awon ibere tie. Ema bawakalo...
1)FUN EJE RIRU
2)FUN AIDS
3)FUN DIABETES ITO SUGAR
4)JEDIJEDI PILL TROUBLE
5)AISAN OJU/EYES DISEASES
6)MEASLES DISEASES/IGBONA
7)RHEUMATISMS/ARUNMO LEGUN
coolFEVER AND WORMS/IBA ATI ARA GBIGBONA
9)COUGH OR CATARRH/ IKO ATI OFINKIN
10)ASTHMATIC ATTACK

(1) (Reply)

PHOTOS: See The Inside Of The New Ooni Of Ife Palace. / Yorubas And The Ancient Egypt Connection / Weird Facts From Around The World

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 8
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.