Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,155,670 members, 7,827,458 topics. Date: Tuesday, 14 May 2024 at 12:22 PM

Awon Asiwaju Wa Ti Dab. Fun Awon Ti O Ba Leka Yoruba. - Politics - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Awon Asiwaju Wa Ti Dab. Fun Awon Ti O Ba Leka Yoruba. (766 Views)

Atiku Abubakar Learns The "Dab" Dance (photos) / Bayo Adeyinka Wrote:open Letter To Asiwaju Bola Ahmed Tinubu / Students 'Dab' For Kebbi Governor Bagudu During Parade. Photos (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Awon Asiwaju Wa Ti Dab. Fun Awon Ti O Ba Leka Yoruba. by iammrjohnson(m): 10:22am On Apr 08, 2016
ekaaro o. o da bi eni pe oro wa ni nigeria yi bayi ti waa gba epe gidi gidi. e duro na, she oloriburuku ni awon asiwaju wa ni? abi aye won fe baje lapapo ni? latigbati didinrin alainironu minisita fun epo robi yen ti soro radarada lori afefe wipe ohun komo ibi ti awon oni filling station gann tin ri epo ta ni igboro ti daru. epo robi ti wa di N300 fun lita kan, aatun ni rira nirorun. ila awon to fe ra epo ni filling station naa wa gun bi ewon jonathan. alayebaje jonathan ati iyawo e to da bi apo garri ti won ji gbe ni bodija yen, won shi ma lo sewon.
latigbati buhari ti lo bi osu mefa to loun nwa awon minisita to yekoro kiri ni mo ti pe iru iro nborun, radarada lomaa gbeyin oshi oriburuku ton ba kaakiri nigbayen. bimo she feran fasola to, kii she bi ki ohun nikan maa da pase minisitiri nla nla meta. ina nepa ti waa di oshi robo kale, awon alainishe yen naa, won ni awon o le ta ina 1000 naira mo, pe 2000 naira ni ina to kere ju ti awon leta. mo wa bere lowo won wipe 'abi aye yin fe baje mon tile ni? kofe dafun awon ti niyin ni? abi ori gbogbo wa tie ti buru ni nigeria yii ni? she baba nla baba yin lohun shishe owo simi lowo ni? abi kofe ye yin ni?'.
shebi ohun to ba deba ori lodeba orun ati gbogbo ara. ti kii base aboki president waa ati 'danku ara wa ni' vice president wa to je wipe opolo jina siwon, tiwon wan shoshi bi eran to she iwo kaakiri agbaye, shebi gbogbo nkan o ba ma dojuru bayi. shugbon, baba were,opa gboro omo fulani yen, koni joko si nigeria. o wan fi owo wa she honeymoon kaakiri agbaye. eyi to tie man dun mi ju nibe nipe, aawa tun maa paro pe won ti fun ohun ni oruko gbogbo awon to kowo je ti won si kolo si oke okun, shugbon kodaru ko enikan shosho, iro ni, oloriburuku ara won a so pe awon n shishe lori won lowo. e ti ya were, ishe lago nshe ku, ishe ori buruku yen lema she ku. eyin ti koni yen yin kale yi.
tikii baishe aifekan she, tani o mo pe ogbologbo onigoloju tinubu to da bi eran ibiye yen, baba nla corruption ni.

shugbo won ni pe ile to ban dun omo ale ibe o tii dagba ni. awon omo ale ti wa yapa bi eruku bayi, ona wo lafe gbegba ti oro ilu yi a fi dara? koye mi o, shugbon lati eni yi lo, epe ni maa fi ba aye gbogbo won je.

1 Like

(1) (Reply)

Biafra:.....and Director Spoke. / How Abia State Commercialise Kidnappings In Nigeria – akpabio / Height Of Deciet In Minna (niger State).

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 14
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.