Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,154,740 members, 7,824,135 topics. Date: Saturday, 11 May 2024 at 12:04 AM

Majemun Lailai - Health - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Majemun Lailai (45425 Views)

(2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Majemun Lailai by 08101646045atwp(m): 8:23am On Jun 02, 2016
OSE IGBEGA LENU ISE TODAJU:
Awo ekun ,ewe sawerepepe ,ewe ogede agbagba ati ewe aanu. Jijo po pelu odindin atare kan, ao po mo ose dudu tabi ose toba wun wa, ao ko sinu ike funfun ao fima we.
Ogun Asegbe
Ewe imi esu ati alubosa elewe ao gun papo ao da sinu kolobo ao da ogere epo pupa si ao mala
NB Ise yi dara pupo lona eto gege bi owo fun awan janduku wan ko nile diwa lowo toba lo lona aito koni sise kokinsepe man jemu ise nan
Eyonu odaju
Ewe imin esu epo obo ao gun papo month ose dudu ao mafi we, iseyi kere loju sugbon odara pupo
Aseje Owo togbona
Ewe imi esu eyokan tojo, ao loma iyere 3 ao fi din eyin ororo kanje pelu epo ati iyo die ninu koko Aseje ao wa ogorun nera ao fikale ao se adua iye ti anbafe si owo yi ao wa so aseje sori ibikan tobati jina ao nije ki idi isasun na kanle toba tutu die ao gbeka ori ogorun nera yi ao wa je aseje na ao wa lo fi owo na se sara fun oni bara odaju
OGUN OWO TODAJU(respect)
Ewe Owo tutu ao so ogunna eyokan sinu omin ao fi ewe owo yi gba ao tunwa fi owu tutu gba legbe ao we lowu dudu ati funfun ao ma fi sapo odaju
NB owo yi wa fun lati dabobo arare lona eto ti oko bati fi se aburu odaju pupo ati omo ita ati dana dana wan aman fi owo wo e ni sugbon olewu lati lo fun iwa kiwa ijona ni yio baje ti koni sise mo
Aseje osole (awure owo)
Ewe onitikuti to lale wu (ewe timati) ao fi owo lu lemeta pelu gboloun onitikuti ti olowo olola wa bami pelu owo lowo 4times
Ao wa ja aolo pelu ata ijosi 16 ao wa lora eja aro ao gesi ona merin ao fiseje ninu koko isasun ibile lepo niyo
Aje funyin lagbara eledua Oba odumare
OGUN TI OWU ALANTAKUN BA N KO ENIYAN LARA
Oku opolo kan ao ki igi bo lati enu ti yoo wole dada ti yoo ha mon ninu dada ao wa mun ao ma fi ko gbogbo jankariwo inu ile titi afi ni leri ara opolo yen mo ti aba ti se bayen tan ao gbodo fi owo kan mon, ao fi ada ge igi yen mo ao wa fi igi gbe sinu agbada ao jo pelu odidi atare kan sugbon ako gbodo fi owo kan ti oba ti jo tan na... ao wa lo epo obo ti yio kuna daada bi atike, ao wa da mo igba yen ni a to le fowo kan.
Ogun ti akofini je nkan loju orun
Ao wa ajesi adie ao jo pelu odidi atare kan ao lo ti yio kuna dada ao fi foko mun lekanna opari
OGUN ORUKA KOBINRIN MALOYUN [ELE].
1. Ewe arilu,
2. Akoko ye eyin adie ti ko ye ri
3. Odindi atare [1]
Ao pa eyin adie ni pasan, ao lo ewe arilu yen ao koko po eyin adie yen dada ki ato pa ni pasan, ao bo atare yen leyo ao da si eyin na ao ki oruka
elelo sinu re ao ko ewe ti a lo yen si ao wa de ao re sinu ako ibepe fun ojo7, kia to ko ao ma fi sowo ba obinrin sun koni loyun tabi ki obinrin fi sowo ko ni loyun afi toba yo kuro.
O dara fun family planning.
OOGUN LATI RI OMO ODO, OMO ILE IWE, ILE KEWU
Ileke itun, ifa, abere, ogede wewe to ti pon, esinsin 9, to ba je obirin 7, a o lo gbogbo re po, a o po mose, oluware yio fi ma fo ori nikan lararo.
Ofo re): Ti ogede ba pon, nse ni esikanrin n bo, ki omodo bo mi, a o se adua s
Ogun promise and fail
Ogah gbigbe 1 efun ado, osun buke,imi ojo, ikumu ojia, ewe areyin kosun, odidi atare ao jo papo ao fi omi agbon pomo ose dudu ao kosinu fitila oloju kan ao wa te ifa ogbe fun (ogbe ofun) si ori ose na lori
NB inu fitila oloju kan lama ko ose yi si lao sese Wa te ifa yi si lori ao mafi we odaju
Promise and fail yio da gbere
EBE AWON AGBA
Eyin Adie ororo Eyele funfun kan ao jo papo ao lo kuna ao ma fi ro ekuru je opari
Ogun iferan gbogbo aye
Ao fo eyin agiriki meji sinu igba ao se adua si ao gbe agbada kana ao da omi agban si to bati ho ao da eyin yi si ao fidin lai si iyo nibe ao koje opari
"OGUN TI OKO OKUNRIN BAKERE TI YIO FI YO JADE TI YIOSI TOBI. Ao wa igbin nkan toba bonu, ao ju sinu
omi fun igba die, bi iseju mewa tabi marundogun,ao
yo igbin naa pada, ao
fi sile, tobati yo ori jade funrare, ao fi ada be ori re lekan, ao wa gun po mose dudu, ao mafi fo
gbogbo ara oko wa. oko wa yojade
ti yio si gun dada.
OSE ILE TUTU FUN OMODE....
Ewo osan wewe, eru, adin, egbo efo yanrin ao gun mo ose dudu, ao ma fi we omo na.
OGUN TI OWO ATI ESE OMO BA NWU..
Egbo tude, egbo ogano, eso pandoro. Ao gesi wewe ao ko si inu igo, ao da oti ibile odi mimu, 3 times loju mo
OGUN KI OMODE TI KO LE SORO BA LE SORO...
Ori odidere, eran owawa, ewe ela, ikoko titun, ao da ni agbo ao ma fun omode na mu,yi soro
OGUN EHIN OMODE..
ki omode le wu eyin ni irorun, rugudu ori ogede wewe ao gun mo ose ao ma fi we omo naa..
OGUN OMO TON RU TON GBE...
Adin, eeru alamo, alubosa elewe,kanfura pelebe, osan tanjarin,
Ao fi se agbo omo naa a mamu atun mafi we omo na
EYONU OWO NLA KAN LARIN OJO 9
Ao wa ori oka toni ase lenu, iyere 41 ao lo po dada tio kunna ao fi se eja aro tutu kan je, ao ge si meta, ao ni ge ja o, ao je pelu adua.
E dan wo ke fun mi labo.
Asiri Owo(Asiri bibo)
Eye lekeleke odidi kan ao fi orisi owo meji, eyokan lapa otun, ikan lapa osi e.g (1000 naira and 500naira) or 200/100
Ao gbe sinu agbada ao ko opolopo ewe aje lelori ti yio bomole ao wa fi odidi atare meta si ati oko atare meta ati eyo atare meta ao jo ao ma fi miliki olope lo lararo kato soro si eniyan odaju
Ise yi dara debi wipe taba lotan osukan si meji atun ma sise lo larawa, lekeleke ki rinrin idoti asiriwa yio bo, ise yi daju tobarise oti kuro ninu egbe otosi.
Danwo o confirm No repercursion
OGUN OSOLE
IJAPA KEKERE KAN,IGBIN KEKERE KAN,ODIDI ATARE KAN,ERAN NLA DIE,AO JOPO,AO LO DADA AO DA SI MEJE,AO FI OTI OYINBO LO FUN OJOMEJE AO RI OWO NLA,PELU OGO OLORUN OBA ALAH
ASIRI BIBO. E lo re wa isu~etiponola, ewe papasan,awom miran n pe ni dedenkude, eyin adire ororo meta,ati ori.
E o lo awon ewe yen papo ni,eo jo eyin yen sibi kan,eo da ewe yen si ti e ba ti lo tan,eo po papo daada.
Eo ju ori yen sinu agbada,ti o ba ti yo,ori yen ni eo fi din eyin yen.
Idi-ikoko yen o gbodo kanle mo oo. Ti o ba ti di ni oru,eo bo ara sile ni ihoho,eo se adura si,eo si ko je.
E o ti wa iyere-osun sile,
iyere-osun yen ni e o fi te eji-ogbe
EO WA PE IFA YI SI Ifa ni oro kan n semi bi kin ma jo, kin ma jo. Oro kan mama nse mi bi kin ma yo bi kin ma yo. Mo wo apa mi otun n o ma ri alasiri mi, mo wo apa mi osi n o ma ri alasiri mi, owo mi wa ba iyere-osun, ifa mo lo to gege ki o wa bo asiri mi, Eji-Ogbe oo wa lo re gbe eni rere ko mi, mo ni o to gege ki o je ki gbogbo eniti o ba fojukan mi ma fi owo nla-nla bo asiri mi. Lagbara Eledumare, Asiri gbogbo wa ni yio bo oooo. Ase orisa lenu mi, eyi ti mo ba wi ni irunmole yio gba, ase orisa lenu mi. Ase..!
(1) OGUN BASIRI FUN INAWO¤. Ewe abamoda, ata ijosi, ao ko sinu Isasun titun, ao fi oju Malu(eyes of a cow) mejeeji se laseje. O DAJU !!!
(2) OGUN IRIRAN. Ao be Gbaguda Oojo, ao gun ninu Odo, ao fun omi re. Ao fipo Efun ile, ao maa kan sinu oju wa mejeeji. O DAJU!!!
(3) OGUN IDANWO. Ojele ewe olosan ati glass, ao waa fi Ewe Olosan napa GLASS na loju. ao maafi glass na wo oju nigba EXAM
PA EGUN, EPE, ATI ISE RUN. A o lo wa omi-agbon to po daadaa, ao wa mu oguna to ti pon daadaa ninu ina,ao sare ju si inu omi(owo(hand) ni ao fi mu ogunna yen ninu aro),ao ju si ori-olo,ao lo,ao po mo ose dudu,omi-agbon yen ni ao fi po ose yen. Kanrinkan titun ni ao fi we ose yen ni odo to n san.
GBOLOHUN yi ni ao ma pe ti a ba ti n we ose yen:
ojo ti ina ba wo inu omi ni egun aye re tan, ki egun aye mi ko tan loni.
Owo(hand) mi ti ba omi-apegunrun lo ni, ki gbogbo egun aye mi ko tan loni,
ati egun, ati epe, ati ise(poverty) aye mi ko ma ba omi lo loni, ko je ki n gbaye se rere.
Ao ju kanrinkan yen si odo,yio ma ba omi lo.
Ebe awon agba. Eiye obe kan, ataare aja kan, ati owo eyikeyi ti o ba wu yin. Inu owo
yen ni a o ko eiye yen ati ataare yen si ti a o fi owo yen we ti a o si jo papo.
A le fi pese sita fun awon eleye..
A si le tun da sinu oti.
Gbolohun re niyi- aso aye mo fi obe be yin, aje aye mo fi obe be yin., omo awo kii ti,omo awo kiite, e ma je jin te, e wa dari aje si odo mi.
Ti a ba fe fi pa ese sita.. Ijape tinu eran ni e ma lo...e o si se adura si.
AWURE OJA TITA ATI FUN ENI TI WA ISE. Ori--Langba, Oyin die, Omi-Omu, Ewe sawerepepe, Ewe-afomo ajade, ao gun won po mo ose, ao ko sinu igba-olomori, omi-omu yen ni ao fi po ose yen oo. Ao te ose yen ni eji-ogbe, ao ma fi we. Aboru, Aboye, Abo-sise!
AJEGUN ABALAYE Owo-osi elegbede, ewe-ina pupa, ewe-esisi, odidi atare kan, etu ibon. Owo-osi elegbede yi ni ao koko jo papo mo awon ewe-ida yoku, ti o ba jo tan ti a so kale, ao wa je ko tutu, ao wa da etu-ibon yen si, ao lo po dada, ao fi sin gbere yi orun owo mejeji ka, ao po iyoku mo ose, ao ma fi fo owo.
OGUN KI A MA BA LU MAGUN Panumo, ewe seyo, ao lo papo mo oko-atare kan, ao fi sin gbere yika isale ikun wa. Baba ifankehaleluya, e ma binu, se ewe sayo le fe ko?
Ose Awure E lo re wa ewe-marugbo-sanyan ati eru, ao gun po mo ose,ao ma we nigba to ba wu wa.
LOFINDA AWURE. Erupe oju-ona ti ese n to dada, ewe-sawerepepe, ati ewe-ominsinminsin mejeji, ao lo kunna dada, ao da sinu lofinda
Lo ba tan!
OSE EYONU AWN AGBA Imi-ewure, Imi-agutan, Ewe-orijin pupo, ewe-eko ti won sonuAo gun papo mo ose, ao ko sinu igba onikoko, Ao te ni eji-ogbe, ao ma fi we.
EYONU TO DAJU.
Erupe ona oja die,Erupe ona church,Erupe ona mosque,Erupe oritameta,Ose aipo,atare aija,. Aa gun gbogbo re papo pelu omi agbon,aa ko sinu Ike fun fun olomori.
LILO; waa maa we ose naa pelu omi gbigbona(Hot water) ni Ale monday ati Thursday .
Ofo re; oju tii nsun losan, oju to nsun loru,e waa maa pe Temi lagbaja omo lagbaja nire.
Tested trusted and certain
AYAJO EYONU TO DAJU FUN OJO MONDAY. Ogundabede awo ile olokun,lo ni ki gbogbo Aiye maa fi oju ire womi loni
Afena lobirin nfena
Amomo ni eniyan moro
Tomode tagba lo mo Afin loja
A kii tori obo ka yobe
Nire nire la nsoro atare
Eniti o dami mo ati eniti ko dami mo e maa sooro mi nire loni.
Pelu atare meje lenu
EBE AWON AGBA A o lo epo-obo, a da senu ona,a po mo ose, a wa fi iyo fon inu-isasun tuntun kekere kan,ao gbe ose yen sinu re, ao wa fi odidi igbin kan bo inu ose yen. O di wiwe leyin ojo keje ti a se ose yi.
AYAJO AWEBI, AWE-OGUN IDILE
AWE-EPE etc
Efun ni baye osun je
Osun ni baye efun je
Atefun Atosun edu ni baye awon
mejeji je.
Gbogbo asasi, edi, offa, aisan, epe,
idiwo, arun, owo kowo, airi je, airi
mu tin be lara oni kaluku wa koba
je, kopa ibi da, koso dire, ki ona
owo nlala ati arisiki kio la kan mi ati
gbogbo ololufe Nairalanders!!! Ase
odumare

Osun yoba ao lo loto, efun ado ao lo loto eedu ao lo loto ose dudu ao ti fi omi de ti yio ro dada igba olomori ao bu sibi kan osun sinu igba yi ao wa bu sibi kan efun sinu igba ao bere si mape ofore si ao ropo ao tun bu sibi kan eedu si ao tun ropo ao wa mu ose tati gun toti de dada ao jusi ao ma fi owo po dada ao wa fi sile bi iseju marun ao lo epo obo die kuna ao te ifa osa meji si ao da si leyin tati se opolopo adua ao tun popo dada ao de idire kogbodo kanle man leyin taba ti setan tati gbe kuro ni ile toba jabo nibi tagbesi ao lore jusi ori atan nio ise yi daju ti ona badi ti araye nkorira re fi epo rara koto lore we kosi fi igo epo kan se sara ona yio si lesekese
ATUDE
Epo obo ao gun saka saka ao ko sinu koko ao ko ata ijosi merindinlogun si ao bu omin si ao se ti yio ho dada ao yo omire sinu omin iwe ao fi sanra taba fe sun lale ao se bi emeta lerawon ona yio si funw

1 Like

Re: Majemun Lailai by 08101646045atwp(m): 9:43am On Oct 15, 2016
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ati paapa eyin Omo June 22 to July 23 ati 2/19to3/20 haa! Afiti ori won bagbe alawore kowon nitori hmm olagbara'o ajuwase'o

Asitun nfi asikoyi sofun eyin aworo sasa todarare loju wipe anfani Ti si sile bai lati join egbe awon ojogbon Ti ape oruko'e Ni MAJEMU LAILAI on wasp.
Kajolasepe'o

3 Likes 1 Share

Re: Majemun Lailai by 08101646045atwp(m): 8:04am On Oct 30, 2016
OSE ILE TUTU FUN OMODE....
Ewo osan wewe, eru, adin, egbo efo yanrin ao gun mo ose dudu, ao ma fi we omo na.
OGUN TI OWO ATI ESE OMO BA NWU..
Egbo tude, egbo ogano, eso pandoro. Ao gesi wewe ao ko si inu igo, ao da oti ibile odi mimu, 3 times loju mo
OGUN KI OMODE TI KO LE SORO BA LE SORO...
Ori odidere, eran owawa, ewe ela, ikoko titun, ao da ni agbo ao ma fun omode na mu,yi soro
OGUN EHIN OMODE..
ki omode le wu eyin ni irorun, rugudu ori ogede wewe ao gun mo ose ao ma fi we omo naa..
OGUN OMO TON RU TON GBE...
Adin, eeru alamo, alubosa elewe,kanfura pelebe, osan tanjarin,
Ao fi se agbo omo naa a mamu atun mafi we omo na
EYONU OWO NLA KAN LARIN OJO 9
Ao wa ori oka toni ase lenu, iyere 41 ao lo po dada tio kunna ao fi se eja aro tutu kan je, ao ge si meta, ao ni ge ja o, ao je pelu adua.
E dan wo ke fun mi labo.
Asiri Owo(Asiri bibo)
Eye lekeleke odidi kan ao fi orisi owo meji, eyokan lapa otun, ikan lapa osi e.g (1000 naira and 500naira) or 200/100
Ao gbe sinu agbada ao ko opolopo ewe aje lelori ti yio bomole ao wa fi odidi atare meta si ati oko atare meta ati eyo atare meta ao jo ao ma fi miliki olope lo lararo kato soro si eniyan odaju
Ise yi dara debi wipe taba lotan osukan si meji atun ma sise lo larawa, lekeleke ki rinrin idoti asiriwa yio bo, ise yi daju tobarise oti kuro ninu egbe otosi.
Danwo o confirm No repercursion
OGUN OSOLE
IJAPA KEKERE KAN,IGBIN KEKERE KAN,ODIDI ATARE KAN,ERAN NLA DIE,AO JOPO,AO LO DADA AO DA SI MEJE,AO FI OTI OYINBO LO FUN OJOMEJE AO RI OWO NLA,PELU OGO OLORUN OBA ALAH
ASIRI BIBO. E lo re wa isu~etiponola, ewe papasan,awom miran n pe ni dedenkude, eyin adire ororo meta,ati ori.
E o lo awon ewe yen papo ni,eo jo eyin yen sibi kan,eo da ewe yen si ti e ba ti lo tan,eo po papo daada.
Eo ju ori yen sinu agbada,ti o ba ti yo,ori yen ni eo fi din eyin yen.
Idi-ikoko yen o gbodo kanle mo oo. Ti o ba ti di ni oru,eo bo ara sile ni ihoho,eo se adura si,eo si ko je.
E o ti wa iyere-osun sile,
iyere-osun yen ni e o fi te eji-ogbe
EO WA PE IFA YI SI Ifa ni oro kan n semi bi kin ma jo, kin ma jo. Oro kan mama nse mi bi kin ma yo bi kin ma yo. Mo wo apa mi otun n o ma ri alasiri mi, mo wo apa mi osi n o ma ri alasiri mi, owo mi wa ba iyere-osun, ifa mo lo to gege ki o wa bo asiri mi, Eji-Ogbe oo wa lo re gbe eni rere ko mi, mo ni o to gege ki o je ki gbogbo eniti o ba fojukan mi ma fi owo nla-nla bo asiri mi. Lagbara Eledumare, Asiri gbogbo wa ni yio bo oooo. Ase orisa lenu mi, eyi ti mo ba wi ni irunmole yio gba, ase orisa lenu mi. Ase..!
(1) OGUN BASIRI FUN INAWO¤. Ewe abamoda, ata ijosi, ao ko sinu Isasun titun, ao fi oju Malu(eyes of a cow) mejeeji se laseje. O DAJU !!!
(2) OGUN IRIRAN. Ao be Gbaguda Oojo, ao gun ninu Odo, ao fun omi re. Ao fipo Efun ile, ao maa kan sinu oju wa mejeeji. O DAJU!!!
(3) OGUN IDANWO. Ojele ewe olosan ati glass, ao waa fi Ewe Olosan napa GLASS na loju. ao maafi glass na wo oju nigba EXAM
PA EGUN, EPE, ATI ISE RUN. A o lo wa omi-agbon to po daadaa, ao wa mu oguna to ti pon daadaa ninu ina,ao sare ju si inu omi(owo(hand) ni ao fi mu ogunna yen ninu aro),ao ju si ori-olo,ao lo,ao po mo ose dudu,omi-agbon yen ni ao fi po ose yen. Kanrinkan titun ni ao fi we ose yen ni odo to n san.
GBOLOHUN yi ni ao ma pe ti a ba ti n we ose yen:
ojo ti ina ba wo inu omi ni egun aye re tan, ki egun aye mi ko tan loni.
Owo(hand) mi ti ba omi-apegunrun lo ni, ki gbogbo egun aye mi ko tan loni,
ati egun, ati epe, ati ise(poverty) aye mi ko ma ba omi lo loni, ko je ki n gbaye se rere.
Ao ju kanrinkan yen si odo,yio ma ba omi lo.
Ebe awon agba. Eiye obe kan, ataare aja kan, ati owo eyikeyi ti o ba wu yin. Inu owo
yen ni a o ko eiye yen ati ataare yen si ti a o fi owo yen we ti a o si jo papo.
A le fi pese sita fun awon eleye..
A si le tun da sinu oti.
Gbolohun re niyi- aso aye mo fi obe be yin, aje aye mo fi obe be yin., omo awo kii ti,omo awo kiite, e ma je jin te, e wa dari aje si odo mi.
Ti a ba fe fi pa ese sita.. Ijape tinu eran ni e ma lo...e o si se adura si.
AWURE OJA TITA ATI FUN ENI TI WA ISE. Ori--Langba, Oyin die, Omi-Omu, Ewe sawerepepe, Ewe-afomo ajade, ao gun won po mo ose, ao ko sinu igba-olomori, omi-omu yen ni ao fi po ose yen oo. Ao te ose yen ni eji-ogbe, ao ma fi we. Aboru, Aboye, Abo-sise!
AJEGUN ABALAYE Owo-osi elegbede, ewe-ina pupa, ewe-esisi, odidi atare kan, etu ibon. Owo-osi elegbede yi ni ao koko jo papo mo awon ewe-ida yoku, ti o ba jo tan ti a so kale, ao wa je ko tutu, ao wa da etu-ibon yen si, ao lo po dada, ao fi sin gbere yi orun owo mejeji ka, ao po iyoku mo ose, ao ma fi fo owo.
OGUN KI A MA BA LU MAGUN Panumo, ewe seyo, ao lo papo mo oko-atare kan, ao fi sin gbere yika isale ikun wa. Baba ifankehaleluya, e ma binu, se ewe sayo le fe ko?
Ose Awure E lo re wa ewe-marugbo-sanyan ati eru, ao gun po mo ose,ao ma we nigba to ba wu wa.
LOFINDA AWURE. Erupe oju-ona ti ese n to dada, ewe-sawerepepe, ati ewe-ominsinminsin mejeji, ao lo kunna dada, ao da sinu lofinda
Lo ba tan!
OSE EYONU AWN AGBA Imi-ewure, Imi-agutan, Ewe-orijin pupo, ewe-eko ti won sonuAo gun papo mo ose, ao ko sinu igba onikoko, Ao te ni eji-ogbe, ao ma fi we.
EYONU TO DAJU.
Erupe ona oja die,Erupe ona church,Erupe ona mosque,Erupe oritameta,Ose aipo,atare aija,. Aa gun gbogbo re papo pelu omi agbon,aa ko sinu Ike fun fun olomori.
LILO; waa maa we ose naa pelu omi gbigbona(Hot water) ni Ale monday ati Thursday .
Ofo re; oju tii nsun losan, oju to nsun loru,e waa maa pe Temi lagbaja omo lagbaja nire.
Tested trusted and certain
AYAJO EYONU TO DAJU FUN OJO MONDAY. Ogundabede awo ile olokun,lo ni ki gbogbo Aiye maa fi oju ire womi loni
Afena lobirin nfena
Amomo ni eniyan moro
Tomode tagba lo mo Afin loja
A kii tori obo ka yobe
Nire nire la nsoro atare
Eniti o dami mo ati eniti ko dami mo e maa sooro mi nire loni.
Pelu atare meje lenu
EBE AWON AGBA A o lo epo-obo, a da senu ona,a po mo ose, a wa fi iyo fon inu-isasun tuntun kekere kan,ao gbe ose yen sinu re, ao wa fi odidi igbin kan bo inu ose yen. O di wiwe leyin ojo keje ti a se ose yi.
AYAJO AWEBI, AWE-OGUN IDILE
AWE-EPE etc
Efun ni baye osun je
Osun ni baye efun je
Atefun Atosun edu ni baye awon
mejeji je.
Gbogbo asasi, edi, offa, aisan, epe,
idiwo, arun, owo kowo, airi je, airi
mu tin be lara oni kaluku wa koba
je, kopa ibi da, koso dire, ki ona
owo nlala ati arisiki kio la kan mi ati
gbogbo ololufe Nairalanders!!! Ase
odumare

Osun yoba ao lo loto, efun ado ao lo loto eedu ao lo loto ose dudu ao ti fi omi de ti yio ro dada igba olomori ao bu sibi kan osun sinu igba yi ao wa bu sibi kan efun sinu igba ao bere si mape ofore si ao ropo ao tun bu sibi kan eedu si ao tun ropo ao wa mu ose tati gun toti de dada ao jusi ao ma fi owo po dada ao wa fi sile bi iseju marun ao lo epo obo die kuna ao te ifa osa meji si ao da si leyin tati se opolopo adua ao tun popo dada ao de idire kogbodo kanle man leyin taba ti setan tati gbe kuro ni ile toba jabo nibi tagbesi ao lore jusi ori atan nio ise yi daju ti ona badi ti araye nkorira re fi epo rara koto lore we kosi fi igo epo kan se sara ona yio si lesekese

2 Likes 2 Shares

Re: Majemun Lailai by 08101646045atwp(m): 5:45am On Nov 01, 2016
ASINA OWO / KIWON LE OWO NLALA BERE WA. ileke itun, ileke ifa, abere, ewe anu, ewe ela. gigun pomo ose, aofi omi agbon po ose na pelu lofinda bittu. Aoma fiwe pelu ohun OHUN; Itun loni ki efi owo million tun mi se Ifa loni ki efi owo nlala fami mora Abere loni ki efi millions bere mi. Nibiti oka bakasi lonje oka nba Ki millions oto mi wa, kiwon wafi damilola.

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o
Re: Majemun Lailai by dealslip(f): 1:13pm On Nov 05, 2016
Se e ni efun ile to da ga an?
Re: Majemun Lailai by horlakunmy: 9:32am On Jul 14, 2017
Ogun owo kan niyi.......teti re ko gbomi....kosi Ogun owo kan ti apada re manda ...roowo koto she ,emioso wipe kosi Ogun owo sugbon ,ehn ehn ,oju loman to yonu ,kaka Kiowa biwashe segun tonda ile aye re laamu Ogun owo lonwa kiri ,awon egbere nsorire tiwankosi se Ogun owo,oya jowo bami bi arare lere wipe ,she Iwo kole ni oro laishepe ose Ogun owo?nkan ton damu awa omo eniyan ni wipe aoni igbagbo si oruko olohun eleda WA man ,sebi OLUWA lo sope kiafi oruko ohun here ohun to abafe , ,ohun asi dahun . OMO iya MI eje kinkoyin ni Ogun ase kan ti olohun mafin ba omo eniyan segun airina.. please don't play with ,emikii fonu rara ,danwo lobi iya okore . lowa any ewe orisi ogota ati mefa (any 66 types of leaves that u know)ao gun gbogbo ewe na tiyio ribi powder ..ao walo si odo awon alfa tiwanman han hantu wipe kiwan bawa han oruko mimo olohun towa larin bracket yi nigba 6666 ( ﺍﻟﻠﻪ ) egberun mefa ati ogorun mefa ati ogota ati mefa,6666.leyin ti wanba hanta ao funwan ni owo ti wanba fe ,ao wa sowipe kiwanbawa fo hantu yen pelu omi ofuru ojo ,ao da hantu na sinu roba funfun,ao wa bu sibi mefa ninu ewe ti atigun yen sinu hantu towa ninu roba ,larin magrib si ishai ni ao mamu hantu yi fun odidi ojo meje ni ao mafi mun hantu na ,ti iyen tumo si wipe aoni mun hantu na tan lekan soso,ojo meje laofimu ,larin magrib si ishai ni mumu re .funfun Iwo ti obani ibere kan tabi meji ,peni si ori ero ibani soro yi 07087774041 tabi 08140444773 .tabi 07039519839.
Re: Majemun Lailai by lambvard: 3:52pm On Jul 21, 2017
ok
Re: Majemun Lailai by castrol180(m): 8:57am On Jan 08, 2018
08101646045atwp:
OSE IGBEGA LENU ISE TODAJU:
Awo ekun ,ewe sawerepepe ,ewe ogede agbagba ati ewe aanu. Jijo po pelu odindin atare kan, ao po mo ose dudu tabi ose toba wun wa, ao ko sinu ike funfun ao fima we.
Ogun Asegbe
Ewe imi esu ati alubosa elewe ao gun papo ao da sinu kolobo ao da ogere epo pupa si ao mala
NB Ise yi dara pupo lona eto gege bi owo fun awan janduku wan ko nile diwa lowo toba lo lona aito koni sise kokinsepe man jemu ise nan
Eyonu odaju
Ewe imin esu epo obo ao gun papo month ose dudu ao mafi we, iseyi kere loju sugbon odara pupo
Aseje Owo togbona
Ewe imi esu eyokan tojo, ao loma iyere 3 ao fi din eyin ororo kanje pelu epo ati iyo die ninu koko Aseje ao wa ogorun nera ao fikale ao se adua iye ti anbafe si owo yi ao wa so aseje sori ibikan tobati jina ao nije ki idi isasun na kanle toba tutu die ao gbeka ori ogorun nera yi ao wa je aseje na ao wa lo fi owo na se sara fun oni bara odaju
OGUN OWO TODAJU(respect)
Ewe Owo tutu ao so ogunna eyokan sinu omin ao fi ewe owo yi gba ao tunwa fi owu tutu gba legbe ao we lowu dudu ati funfun ao ma fi sapo odaju
NB owo yi wa fun lati dabobo arare lona eto ti oko bati fi se aburu odaju pupo ati omo ita ati dana dana wan aman fi owo wo e ni sugbon olewu lati lo fun iwa kiwa ijona ni yio baje ti koni sise mo
Aseje osole (awure owo)
Ewe onitikuti to lale wu (ewe timati) ao fi owo lu lemeta pelu gboloun onitikuti ti olowo olola wa bami pelu owo lowo 4times
Ao wa ja aolo pelu ata ijosi 16 ao wa lora eja aro ao gesi ona merin ao fiseje ninu koko isasun ibile lepo niyo
Aje funyin lagbara eledua Oba odumare
OGUN TI OWU ALANTAKUN BA N KO ENIYAN LARA
Oku opolo kan ao ki igi bo lati enu ti yoo wole dada ti yoo ha mon ninu dada ao wa mun ao ma fi ko gbogbo jankariwo inu ile titi afi ni leri ara opolo yen mo ti aba ti se bayen tan ao gbodo fi owo kan mon, ao fi ada ge igi yen mo ao wa fi igi gbe sinu agbada ao jo pelu odidi atare kan sugbon ako gbodo fi owo kan ti oba ti jo tan na... ao wa lo epo obo ti yio kuna daada bi atike, ao wa da mo igba yen ni a to le fowo kan.
Ogun ti akofini je nkan loju orun
Ao wa ajesi adie ao jo pelu odidi atare kan ao lo ti yio kuna dada ao fi foko mun lekanna opari
OGUN ORUKA KOBINRIN MALOYUN [ELE].
1. Ewe arilu,
2. Akoko ye eyin adie ti ko ye ri
3. Odindi atare [1]
Ao pa eyin adie ni pasan, ao lo ewe arilu yen ao koko po eyin adie yen dada ki ato pa ni pasan, ao bo atare yen leyo ao da si eyin na ao ki oruka
elelo sinu re ao ko ewe ti a lo yen si ao wa de ao re sinu ako ibepe fun ojo7, kia to ko ao ma fi sowo ba obinrin sun koni loyun tabi ki obinrin fi sowo ko ni loyun afi toba yo kuro.
O dara fun family planning.
OOGUN LATI RI OMO ODO, OMO ILE IWE, ILE KEWU
Ileke itun, ifa, abere, ogede wewe to ti pon, esinsin 9, to ba je obirin 7, a o lo gbogbo re po, a o po mose, oluware yio fi ma fo ori nikan lararo.
Ofo re): Ti ogede ba pon, nse ni esikanrin n bo, ki omodo bo mi, a o se adua s
Ogun promise and fail
Ogah gbigbe 1 efun ado, osun buke,imi ojo, ikumu ojia, ewe areyin kosun, odidi atare ao jo papo ao fi omi agbon pomo ose dudu ao kosinu fitila oloju kan ao wa te ifa ogbe fun (ogbe ofun) si ori ose na lori
NB inu fitila oloju kan lama ko ose yi si lao sese Wa te ifa yi si lori ao mafi we odaju
Promise and fail yio da gbere
EBE AWON AGBA
Eyin Adie ororo Eyele funfun kan ao jo papo ao lo kuna ao ma fi ro ekuru je opari
Ogun iferan gbogbo aye
Ao fo eyin agiriki meji sinu igba ao se adua si ao gbe agbada kana ao da omi agban si to bati ho ao da eyin yi si ao fidin lai si iyo nibe ao koje opari
"OGUN TI OKO OKUNRIN BAKERE TI YIO FI YO JADE TI YIOSI TOBI. Ao wa igbin nkan toba bonu, ao ju sinu
omi fun igba die, bi iseju mewa tabi marundogun,ao
yo igbin naa pada, ao
fi sile, tobati yo ori jade funrare, ao fi ada be ori re lekan, ao wa gun po mose dudu, ao mafi fo
gbogbo ara oko wa. oko wa yojade
ti yio si gun dada.
OSE ILE TUTU FUN OMODE....
Ewo osan wewe, eru, adin, egbo efo yanrin ao gun mo ose dudu, ao ma fi we omo na.
OGUN TI OWO ATI ESE OMO BA NWU..
Egbo tude, egbo ogano, eso pandoro. Ao gesi wewe ao ko si inu igo, ao da oti ibile odi mimu, 3 times loju mo
OGUN KI OMODE TI KO LE SORO BA LE SORO...
Ori odidere, eran owawa, ewe ela, ikoko titun, ao da ni agbo ao ma fun omode na mu,yi soro
OGUN EHIN OMODE..
ki omode le wu eyin ni irorun, rugudu ori ogede wewe ao gun mo ose ao ma fi we omo naa..
OGUN OMO TON RU TON GBE...
Adin, eeru alamo, alubosa elewe,kanfura pelebe, osan tanjarin,
Ao fi se agbo omo naa a mamu atun mafi we omo na
EYONU OWO NLA KAN LARIN OJO 9
Ao wa ori oka toni ase lenu, iyere 41 ao lo po dada tio kunna ao fi se eja aro tutu kan je, ao ge si meta, ao ni ge ja o, ao je pelu adua.
E dan wo ke fun mi labo.
Asiri Owo(Asiri bibo)
Eye lekeleke odidi kan ao fi orisi owo meji, eyokan lapa otun, ikan lapa osi e.g (1000 naira and 500naira) or 200/100
Ao gbe sinu agbada ao ko opolopo ewe aje lelori ti yio bomole ao wa fi odidi atare meta si ati oko atare meta ati eyo atare meta ao jo ao ma fi miliki olope lo lararo kato soro si eniyan odaju
Ise yi dara debi wipe taba lotan osukan si meji atun ma sise lo larawa, lekeleke ki rinrin idoti asiriwa yio bo, ise yi daju tobarise oti kuro ninu egbe otosi.
Danwo o confirm No repercursion
OGUN OSOLE
IJAPA KEKERE KAN,IGBIN KEKERE KAN,ODIDI ATARE KAN,ERAN NLA DIE,AO JOPO,AO LO DADA AO DA SI MEJE,AO FI OTI OYINBO LO FUN OJOMEJE AO RI OWO NLA,PELU OGO OLORUN OBA ALAH
ASIRI BIBO. E lo re wa isu~etiponola, ewe papasan,awom miran n pe ni dedenkude, eyin adire ororo meta,ati ori.
E o lo awon ewe yen papo ni,eo jo eyin yen sibi kan,eo da ewe yen si ti e ba ti lo tan,eo po papo daada.
Eo ju ori yen sinu agbada,ti o ba ti yo,ori yen ni eo fi din eyin yen.
Idi-ikoko yen o gbodo kanle mo oo. Ti o ba ti di ni oru,eo bo ara sile ni ihoho,eo se adura si,eo si ko je.
E o ti wa iyere-osun sile,
iyere-osun yen ni e o fi te eji-ogbe
EO WA PE IFA YI SI Ifa ni oro kan n semi bi kin ma jo, kin ma jo. Oro kan mama nse mi bi kin ma yo bi kin ma yo. Mo wo apa mi otun n o ma ri alasiri mi, mo wo apa mi osi n o ma ri alasiri mi, owo mi wa ba iyere-osun, ifa mo lo to gege ki o wa bo asiri mi, Eji-Ogbe oo wa lo re gbe eni rere ko mi, mo ni o to gege ki o je ki gbogbo eniti o ba fojukan mi ma fi owo nla-nla bo asiri mi. Lagbara Eledumare, Asiri gbogbo wa ni yio bo oooo. Ase orisa lenu mi, eyi ti mo ba wi ni irunmole yio gba, ase orisa lenu mi. Ase..!
(1) OGUN BASIRI FUN INAWO¤. Ewe abamoda, ata ijosi, ao ko sinu Isasun titun, ao fi oju Malu(eyes of a cow) mejeeji se laseje. O DAJU !!!
(2) OGUN IRIRAN. Ao be Gbaguda Oojo, ao gun ninu Odo, ao fun omi re. Ao fipo Efun ile, ao maa kan sinu oju wa mejeeji. O DAJU!!!
(3) OGUN IDANWO. Ojele ewe olosan ati glass, ao waa fi Ewe Olosan napa GLASS na loju. ao maafi glass na wo oju nigba EXAM
PA EGUN, EPE, ATI ISE RUN. A o lo wa omi-agbon to po daadaa, ao wa mu oguna to ti pon daadaa ninu ina,ao sare ju si inu omi(owo(hand) ni ao fi mu ogunna yen ninu aro),ao ju si ori-olo,ao lo,ao po mo ose dudu,omi-agbon yen ni ao fi po ose yen. Kanrinkan titun ni ao fi we ose yen ni odo to n san.
GBOLOHUN yi ni ao ma pe ti a ba ti n we ose yen:
ojo ti ina ba wo inu omi ni egun aye re tan, ki egun aye mi ko tan loni.
Owo(hand) mi ti ba omi-apegunrun lo ni, ki gbogbo egun aye mi ko tan loni,
ati egun, ati epe, ati ise(poverty) aye mi ko ma ba omi lo loni, ko je ki n gbaye se rere.
Ao ju kanrinkan yen si odo,yio ma ba omi lo.
Ebe awon agba. Eiye obe kan, ataare aja kan, ati owo eyikeyi ti o ba wu yin. Inu owo
yen ni a o ko eiye yen ati ataare yen si ti a o fi owo yen we ti a o si jo papo.
A le fi pese sita fun awon eleye..
A si le tun da sinu oti.
Gbolohun re niyi- aso aye mo fi obe be yin, aje aye mo fi obe be yin., omo awo kii ti,omo awo kiite, e ma je jin te, e wa dari aje si odo mi.
Ti a ba fe fi pa ese sita.. Ijape tinu eran ni e ma lo...e o si se adura si.
AWURE OJA TITA ATI FUN ENI TI WA ISE. Ori--Langba, Oyin die, Omi-Omu, Ewe sawerepepe, Ewe-afomo ajade, ao gun won po mo ose, ao ko sinu igba-olomori, omi-omu yen ni ao fi po ose yen oo. Ao te ose yen ni eji-ogbe, ao ma fi we. Aboru, Aboye, Abo-sise!
AJEGUN ABALAYE Owo-osi elegbede, ewe-ina pupa, ewe-esisi, odidi atare kan, etu ibon. Owo-osi elegbede yi ni ao koko jo papo mo awon ewe-ida yoku, ti o ba jo tan ti a so kale, ao wa je ko tutu, ao wa da etu-ibon yen si, ao lo po dada, ao fi sin gbere yi orun owo mejeji ka, ao po iyoku mo ose, ao ma fi fo owo.
OGUN KI A MA BA LU MAGUN Panumo, ewe seyo, ao lo papo mo oko-atare kan, ao fi sin gbere yika isale ikun wa. Baba ifankehaleluya, e ma binu, se ewe sayo le fe ko?
Ose Awure E lo re wa ewe-marugbo-sanyan ati eru, ao gun po mo ose,ao ma we nigba to ba wu wa.
LOFINDA AWURE. Erupe oju-ona ti ese n to dada, ewe-sawerepepe, ati ewe-ominsinminsin mejeji, ao lo kunna dada, ao da sinu lofinda
Lo ba tan!
OSE EYONU AWN AGBA Imi-ewure, Imi-agutan, Ewe-orijin pupo, ewe-eko ti won sonuAo gun papo mo ose, ao ko sinu igba onikoko, Ao te ni eji-ogbe, ao ma fi we.
EYONU TO DAJU.
Erupe ona oja die,Erupe ona church,Erupe ona mosque,Erupe oritameta,Ose aipo,atare aija,. Aa gun gbogbo re papo pelu omi agbon,aa ko sinu Ike fun fun olomori.
LILO; waa maa we ose naa pelu omi gbigbona(Hot water) ni Ale monday ati Thursday .
Ofo re; oju tii nsun losan, oju to nsun loru,e waa maa pe Temi lagbaja omo lagbaja nire.
Tested trusted and certain
AYAJO EYONU TO DAJU FUN OJO MONDAY. Ogundabede awo ile olokun,lo ni ki gbogbo Aiye maa fi oju ire womi loni
Afena lobirin nfena
Amomo ni eniyan moro
Tomode tagba lo mo Afin loja
A kii tori obo ka yobe
Nire nire la nsoro atare
Eniti o dami mo ati eniti ko dami mo e maa sooro mi nire loni.
Pelu atare meje lenu
EBE AWON AGBA A o lo epo-obo, a da senu ona,a po mo ose, a wa fi iyo fon inu-isasun tuntun kekere kan,ao gbe ose yen sinu re, ao wa fi odidi igbin kan bo inu ose yen. O di wiwe leyin ojo keje ti a se ose yi.
AYAJO AWEBI, AWE-OGUN IDILE
AWE-EPE etc
Efun ni baye osun je
Osun ni baye efun je
Atefun Atosun edu ni baye awon
mejeji je.
Gbogbo asasi, edi, offa, aisan, epe,
idiwo, arun, owo kowo, airi je, airi
mu tin be lara oni kaluku wa koba
je, kopa ibi da, koso dire, ki ona
owo nlala ati arisiki kio la kan mi ati
gbogbo ololufe Nairalanders!!! Ase
odumare

Osun yoba ao lo loto, efun ado ao lo loto eedu ao lo loto ose dudu ao ti fi omi de ti yio ro dada igba olomori ao bu sibi kan osun sinu igba yi ao wa bu sibi kan efun sinu igba ao bere si mape ofore si ao ropo ao tun bu sibi kan eedu si ao tun ropo ao wa mu ose tati gun toti de dada ao jusi ao ma fi owo po dada ao wa fi sile bi iseju marun ao lo epo obo die kuna ao te ifa osa meji si ao da si leyin tati se opolopo adua ao tun popo dada ao de idire kogbodo kanle man leyin taba ti setan tati gbe kuro ni ile toba jabo nibi tagbesi ao lore jusi ori atan nio ise yi daju ti ona badi ti araye nkorira re fi epo rara koto lore we kosi fi igo epo kan se sara ona yio si lesekese
ATUDE
Epo obo ao gun saka saka ao ko sinu koko ao ko ata ijosi merindinlogun si ao bu omin si ao se ti yio ho dada ao yo omire sinu omin iwe ao fi sanra taba fe sun lale ao se bi emeta lerawon ona yio si funw

E jowo eyin baba se a le fi ero gas se aseje abi ki a fi jo ise?
Re: Majemun Lailai by 08101646045atwp(m): 12:57pm On Sep 25, 2018
eniti o bere pe ASIRI wo lobe ninu ise iranse ti o si ninu bibeli ,idahun mi re o ,ASIRI imo ijinle Olorun po lowo awon woli isaju ti won si pawon mo ti won o kowon sinu bibeli,tori komadi oun imulo fun taja teran ni,bibeli gan wipe ASIRI OLUWA wa pelu awon to beru re yio si fiwon mo majemure,Orin Dafidi 25:14, nibo ni JEHOVAH EL ADONAI, wa ninu Bibeli kideni won fi se bawo lawon woli se lo ti Olorun fi yara gbo tiwon,juti awon ti o Ku lo,Iwo na bere akara biti Elijah Ki eye Iwo gbe wa fun Iwo na,besini ASIRI yi siwa lowo awon woli mimo ti won fi irele sun mo Olorun biti Elijah, sugbon ejoreto sebi opo babalawo ti pe ara re ni woli loni ni o je kamo awon woli ododo mo,se o gbagbe pe bibeli wipe bi ogbon ba Ku fun enikeni Ki o bere lowo Olorun ni,ASIRI Olorun po,ti enikeni o mo o,sugbon ti Olorun si fi han awon woli re,tori agbara igbohun Irina imoaya,ala,ati bebelo siwa sibe ti Olorun fi fi asiri ohun ijinle han awon woli re o.Jesus is Lord. Hallelujah
Re: Majemun Lailai by omomajemuorun: 11:50pm On Nov 20, 2019
Baba ejo nje e le ba wa salaye koleyewa Dada Lori eto ise OGUN OWO (respect)
Ewe Owo tutu ao so ogunna eyokan sinu omin ao fi ewe owo yi gba ao tunwa fi owu tutu gba legbe

Atipe bi e se ko awon oro wonyin ni ede Yoruba ko ye wa dada
Baba ti e ba mind e le send e si email (omomajemuorun@gmail.com )
Eseun baba o
Ewe a ma he o
E pe fun was o.

(1) (Reply)

I Have Man Boobs (Gynecomastia). Please I Need Help / Corper Runs Mad At An Eatery In Lagos - Pictures / Lady Raises Alarm After Failed Nose Surgery In Lagos (pic/video)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 132
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.