Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,132 members, 7,814,956 topics. Date: Thursday, 02 May 2024 at 01:45 AM

Sola Allyson- Ayanmo Ife Lyrics - Music/Radio - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Music/Radio / Sola Allyson- Ayanmo Ife Lyrics (9857 Views)

Shola Allyson Ft Adekunle Gold - Alujanjankijan (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Sola Allyson- Ayanmo Ife Lyrics by ayoolagr8ness(f): 5:54am On Aug 10, 2016
Shola allyson - Ayanmo Ife

Ololufe woju mi
So fun mi pe o fe mi
Ayanmo ife laje fun ra wa
Lat'odo Eni to da wa

Ofi imole re fun mi
Ofi agbara mi fun o
Ofi idanu sinu wa
Lati mo'fe lati mo're

Owo mi re fami dani
Ase oluwa ni
Ayanmo ife laje fun ra wa
Lat'odo eni to da wa

Ayo wa ti dajo se
Ola wa ti dajo ni
Irin wa to dajo rin
Ibanuje koji na si wa

Womi otun mi wo
Pelu oju inu
Irin wa laye jo ra won ^2
Ayanmo wa jo ayanmo
Loro ife wa se se regi

Owo mi re fami da ni
Ase oluwa ni
Ayanmo ife laje fun ra wa
Lat'odo eni to da wa

Kole se kija ma wa
Jowo jajo so asoye
Boro ba se bi oro
Jowo fi suru bamise

Ore kan mi pemi o o bi mi
Ogiri wa koma laanu^2
Bi a bafi imo wa sokan
Oke oke la o ma lo^2

Owo mi re o fa mi dani...

Ololufe woju mi...

Bafefe idanwo ba fe de
Durotimi girigiri
Botiwu ko run mo to,
Sanmo dudu a wa dandan ni
Iwenumo ma lo je
Ka tu le ri anu gba si ni
Isoro ni adun ola ni adun ola ni
Ayo ati ope lo ma jasi

Owo mi re fami dani ....

Chorus.

2 Likes 1 Share

Re: Sola Allyson- Ayanmo Ife Lyrics by xedyl(m): 6:39am On Aug 10, 2016
I Jux like her voice

(1) (Reply)

'Expressions': Styl-plus New Album / Complete Lil Frosh Biography, Net Worth And Age 2020 / The Life Of Pablo

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.