Welcome, Guest: Join Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 2,796,484 members, 6,680,839 topics. Date: Tuesday, 18 January 2022 at 02:55 PM

Ebe Awon Agba Ti Eniyan Mafi Nri Aye Se Ni Irorun Lori Oun Gbogbo Taba Fe See - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ebe Awon Agba Ti Eniyan Mafi Nri Aye Se Ni Irorun Lori Oun Gbogbo Taba Fe See (11083 Views)

Ogun Ti Afi Ngbe Aye Ni Irorun Ati Ogun Korikosun To Gbona Gan / Ti Eniyan Ba Nse Ogun Ti Kii Sise Fun / Perfection For Stroke :-ogun Ti Eniyan Kii Fi Ni Ropa- Rose (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Ebe Awon Agba Ti Eniyan Mafi Nri Aye Se Ni Irorun Lori Oun Gbogbo Taba Fe See by Laniretiawoagba: 1:52pm On Mar 02, 2018
odidi okete tutu kan ao lani aya, ao ko epo obo ati imi ojo sinu ree, pelu odidi atare kan, ao ran pada ao gbe sinu isasun tuntun olomori kan ao Jo poo , ao lo kunna ao wa fite ifa owonrin mekun sinu isasun naa ao pe gbolohun ree sii, ao da ogere epo pupa lelori, nibe lao tima bu fun enikeni laa, (ofo ree) ORUNMILA jini kutu kutu o ronu ogba ojude awon eleye loo, oda ifa owonrin mekun, awon iyami osoronga ni Iwo talo n difa owonrin mekun ni beun, oni oun olajogun , ijeremogun nii, woni kilo rii tofi NDA ifa owonrin mekun, oni tori alaboyun ori ikunle to nro bii lowo tiko me bimo nii, ati nitori awon agan tiwon koti owo alabosun, nitori okunrun idubule to nse aisan lowo tiko me dide, ati nitori awon alaseri to nsise tiwon kori oiutu ree tiwon kosi ni owo lowo, awon iyami wa nbinu woni awon to kaa sile wonyi ounje waa nii,ORUNMILA ni mo Mon pe ounje yin ni won, sugbon mowa lati wa see isipe won nii, woni awon koni GBA ki ORUNMILA o see isipe naa lailai, oniti eyin koba gba isipe mii, emi too pitan funyin woni ki omura ko pitan naa, olupowo loruko ti yeye eyin aje n jee, eyin larin ihoho woja, a lakaka he idin, woni ki oda itan naa duro ko toro ohun toba n fee, ao si yonda enina ninu aye pata pata, OGUN yii sise pupo,ti aba ri ounkoun tafe bere Lori Ogun tabi agbara, e pemi 08037492173 tabi WhatsApp

(1) (Reply)

How Often Do You Mix English With Your Native Language While Talking? / List Of American Instruments Of African Origin That Survived The TST. / Wait!! Before You Marry That Your Igbo Girlfriend, You Have To Read This!!

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2022 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 28
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.