Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,222,391 members, 8,051,947 topics. Date: Monday, 13 January 2025 at 08:25 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ogun Ti Okunrin Tabi Obinrin Koba Lori Oko Tabi Aya (9494 Views)
Osole Gbewa 15 Million Tabi 9million. / Ogun Ti Afi Ngbe Aye Ni Irorun Ati Ogun Korikosun To Gbona Gan / Ogun Ti Akoba Fe Ki Okunrin Tabi Obinrin Loju Miran Leyin Eni (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Ogun Ti Okunrin Tabi Obinrin Koba Lori Oko Tabi Aya by Laniretiawoagba: 10:17pm On Jun 06, 2018 |
ewe jinwini, eesan ekuro, ewe awoyoyo, roro orun agbo, irun ori oruko, ori akuko adiye fun obinrin, ori about adiye fun okunrin ki aripe adiye naa ko dagba juu, ao Jo papo, ao pomo (ofo ree) itu ko lowo tinfi soko ewure jinwini won ko sai femi bee jinwini, agbo ko lowo tinfi soko aguntan kan bolojo jinwini won ko sai femi bee jinwini, akuko adiye KO lowo tinfi soko agbebo kan bolojo jinwini won ko sai femi bee jinwini, bi nlaso bi nlewu jinwini ko sai femi bee jinwini, ki gbogbo obinrin tabi okunrin ma femi bee jinwini, ki afee eyi toba wuwa nibee, ti aba ni ibeere ki e pemi sori 08037492173 edumare too GBA funwa |
(1) (Reply)
I Would Like To Know Some About Igbo Traditions / Where Are My Hausa Speaking Nairalanders? Please Come In Let's Have A Talk. / Shehu Of Dikwa, Mohammed El-Kanemi Dies At 79
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2025 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7 |