Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,142 members, 7,815,001 topics. Date: Thursday, 02 May 2024 at 04:21 AM

Ifaa Olaa - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ifaa Olaa (1185 Views)

Ogun Ti Afi Nse Olaa (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Ifaa Olaa by Laniretiawoagba: 5:57am On Jun 24, 2018
fun a won eniyan wa ti nse aroye wipe a won ko lowo lowo, ejeki a Dan IFA kekere yii woo, eyele funfun kan,awo ekun, iyere, iruworo, ao lo papo ao wa ko sinu isasun asejee tuntun ao pa eyele naa ao gesi mesan fun okunrin, meje fun obinrin, ao wa kole toba fe jinna tan, ao walo awo ekun Miran loto,ao fi tefa eji ogbe ao pe ofo ree sii, olorarudu 3x, yawara 3x, orunmila no tani npe iyami loruko moni emi ---omo --- ni mo npe iyare loruko, 3x, oni enikan kimo oruko iyami ki oju owo o pon oluware Mon lailai3x, IFA onifa too somi di aridigi loju omo araye, nitori oku ekun owo nii aye ekun owo nii, aridigi niti ekun, gbogbo ara ekun owo nii, orunmila owo tofunmi Lana di ipamo

(1) (Reply)

Nigerian Village Where Men And Women Speak Different Languages / SLAVERY | Africa Needs To Apologize. / The Ilaje People Of Ondo State

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 8
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.