Stats: 3,165,881 members, 7,862,991 topics. Date: Monday, 17 June 2024 at 10:15 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (377844 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (27) (28) (29) (30) (31) (32) (33) ... (167) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 4:49pm On Jun 01, 2007 |
@segoye mo n gbadun story e oh! jowo pada ko wa fun wa ni more details oh! ![]() sugbon oh! awon wo ni aboki ![]() ![]() ![]() ![]() @muki ki lon sele? ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 5:56pm On Jun 01, 2007 |
ogbeni segeoye ori gidi le so yen jare, oye kia ma ran ra wa lowo nibi kibi ti a ba ti ri ara wa gege bii omo naija gbogbo. omo aboki ni eyin tun tasi nisiyin? oro yen ti fe di long distance oh, sugbon ti owo ba ti wa, e si mama ri ara yin leekan tabi leemeji losu. Olorun wa ma fun yi se. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 5:58pm On Jun 01, 2007 |
Good afternoon y'all Bawo ni? Se alafia ni gbogbo yin wa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Dapo4u(m): 6:55pm On Jun 01, 2007 |
E ku ile laa ki ara iwaju, e kaa bo laa ki ero eyin.Mo se iba fun olorun oba ti o ni ojo eni.E ku ile ooo, ta lo wa lago? tani ogboju babalawo ti yi o kan omo aje niko?Hiyaaa,gbe ra nile,omo elegun. ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Dapo4u(m): 6:56pm On Jun 01, 2007 |
E ku ile laa ki ara iwaju, e kaa bo laa ki ero eyin.Mo se iba fun olorun oba ti o ni ojo eni.E ku ile ooo, ta lo wa lago? tani ogboju babalawo ti yi o kan omo aje niko?Hiyaaa,gbe ra nile,omo elegun. ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 7:32pm On Jun 01, 2007 |
Dapo4u:Damn! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Dapo4u(m): 7:37pm On Jun 01, 2007 |
i]Eyin omo Ibadan[/i], ki ni so re? so suo ni (so = show, suo = sure ) ki le je lana? eran sinkin ni ( sinkin= chicken) ki le fi joko? kusin sia ni. (kusin sia = cushion chair) ki ni time? sefun sap ni (sefun =seven, sap =sharp? ![]() ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Dapo4u(m): 7:40pm On Jun 01, 2007 |
nana, jeje mi lomo eko mi n lo o. ki ni itumo damn? da kun ba mi se ogbufo re si ede abinibi mi. ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:40pm On Jun 01, 2007 |
Mo beri fun awon ti mo ba loju opon ooo Kilo nsele?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:41pm On Jun 01, 2007 |
ma da loun, ko ri nkan to ko ka ni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:42pm On Jun 01, 2007 |
@Nana oo ti e kiwa kaabo, Kilode now? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Dapo4u(m): 7:43pm On Jun 01, 2007 |
abi o,o wa gba mi Mishoo. Ki la gbe ki le ju? jeje mi le mi sin mo n lo o. ha wu! ba wo ni ja re ore mi. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:48pm On Jun 01, 2007 |
mo wapa. amon mo ti sun kuro nibi ti e fimi si oo. mo te siwaju ! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:49pm On Jun 01, 2007 |
sugbon @Dapo4u, o da bi eni pe igba ti ariya pari tan ni a wo oju agbo ooo?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 7:53pm On Jun 01, 2007 |
ariya titun ma bere laipe, olootu Dapo, ijinle yoruba ni eyin moo so o! awa si wa ni ile iwe lati ko aayan ogbufo gidi. ti e ba laye boya e le ko mi die die. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Dapo4u(m): 8:01pm On Jun 01, 2007 |
Mishoo Igba n ba jo lo nilu gbe ilu lo.Alejo to fi oru wolu,ki ni yio je Mishoo? idodo oro ni. ![]() Debosky, O da bi eni wipe eyin ko ti se alabapade okunrin kan ti oruko re n je Richlaw? ni ori foorum(forum),Baale abule yoruba thread ni yen ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:04pm On Jun 01, 2007 |
otito ni oo. Richylaw ni kiniun ninu eranko yoruba ni ori okun (thread) yi. Amon o to ojo mate oo. nibo ni owa?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 8:05pm On Jun 01, 2007 |
emi o ti se alabapade ogbeni Richlaw ti en so yii. se oro enu tie tu ju teyin lo ni?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:06pm On Jun 01, 2007 |
@Debosky kaabo. mo man gbadun e gan ni. agaga nigba ti iwo ati Segoye n ta si ara yin ni oju iwe melo seyin.Se ara re le? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ThiefOfHearts(f): 8:14pm On Jun 01, 2007 |
o jeki debo ati mishoo shey igbeyawo ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:15pm On Jun 01, 2007 |
Haba, okunrin ati okunrin ![]() ![]() ![]() ![]() ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 8:17pm On Jun 01, 2007 |
olorun maje, awon omo ale ati oloriburuku nikan ni won man se iru nkan yen. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:17pm On Jun 01, 2007 |
iwo o se ma kiss obinrin ninu aworan ee.kilode ti o fi fi aworan obinrin to n fi enu ko kunrin lenu sibe?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kitaun(m): 8:26pm On Jun 01, 2007 |
IBI YI LEYIN T'EMI WA ABI? ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Dapo4u(m): 8:28pm On Jun 01, 2007 |
Eewo! okunrin si okunrin? Ni ile Oodua,omo ti ekun ba bi,ekun ni yoo jo.E dakun e ma ma gbe asa okere de ibi o. ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 8:33pm On Jun 01, 2007 |
![]() ![]() ![]() ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:35pm On Jun 01, 2007 |
omidan ikameka, o si wa ni adugbo yi ni?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 8:44pm On Jun 01, 2007 |
se lagege? abi shomolu? ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:47pm On Jun 01, 2007 |
ikamefa:AJ city ni. LOL |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Dapo4u(m): 8:49pm On Jun 01, 2007 |
se lagege? abi shomolu isale eko? Agarawu? Oyingbo? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:52pm On Jun 01, 2007 |
@thiefofhearts ye da na? o so isokuso tan o ya ba ese re soro ![]() ![]() e so fun pe ti nba gbamu, - - - - - - - |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:57pm On Jun 01, 2007 |
emi nlo ile nitemi oo. O di gigba kanna. ooko kan la o ji oo!! Kasun layo, kaji layo oo. |
(1) (2) (3) ... (27) (28) (29) (30) (31) (32) (33) ... (167)
Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 30 |