Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,613 members, 7,851,086 topics. Date: Wednesday, 05 June 2024 at 01:14 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (100) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (377436 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (97) (98) (99) (100) (101) (102) (103) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by aloib(f): 2:04pm On Aug 13, 2007
en le o, e joko, kile fe jeun
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ellab(f): 4:18pm On Aug 13, 2007
@aloib,mo fe je iyan ati eforiro. grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 4:33pm On Aug 13, 2007
Se o le se egusi ati isapa pelu eran ogufe??
Ki o si se sinu igba dudu ni oo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 4:41pm On Aug 13, 2007
lol.igbadudu bi ti bawo?

kishe ebo now,so why igbadudu?

anyway.
enle nbi loni,eku boju ojo tiri o.
eede odun bi?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 4:48pm On Aug 13, 2007
Ayaba Iseju, Ebo bawo?? Mi ki i se alujannu oo tabi ebora !!!

Sugbon awon igba ti a fi amo se yen ti a si fi ina jo leyin lati je ki o gbe ni mo n soro nipa.
Se eyin mo ounje se ni?? Ounje abinibi ni oo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 5:07pm On Aug 13, 2007
oye mi wayii.
enikan sofunmi pe awon isaasun obe yen maa nmobe dun,she otito ni?

kin ma mo se kodoran.


lol.mo monje se daadaa.

she ekuru ati atadindin ni? abi amala ati abula lefe soni,ewa igan naa ogbeyin,eba felefele ati ila elegusi pelu eja tutu
nko? moinmoin naa wanbe.

yes- won ko mi mode gba eko.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tdino(f): 5:09pm On Aug 13, 2007
i guess i cant speak yoruba.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:21pm On Aug 13, 2007
minute:

she ekuru ati atadindin ni? abi amala ati abula lefe soni,ewa igan naa ogbeyin,eba felefele ati ila elegusi pelu eja tutu
nko? moinmoin naa wanbe.


Yeeee !! Otito ooo!! Ni se ni enu mi da to !!
Koda oro re mu ebi pami.
Sugbon nko feran ekuru ti ko ba ni ile ninu oo, nitori o man pa mi lorun.
Se o le ju awon ounje wonyi lati inu afefe ??
Ki n wa gba sori ero ibanisoro mi ??

tdino:

i guess i can't speak yoruba.
Talo pe e wa ni gba na ??
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 5:28pm On Aug 13, 2007
ma laagun jinaa.lol.

mole ko yin biwon shen  se.ti eba mind.

mogbadun ekuru gaan---infact the brownish one yeen mo le fishe ounje ojo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:39pm On Aug 13, 2007
TI IYA MI BA SE EKURU NI IGBA TI MO WA LEWE. EMI KII FE KI WON BA MI FO RARA. MO MAN FE KI WON BA MI BU OBE SI I DIPO KI WON FO.

WELL SHA, TI E BA SETAN ATU KO MI. INU MI YIO DUN GAN.

SE E MA N FI EKO JE E NI??

YUCK !! MO KORIRA EKO (MIMU ATI JIJE) SUGBON TO WON BA FO EKO JIJE SINU ABO IDEMU TI WON SI FI SUGAR ATI MILO SI, MO LE MU.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 5:49pm On Aug 13, 2007
richy and others, E ka re ooo  cheesy

ti obirin (okurin) o ba she enu, alangba o le wo be lo
grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 5:56pm On Aug 13, 2007
any time ure ready

ati  eko mimu ati jije--anything goes.

omo iya agba ni mi---eyikeyi to ba gbe simi niwa ju naa ni-mio mind.

but eko lodun je ekuru even tho ope die timo fenukan.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DisGuy: 6:24pm On Aug 13, 2007
oga richylaw eku ijo meta, shey dada ni shey hen gburo ile, dada ni amakpade o

odaron dblock awon hommies hen ko shey e ko fa ijogbon grin

eyin ara she gbogbo hen lo? ki e tey ikpa ma shey, ki ojo iwaju ley dara cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 6:30pm On Aug 13, 2007
Dis Guy, o n gbiyanju, sugbon ko si 'ikpa' ninu yoruba oo. Konsonanti ma n wa legbe Faweli ni. Konsonanti meji kii si ni egbe ara won afi bii 'gb' ati 'ng' nikan.
E mura si kiko yoruba yin oo.
O dara be e !!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DisGuy: 6:37pm On Aug 13, 2007
say what?

shey e man e kpe yoruba ko kin shey ikana mole ma so yoruba awon ara oke abi awon ara isele abi yoruba hausa gam sef so mo wa allowed lati modernise e, esp bi mo shey ma bi mo ma shey type awon proper yoruba alphabet ti wa ni igi lori ati l'abe wink

ikpa= akpa=apa= ki e t'apa ma ese cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 6:40pm On Aug 13, 2007
Sugbon Yoruba kiko ko ni agbagbe rara oo. Ko si 'sh' nibe. Kakabe o maa dara to ba ko 's' ati 'pa' dipo 'kpa' . Se ara Benin ni e ni abi igbo to ti pe ni ile yoruba !!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 6:45pm On Aug 13, 2007
infact mio le ka nkan to type yeen

odaabo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DisGuy: 6:46pm On Aug 13, 2007
ara fulani ni me grin

awon teacher won ko wa ni yoruba ni ile ewe, mole so mosi gbo; mikole ko yoruba dada
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:27pm On Aug 13, 2007
o tie n gbiyanju. Mura sii ni sise !!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by aloib(f): 7:30pm On Aug 13, 2007
ewo sisi yen ton se sepe sepe figure 8
orombo aya re o dun ju osan lo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DisGuy: 7:33pm On Aug 13, 2007
aloib, bo si oju agbo ka jo, moni dollars ti mo fe spray e wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by seunniji(m): 9:41pm On Aug 13, 2007
kilo se ti o re baje, woooo ko isi ki eniyan ko yoruba sile oooo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 10:21am On Aug 14, 2007
Ejiire bii?

Se alafia ni gbogbo yin wa o.

Eku ojo meta o, asi ku bi oju ojo se ri.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 2:06pm On Aug 14, 2007
E ku ikale o gbogbo eniyan, se mo ba gbogbo yin da.

minute :

richy and others, E ka re ooo

ti obirin (okurin) o ba she enu, alangba o le wo be lo


O dami loju wipe ohun ti o fe so ni yi, ' bi ogiri (monolithic wall) o ba la enu, alangba o le wobe.' Emi ko ri idi ti obinrin tabi okunrin yio se la enu fun alangba o grin. Minute ohun ti o ba je ki o mo ekuru pelu atadindin ati ila, ila elegusi , ikoko isaasun ati bebelo, o ti fihan gbangbangba wipe ile ti o mo iyi asa ounje ile youruba ni o ti wa, ogidi omo kaaro ojiire ni o. Koda bi o ti se n pe ede jade lenu lowolowo yii n je ki n se iye meji [[s]sup]e be like say u dey hide face before [/sup] [/s] Ju gbogbo re lo, e ku akitiyan

Dis guy mo n je o bi o se n ki mi o.
Mishoo, o ye ki o ti ri wipe ara Egun ni eni ti o n ba soro now, eyi ti o fi n ko ni yoruba , ko orin ilu won fun:
Eto jowe /x2
Ji le fonto
fe ne jato
Isokiriso
isokiriso
isokiri so so so grin
Desorlah aya Segoye eku itoju oko yin o, a n reti Oloye Segoye pada ninu ilu laipe
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 2:47pm On Aug 14, 2007
rombo rombo state ala kara gbe wa
rombo rombo state, rombo rombo state ala kara gbe wa oooo

wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 4:15pm On Aug 14, 2007
omoge:

rombo rombo state ala kara gbe wa
rombo rombo state, rombo rombo state ala kara gbe wa oooo

wink
Se alakara de ti gbe de? Nitori mo ri wipe orin yen wo e lara gan ni o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 5:35pm On Aug 14, 2007
se daada ni oode yi wa
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 5:37pm On Aug 14, 2007
richy law, bawo ni irin ajoo yin ?
se gbogbo nkan lo ni melomelo
e ku asiko yi o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 6:12pm On Aug 14, 2007
rara kosi akara o

whistling rombo rombo state alakara gbe wa, rombo rombo state, rombo rombo state alakara gbe wa ooooo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tdino(f): 6:17pm On Aug 14, 2007
wetin dey
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tdino(f): 6:18pm On Aug 14, 2007
wetin dey omoge.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 8:04pm On Aug 14, 2007
baale, e ku ojo meta o. kilode ti e jina si wa? a wa yin dele a ko ri yin. se ara le koko bi ota?
mo mo wipe agbo to fi eyin rin agbara lo lo mu wa.

(1) (2) (3) ... (97) (98) (99) (100) (101) (102) (103) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 37
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.