Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,165,828 members, 7,862,727 topics. Date: Monday, 17 June 2024 at 02:39 AM

Tani Jesu Nse? - Jesu Li Oba Israel - Religion - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Tani Jesu Nse? - Jesu Li Oba Israel (682 Views)

Tani Jesu Nse? - Jesu Ni Olorun / Tani Jesu Nse - Jesu Ni Eni Ti A Fi Ami Ororo Yan / Who Is Jesus? - Tani Jesu Nse? (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Tani Jesu Nse? - Jesu Li Oba Israel by Primate7: 10:44pm On Apr 10, 2019
TANI JESU NSE?
JESU LI OBA ISRAEL
IHINRERE TI JOHANNU ORI KINNI, ESE KETADINLADOTA TITI DE IKANKANLELADOTA SO WIPE:
47. Jesu ri Natanaeli mbo wa sodo re, o si wi nipa re pe, Wo o, omo Israeli nitoto, ninu eniti etan ko si!
48. Natanaeli wi fun u pe, Nibo ni iwo ti mo mi? Jesu dahun, o si wi fun n pe, Ki Filippi to pe o, nigbati iwo wa labe igi opoto, mo ti ri o.
49. Natanaeli dahun, o si wi fun u pe, Rabbi, iwo li Omo Olorun, iwo li Oba Israeli.
50. Jesu dahun, o si wi fun u pe, Nitori mo wi fun o pe, mo ri o labe igi opoto ni iwo se gbagbo? iwo o ri ohun ti o poju wonyi lo.
51. O si wi fun u pe, Loto, loto ni mo wi fun nyin, Enyin o ri orun si sile, awon angeli Olorun yio si ma goke, nwon o si ma sokale sori Omo-enia.
LATI INU BIBELI MIMO
10/04/2019

(1) (Reply)

Questions For Those Who Don’t Have Religion But Believe In God / Advantages Of Being An Atheist / Protest Against Fatoyinbo Enters Second Day, COZA Begins Seven-day Fast

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.