Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,151,854 members, 7,813,909 topics. Date: Tuesday, 30 April 2024 at 09:16 PM

Afose Ati Olugbohun Todaju - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Afose Ati Olugbohun Todaju (7845 Views)

Ogun Eyonu Awon Agba Todaju / Ogun Ti Afi Ngbe Aye Ni Irorun Ati Ogun Korikosun To Gbona Gan / Osole Owo Todaju (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Afose Ati Olugbohun Todaju by ogunfrayo: 2:50am On Jan 26, 2021
Yoruba ni wa, eledumare si se eda awon nkan agbara fun wa lopolopo ara e ni: ofe, aluwo, isuju, ayeta, akaaba, agadagodo, epe tabi afose, olugbohun. Orisirisi agbara ni eledua fi jinki wa gegebe eniyan dudu, sugbon olaju ati esin (religion) ni ko jeki opolopo kobi ara si awon nkan wonyi. Awon nkan Miran wa ti awon babanla wa igbani fin se isora ati kikoyo ninu ewu eyikeyi. Oseni laanu wipe opo ni o mo wipe ogun sise tabi ewe ati egbo kodi esin lowo rara. Fun apeere, awon baba wa ni Igba aiye won, won ma nlo olugbohun tabi epe todaju nigba ti ogun tabi ipenija bapoju. Oyinbo ti e tiwa so aye dero yato si Igba ti oju dudu. Ti aba Fe gba ise, tabi gbadura tabi pa ase lori oun ti afe kotete tewalowo, a le lo olugbohun tabi afose lati gbadura fun Ohun ti abafe ti yio si ri bee lesekese. Opolopo asiri wonyi ni opolopo pastor tabi woli nlo lode oni fun agbara ti Kosi han si elomiran ju ara won lo. Abalajo ti Ori oke se po jantirere ti onikaluku si so ori oke won ni Orisirisi Oruko. Anikeni ti oba nilo Afose todaju tabi olugbohun gidi, e le kan simi lori whatsapp number mi(08108458712). Mole ko yin tabi kin bayin se ti e lo ma lo. Sugbon ama bura pelu ogun wipe e ko ni fi se ika tabi ba ti elomiran je, ati Owo sise re. Eseun lopolopo

(1) (Reply)

What Is It With The Yorubas And Their Language? / Should We Continue Paying Bride Price? / Distasteful Dressing By Ghanaian Women In Public (PHOTO)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 9
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.