Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,194,203 members, 7,953,749 topics. Date: Friday, 20 September 2024 at 03:08 AM

Iskilu Wakili Jiyàn Ọ̀rọ̀, Ó Ní Òun Kò Mọ Ohunkohun Nípa Ìṣekúpani Ibarapa - Politics - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Iskilu Wakili Jiyàn Ọ̀rọ̀, Ó Ní Òun Kò Mọ Ohunkohun Nípa Ìṣekúpani Ibarapa (322 Views)

OPC Captures, Arrests Iskilu Wakili And His Fulani Squad (Video) / Sọ̀rọ̀ Sókè, 10 Other Popular Trends Nigerians Used To “catch Cruise" In 2020 / Kayode Alabi Reads ‘ó tó gé’ from Bible at church service (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Iskilu Wakili Jiyàn Ọ̀rọ̀, Ó Ní Òun Kò Mọ Ohunkohun Nípa Ìṣekúpani Ibarapa by Habsonflow(m): 2:19pm On Mar 09, 2021
L'ọjọ Aje ni Isikilu Wakili, ẹni ti wọn fi ẹsun kan lori i ijinigbe to n waye ni ilu Ayetẹ n'ijọba ibilẹ Ariwa Ibarapa ipinlẹ Ọyọ ṣe alaye ohun ti oju ẹ ri lasiko ti awọn ọmọ ẹgbẹ Oodua Peoples Congress, OPC yawọ ibi ti o sọ pe oun dubulẹ aisan si.

Wakili ṣe alaye fun awọn oniroyin niluu Ibadan wi pe oun ṣaisan, bẹẹ sini oun lọ gba itọju ni ilu kan ti wọn pe ni Iparaku.
Baba arugbo naa ṣe alaye wi pe ara oun ko mokun lasiko ti awọn ọmọ ẹgbẹ naa de si ibugbe oun pẹlu alaye wi pe awọn obinrin kan to wa pẹlu oun lasiko naa lo ta oun ni olobo.

O ni, "Ara mi ko ya nitori mo ṣẹṣẹ ti ilu Benin republic de ni. Ibi ti mo dubulẹ si ninu ahere mi ni mo ti gbọ ariwo wi pe awọn Amọtẹkun n dira ogun bọ, ṣugbọn mi o le sare nitori ilẹra mi.

Eyii lo mu ki n sọ fun awọn eeyan to n bẹ layika mi lati sa asala fun ẹmi wọn. Wọn mu mi, wọn si wọ mi lọ si agọ ọlọpaa ni Igboọra ki wọn to gbe mi wa si Ibadan."
Kaa si waju si: https://www.bbc.com/yoruba/56330339
Re: Iskilu Wakili Jiyàn Ọ̀rọ̀, Ó Ní Òun Kò Mọ Ohunkohun Nípa Ìṣekúpani Ibarapa by Mayng01(m): 2:28pm On Mar 09, 2021
I knew he would deny it
Re: Iskilu Wakili Jiyàn Ọ̀rọ̀, Ó Ní Òun Kò Mọ Ohunkohun Nípa Ìṣekúpani Ibarapa by shiffynaani(m): 7:02pm On Mar 09, 2021
Thanks for this piece.

I love it served hot in Yoruba
Re: Iskilu Wakili Jiyàn Ọ̀rọ̀, Ó Ní Òun Kò Mọ Ohunkohun Nípa Ìṣekúpani Ibarapa by Mightyhaiz: 7:36pm On Mar 09, 2021
its well

(1) (Reply)

Education Of Women Is Existential Issue’ – VP Osinbajo / COVID-19: Poor Turnout At Designated Centers As Kano Residents Resist Astra Zene / Governor Abdulrahman Appoints 24-year -old #endsars Panelist As Commissioner

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.