Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,016 members, 7,817,999 topics. Date: Sunday, 05 May 2024 at 03:05 AM

Ohun Taa Pee Nii Asirii Ogun Ado Oso Owo - Health - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Ohun Taa Pee Nii Asirii Ogun Ado Oso Owo (566 Views)

Asirii Tii AA Fii 50k Pere / Ise Osole Awon Babami Ayee Igba Nii Tii Won Fii Jehun / What Your Gee-pee Tank Looks Like After Six Months And After Washing (photos) (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Ohun Taa Pee Nii Asirii Ogun Ado Oso Owo by bullet001: 10:55pm On Apr 21, 2021
ADO OSO OWO NLA TI AFIN DI OLOWO OLORO BOROKINI KAKIRI GBOGBO AGBALAYE
ISE YI DAMILOJU BI IKU
ISE TI MO TI SE FUN ENIA PUPO NI, TI WON SIDI OLOWO OLORO , KOSI NI IPALARA KANKAN
ao wa odidi eiye igun ooye kan
eiye alapandede kan
eiye kowe kan
eiyele funfun balau kan
iye agbe meji
iye aluko meji
iru ti koni iyo pupo
ewe sefunsefun tutu
owo #1000 tuntun kan
ado kinkini kan
....... SISE,RE ,,,,, ao pa eye igun yi, ao fi eje re ra idi ikoko ti ao fi jo ogun yi ao gbe ikoko yi sori aro idi ikoko yi kogbodo kanle rarao ao wa gbe igun yi sinu ikoko ao ko awon eiye yi sinu ikoko ati sibi yi ati ewe yi ao fi iru ti koni iyo pupo bomole ao jopo ao lo kuna dada ao wa ro ebu yi sinu ado kinkini yi ao fi owu akese di enu ado yi pa ao wa eiyele funfun miran kan ao gba eje re sinu ife kan ao tu omi odidi agbon kan si ao pomo dada ao bu die ninu ebu ogun yi sinu re ao tun po pomo omi agbon ti apo mo eje eyeile yi dada ao wa yo okan eyele yi ao lo mo ori ao fi yi gbogbo ara ado kinkini yi ao gbe pamo sibi kan ti oba di ni agogo kan oru gerege ao bora si ihoho ni awa nikan ninu yara leyin na ao gbe omi agbon ti apomo eje eiyele ati ebu yi ao gbe mu lekan na akogbodo je nkan elemi fun odidi ojo meta be sini akogbodo sunmo obinrin fun 21 days hummm etutu re re o ni osu metameta ao ma pa eiyele funfun kan ao gba eje re sinu ife ao fi omi agbon po ao gbe mu kai kai enikeni ti oba se oso owo yi yio ni owo jaburata nitoripe ojo keji ni yio bere ise okiki re yio kan kakiri aiye isena nje dola ise ti moti danwo dada ni
Pemi tio ba fe awon ise mi miron tabi o fe kin bao se 08146664979 abii Koo add mii sii WhatsApp number 08146664979

(1) (Reply)

How To Beat Stress And Live A More Balanced Life / Faforon The Solution To All Stubborn Incurable Ailments / If You Own A Clinic, Hospital Or Pharmacy - See This

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 17
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.