Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,154,195 members, 7,822,036 topics. Date: Thursday, 09 May 2024 at 03:10 AM

Osole Owo Laa Tii Aa Fii Gbee Ilee Aye Nii Irorun - Health - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Osole Owo Laa Tii Aa Fii Gbee Ilee Aye Nii Irorun (1347 Views)

Asirii Tii AA Fii 50k Pere / Ise Osole Awon Babami Ayee Igba Nii Tii Won Fii Jehun / Osole Owo Todaju (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Osole Owo Laa Tii Aa Fii Gbee Ilee Aye Nii Irorun by bullet001: 6:43pm On Apr 26, 2021
#OSO_OWO_NLA_TODAJU_TIWON_NPE_NI_ITIFAGOGO

ni bi odun metala si medogun seyin awon eyan se oso yi gann tojepe kofesi ninu awon olola nigbana lohun ti won o fe se ise yiii naa
kinse ise yiii nikan ooo
larawon ni
ifagbalu tiwon tun npe ni ifabesode
larawon ni ofitifiti ako abo ree naa wa
larawon ni oladogido
larawon ni iji omo inu igbo
larawon ni omikun bori afara
e.t.c

amo nigbati oto asiko kan agbara awon ise yiii walee
won ni agbara pupo mo nitori ero tipo ju lewon lori
awon agbalagba fi owo bo awon miran mole ninu won
besini won fa agbara awon miran walee tan

afi eni toba wo inu ile daada ni o ma tun nri won die

ni gbogbo awon akoko ti won ti fi owo bo awon ise yiii
enikeni toba kowole won nigbanaa o fi owo jona ni

afi eni toba ni IMULE kan tiwon npe ni IMULE pakaja lara ni yio mo eyi to si nje ninu awon oso yiii imule pakaja yiii je imule kan towulo pupo tosepe OGun tio ba sise mo abi eyii tiwon ti fi owo bomole abi eyi ti won fa agbara ree seyin kedere bayii ni won yio ma fi hanyin loju orun won o ma koyin gbigba ti eyan bawa ni classroom ni...imo po lodo awon agbalagbaaa, amo lasiko yiii oso itifagogo si nsise amo koni agbara bi ti tele mo ..tobajepe tele ni eni toba lo yio ri owo to 10milion amo agbalagba ti fa agbara ree ku eni toba lo nisin kole ri ju 3-4miliion lo mo ti yio sini Ebe togbona gidi lara.....eni toba yawo ogun kolo gbinyanju reee abi kiwon bao se ogun ni

#isenaree

Odidi ijapa ako nla kan
Odidi igbin agbonu nla kan
Owo elegbede osi tope
OWo otun akuju kan tope
OGa oye meje
Gbogbo currency
Odidi atare kan
opolopo ewe ola topo dada
igo oti sschnapp meta
akuko adie kan togbo

Ao ma ta awon oti yen si lori inaa titi yio fi jotan

ao so adie yen mo sakani ibi ti ati njo alejo kan yio bawa nbe kato jotan ao fun ni owo ao si gbe igo oti kann ninu oti meta yen fun pelu akuko adie yen
igo oti ikeji lao ma tasi ogun naa lori inaa
igo oti eleketa lao ma yomu pelu awon toba wa nbee ....OKunrin loma wa gbe awon adie ati oti kan ooo pelu oba owo kobaje 1000 or 500

taba jotan ao lo kunnaa dada ao ro sinu igo funfun kan ao gbe sinu asuwo ao gbeko, ejee ka ranti fi epo yika aro ooo
ao ma fi oti lo lararo pelu gbolohun reeeee

#GBOLOHUNRE:-

Itifagogo gongo fa iti gburu fagburu gburu fa igbo
owo(hand) eni fa ire funmi eleran ara eniyan koniji koma ronu kan owo nlanla kan
Alijonu tinbe lode ilu yiii eronu owo nlannnla kan emi l-l ti alagemo baa ta awore afi gbare lowo eledumare odidi owo niki omo araye ma fi tami loree
aniyan.....

ninu oso to nje niyi wa 100%

#Majemu_ree:- enitobari ise yiii ko fi comment dupe ore kole je fun

Dr ifa Lana awoyemi ogboni Ile Yoruba patapata 08146664979abii Koo add mii nii WhatsApp

(1) (Reply)

Strange Growth On My Private Part / Pure Water how pure / Who Do You Know That Wants To Drop 2-3 Dress Sizes In 10 Minutes ?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 13
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.