Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,886 members, 7,810,405 topics. Date: Saturday, 27 April 2024 at 08:25 AM

Omi Iye Naa (CAC Living Water) October 15, 2021 [yoruba] - Religion - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Omi Iye Naa (CAC Living Water) October 15, 2021 [yoruba] (379 Views)

Omi Iye Naa (CAC Living Water) 18th October 2021 / Jesu Ni Ajinde Ati Iye / Ifa Naa Ki Bayi Wipe: Òkàn Sá (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Omi Iye Naa (CAC Living Water) October 15, 2021 [yoruba] by ChristianFeeds: 10:46am On Oct 15, 2021
Laiwo ti igbe/ikede awon ajo to n ri si ominira awon obinrin ti o gba ibi gbogbo kan, o je ohun ti ko se e se pe awon obinrin je ohun -elo elege si okunrin. Kii se eesi bi kose ohun ti o ti wa nikale lati seto iru oro yii ni ojo oni tii se Ayajo Ojo Awon Obinrin Ti O Wa Ni Igberiko.

Ni iseda, Olorun yo egungun kan lati iha okunrin to sun oorun ijika naa, pelu re, O da obinrin naa. E je ki a wo o bayii. Niti eniyan, sisakawe okunrin ti a da lati ibere pepe lati inu erupe ile pelu obinrin ti a da lati inu egungun kan lati iha okunrin naa ni ti agbara/okun le ma mogbon wa. Niti eniyan, eto mimu ki egungun iha naa o fe sii, le mu ki eda ti a da nipase re, obinrin naa, o je alailagbara bi okunrin naa. Abajo ti a fi toka si obinrin bi ohun elege (I Pet. 3:7)

https://www.thechristianfeeds.com/2021/10/omi-iye-naa-cac-living-water-wa-okunrin.html

(1) (Reply)

Rapture In The Old Testament / What Does It Mean That God Is Just? / I Willed It Into Existence (believe And Receive)!!

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 6
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.