Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,158,022 members, 7,835,464 topics. Date: Tuesday, 21 May 2024 at 10:32 AM

Yorùbá Discord|ẹgbẹ́ Ọmọ Odùduwà - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Yorùbá Discord|ẹgbẹ́ Ọmọ Odùduwà (421 Views)

Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán / Odùduwà Republic / Ònkà - The ABC Of Yorùbá Numerals (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Yorùbá Discord|ẹgbẹ́ Ọmọ Odùduwà by Ayobamikale: 11:27pm On Apr 03, 2022
Ẹ káàbọ̀!!! Mo retí pé ọjọ́ ẹ wà dáadáa!!! Mo ti fẹ́ pín ìlujá kan fún gbogbo àwọn Yorùbá tó jẹ́ ẹni olùfìfẹ́hàn ní àṣà, èdè, àti ìṣe Yorùbá. Àwa yóò fẹ́ gidi gan-an fún ẹ láti dara pọ̀ mọ́ àti pín ìmọ̀ ẹ àti àwọn ìrírí ẹ, láti kọ àgbàjọ kan tó dára fún wa, àwọn ọmọ Yorùbá!!! Nínú Discord yìí, àwa máa ń sọ̀rọ̀ nípa gbogbo ohun, bí àwọn nǹkan lórí èdè wa, ẹ̀sìn wa, ìtàn wa, àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Mo retí pé ẹ máa dara pọ̀ mọ́!!!

Ìlujá: https://discord./mFdUFS6CRv

Ẹ káàbọ̀!!! Hello everyone, I hope your day is going well!!! I just wanted to share a Yorùbá Discord server link for anyone who is interested. We would love for you to join and share your knowledge and experiences, and help to build a positive online Yorùbá community!!! In the Discord we talk about everything from language to traditional religion to history and more. I hope you consider joining.

Link: https://discord./mFdUFS6CRv

*We do not accept discrimination based on sex, gender, sexuality, or other personal characteristics. Thanks!!!

(1) (Reply)

Igbo People Are Responsible For Killings In South-east, Not Fulani / Folklore Of Edo Legends - Arhuan the Giant and other Edo Folklore / Book Release: History Of The Obodoukwu People By Canice Muoka Umege

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.