Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,158,080 members, 7,835,644 topics. Date: Tuesday, 21 May 2024 at 12:52 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Eyonu Asina Tipa Tipa By Fire By Fource Ona Masi Fun Wa Dan Dan (355 Views)
Dan Orbih’s N800m Scandal: Members Cry Foul Over Sharing Formula..... / [MUSIC] 2HO – Omotena Roll It [prod: Dan Jiggy] / Gani Adams: How His Unusual Birth Predicted His Aare Ona Kakanfo's Position (2) (3) (4)
(1) (Reply)
Eyonu Asina Tipa Tipa By Fire By Fource Ona Masi Fun Wa Dan Dan by Ifayemi27(m): 12:25pm On Jan 12, 2023 |
EYONU ASINA TIPA TIPA BY FIRE BY FOURCE ONA MASI FUN WA DAN DAN Aidan meje, a o gesi meta meta, Ao ko sinu agbada , Ao fi odidi atare kan si, Ao jo , Ao lo kuna, Ao ro sinu ado kan , Ao ran ado yen ni aso pupa ti ara ado yen koni han sita mo rara LILO RE: Ti a ba ti fe lo ise yi, ao bu si owo osi ao te ni odu ogbeyonu, A o pe gbolohun re si - A o ma fi fokomu laro laro, ki a to soro si enikeni. GBOLOHUN RE: Aji morinse omo ogan, Aji gbedako omo orile atan, Osumare ego nisoju Eledumare wa sile aye sagadade, awon ni won sefa fun awon olomo alabi digi, won sefa fawon olomo alabi tasa, Orunmila ni to ba se bi ija, to ba se bi ibinu oni omo eni laa ran sini, ogbeyonu o! Ogbeyonu Oo!! Ogbeyonu ooo!!!, wa lo ba mi ba awon iya mi osoronga ki won o yonu si Emi lagbaja omo lagbaja . eyi to ba ko to, ba loun oni gbo, e yi to ba ko to ba ni oun ko nigba, Aidan kiri egbe fi lele, koma ri egbe fi le le lode aye, ko ma gba ode orun lo, nitori wipe dandan ni taidan, dandan ni ki emi lagbaja omo lagbaja o ri te mi se nile aye. Ao se adua si daadaa , Ao ma fi fokomu laro laro For more enquiries or consultation:- 08138150914 From group admin asiri ola-ifa Imule agba |
(1) (Reply)
Get The ABC Course Today. Start Earning Your Own Money / Costly Mistakes To Avoid As A Youth / Bad Credit? No Worries! Effortless Instant Approval Loans On Top Platforms
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7 |