Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,157,969 members, 7,835,229 topics. Date: Tuesday, 21 May 2024 at 07:21 AM

F A R T I N G��‍♂� Ẹ Jẹ́ Ká Máa Só Oo� - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / F A R T I N G��‍♂� Ẹ Jẹ́ Ká Máa Só Oo� (212 Views)

Ẹ̀rìndínlógún / Oba Abdulrasheed Akanbi Buys Innoson G-wagon For 2nd Coronation Anniversary / Igwe Godwin Madu Buys Mercedes-benz G-wagen 2018 (Photos) (2) (3) (4)

(1) (Reply)

F A R T I N G��‍♂� Ẹ Jẹ́ Ká Máa Só Oo� by enemyofprogress: 4:02pm On Aug 26, 2023
Farting is usually considered to be the most shameful or humorous function of the body. Everyone farts but have we ever taken a moment to think about the science and history behind it?
Isó sísó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ohun tí àwọn ènìyàn kà kún ohun ìtìjú lára àwọn ohun tí ń jáde lára wa. Gbogbo ènìyàn ní ń só, ṣùgbọ́n, wọn kì í rántí láti kíyè sí ìmọ̀-ìjìnlẹ̀ sáyẹ́ǹsì tó wà nínú isó sísó pẹ̀lú àwọn ìtàn tó rọ̀ mọ́ ọn.

12 Facts About Farting You Probably Didn’t Know
(Àwọn nǹkan méjìlá tí a ní láti mọ̀ nípa isó sísó)

1. Females tend to fart less than males.
1. Àwọn ọkùnrin máa ń só ju àwọn obìnrin lọ.

2. First used in 1962, fart means the wind coming out of the anus. Pretty apt don’t you think?
2. Ìtàn fi yé wa pé ọdún 1962 ni wọ́n kọ́kọ́ lo èdè ìperí Gẹ̀ẹ́sì "Farthing" fún isó sísó, tí ó sì túmọ̀ sí afẹ́fẹ́ tí ń tú jáde ní ojú fùrọ̀.

3. A normal human being will fart over a dozen times every day.
3. Ojúlówó ẹ̀dá ènìyàn gbọ́dọ̀ só ní ìgbà méjìlá tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ lójúmọ́.

4. And the air they produce can be used to blow up one balloon.
4. Afẹ́fẹ́ isó àwọn mìíràn tó láti fọn fèrè kan ṣoṣo tí yóò fi tóbi.

5. Don’t ever be embarrassed about a fart because it is actually an indication of good health. If your digestive system is working as it should, you will fart.
5. Isó sísó kì í ṣe ohun tó yẹ kí ó máa tì wá lójú, nítorí pé àpẹẹrẹ ìlera tó péye ni. Bí òpónà ibi tí oúnjẹ wa ń gbà bá ṣe iṣẹ́ déédéé, ó yẹ kí ènìyàn lè só.

6. The main component of a fart is hydrogen sulfide which helps decrease any damage to the mitochondria. This means that taking in the smell is actually good for you.
6. Ohun tí ó ṣe pàtàkì jù lọ nínú isó sísó ni ẹ̀yà ara ènìyàn kan tó ń ṣe iṣẹ́ déédéé láti dènà ohun tí ó lè ṣe àkóbá fún ìlera wá. Èyí túmọ̀ sí pé, bí a bá ń fa òórùn símú nígbà mìíràn, ó wúlò fún ìlera wa.

7. While women don’t fart as much as men, their farts tend to smell more because they have greater levels of hydrogen sulfide. This makes the air they produce better for your health as well.
7. Àwọn obìnrin kì í só púpọ̀, ṣùgbọ́n, bí wọ́n bá só lẹ́ẹ̀kan ṣoṣo, ó ju kí ọkùnrin mẹ́wàá só papọ̀ lọ. Ìdí ni pé, ẹ̀yà ara tó ń ṣe ìdènà fún ohun tí ń ṣe àkóbá ìlera tó wà lára àwọn obìnrin lọ́ọ̀rìn ju ti àwọn ọkùnrin lọ. Irú isó tí àwọn obìnrin ń só pa wá dára fún ìlera wa.

8. Your farts are much faster than you because they travel 10ft/sec.
8. Isó tí a máa ń só yára jáde kúrò lára sínú afẹ́fẹ́ púpọ̀, ní èyí tí a lè fi wé òdiwọ̀n gíga bàtà mẹ́wàá láàrin ìṣẹ́jú kan.

9. The tighter your sphincter, the more sound your farts will make because they can’t get out easily.
9. Bí a bá ṣe fún fùrọ̀ wa tó, ni dídún isó wa yóò ṣe pariwo tó, nítorí pé isó kì í jáde wọ́ọ́rọ́ lọ́pọ̀ ìgbà.

10. If you chew a lot of gum and drink aerated drinks, it will increase the frequency of your farts.
10. Bí ẹ bá jẹ ṣingọ́ọ̀mù dé ojú àmì pẹ̀lú àwọn ohun mímu ẹlẹ́rìndòdò kan, ó máa ń ṣe okùnfà kí isó sísó ènìyàn ga ju bí ó ti yẹ lọ.

11. Most of our daily farts happen when we are asleep.
11. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn isó tí a máa ń só lójúmọ́ máa sábà jẹ́ ìgbà tí a ń sùn dáadáa.

12. Termites may be small in size but they fart more than any other creature. Camels come a close second, followed by zebras and cattle.
12. Àwọn ikán lè jẹ́ kòkòrò tó kéré lójú wa, ṣùgbọ́n kò sí ẹ̀dá Ọlọ́run kan tí ń só tó ikán. Ràkúnmí ló pọwọ́ lé ikán nínú isó sísó, tí egbin sì tẹ̀ lé Ràkúnmí pẹ̀lú màlúù ọmọ ìkẹyìn wọn.

About 87,9% of men who don't fart when urinating are infertile.😊😊😊
Àwọn òkóbó ọkùnrin tí wọn kò dín ní ìwọ̀n mẹ́tàdínláàádọ́rùn-ún nìkan ni wọn kì í só nígbà tí wọ́n bá ń ṣe ẹ̀yọ́.

Don’t be so hard on yourself.
At least you feel better if you do what nature intended.
After all, it’s healthy for you.
Go ahead and let it rip!🤪
Ẹ má fi ìtìjú kárùn. Ó yẹ kí a lè ṣe ohun tí ó jẹ́ àbùdá-ìṣẹ̀dá àjẹbí wa. Ohun tó dáa gbáà ni kí a máa só oo!🤣

Stay Healthy always 🤝👏
Ẹ jẹ́ kí a kíyè sí ìlera wa ní gbogbo ìgbà oo🤝👏

... FART FOR REAL
.... Ẹ JẸ́ KÍ A SÓ OO

AM I COMMUNICATING?
MO WÍ IRE ÀBÍ N Ò WÍ IRE?
Re: F A R T I N G��‍♂� Ẹ Jẹ́ Ká Máa Só Oo� by Jagabanofafrica: 4:57pm On Aug 26, 2023
Nice write up
Re: F A R T I N G��‍♂� Ẹ Jẹ́ Ká Máa Só Oo� by sirgbeja(m): 12:22pm On Aug 27, 2023
I like this write-up.

(1) (Reply)

Angola �� Vs Ghana �� Which Country Is Better? / Mursi Tribe. The Lips Plate Tribe In Ethiopia / Rivers Community, Ogu Initiate Young Virgins Into Womanhood

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 16
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.