Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,155,075 members, 7,825,394 topics. Date: Sunday, 12 May 2024 at 01:12 PM

Do You Speak Yoruba? - Culture (12) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Do You Speak Yoruba? (102317 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (9) (10) (11) (12) (13) (14) (15) ... (43) (Go Down)

Re: Do You Speak Yoruba? by biggerboy(m): 8:39pm On Jan 13, 2008
Mo tun ti de o !!!

E ma binu si mi o.mo lo si abule wa lati lo gba ogun ti ma fi pa rich dad ni o
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 12:26pm On Jan 14, 2008
biggerboy:

Mo tun ti de o !!!

E ma binu si mi o.mo lo si abule wa lati lo gba ogun ti ma fi pa rich dad ni o

won tun ti de oooooooo

awon gbomogbomo

nibo lo gbalo lati ojo yi ooooo

kilode ti ofi fe pa richdad?

ki lo tun se fun ee oooo

mo ro wipe eti pari ija ni?

2008 ma la wa bayi biggerboy

otun lo si ilu yin nitori richdad shocked shocked shocked shocked

oga gan ooooo

fi iye denu ooooo

lo jebure

ki o si kaabo sori eto yi pada

ki lo mubo fun awon ara ile oooooo

se oko o jeepo oooo

eku ojo meta ooo

esi ku odun ooooo


ilugunboy:

tawa, iwo ko ni mo mba wi jare, tope to ntun blow english lori thread yi ni mo mba wi.

Se owa pa, mo hope pe awon oga o stress e ju loni ni office. Ni nice weekend.

@ilugunboy

ok
mo ro wipe emi loun bawi ni

se o wa ok sha?
bawo ni weekend eee?
eyara si ise oni ooooo


femadis:

@ Tawa temi,

Ose gan nio, Oluwa atun bo ma ran e lowo, O need lati lo courie, sati pe mii tio ba ti se tan.

Ba wo nii idanwo re tio se ni ojo sii? esii ayo la o ma gbo oooo(amin)

eyan mi se o wa ok sa?
ose pelu adura re ooo
bawo ni mo se ma san owo adura bayi?

esi idanwo koiti jade, sugbon ko ni pe jade mo
nitori ati bere another semester bayi.
The last session naa lan se lowo bayi.
Oju nti kan mi, mio le duro ko pari mo
ko easy lati ma se ise ati lati ma lo si ile iwe
but mo n try lati cope sa.

se o wa ok sha?

Richdad nko?
talo bami ri awon season contributors gbogbo won yi?
ebami ki gbogbo won ooooo.


eyara si ise ooooo

Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 1:12pm On Jan 14, 2008
Esioooo
Yoruba ni gbogbo yin gbe laruge to bayi, Mo gbedi fun gbogbo yin, mo si tun juru pelu.
e mura sii, emaa so nso

Emi naa yo laiki lati ki yin ni ede ilu mi Ijesha

hin pele nibe ni ooo hia omo ujesha lo mi ki hin o
se alaafia ni hin wa, hin ku odun, aseyi samodun o, gbogbo ria laa ri odun o mi bo ooo
oba adimula ule ujesha hi ki mi ki in o, o fi oooo(money) die ranse si gbogbo rin sugbon oko je epo lona, ni mo ba foooo rin repo soko. hin ni binu simi ni o

hin pele.
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 4:43pm On Jan 14, 2008
webdezzi:

Esioooo
Yoruba ni gbogbo yin gbe laruge to bayi, Mo gbedi fun gbogbo yin, mo si tun juru pelu.
e mura sii, emaa so nso

Emi naa yo laiki lati ki yin ni ede ilu mi Ijesha

hin pele nibe ni ooo hia omo ujesha lo mi ki hin o
se alaafia ni hin wa, hin ku odun, aseyi samodun o, gbogbo ria laa ri odun o mi bo ooo
oba adimula ule ujesha hi ki mi ki in o, o fi oooo(money) die ranse si gbogbo rin sugbon oko je epo lona, ni mo ba foooo rin repo soko. hin ni binu simi ni o



hin pele.


Infact erin de pami titi mo fi gba oga mi ni ibi ise laya

Ede Ujesha yen dun gan lenu re to po

se wa ko mi ni ede naa?

mo si nrerin,  grin. grin. grin grin grin grin
Re: Do You Speak Yoruba? by femadis(m): 3:49pm On Jan 15, 2008
@ Tawa-temi

Mo wa ok oooo, se ise nlo?.Oluwa tio ba o bere ile-iwe re, yio bao pari re layooooo, mo n bga adura fun ooo.

Wo, Tawa, wa nkan se sii oro biggerboy ati richdad yioo,kii won te jeje ooo,.

Tawa, mo ma nhun appreciate awon foto tio oma nhun fi ranse pelu oro re lori tirendi yi.
Re: Do You Speak Yoruba? by kochito(m): 6:29pm On Jan 15, 2008
@webdezzi,
mo gbadun Ijesha to so yen,okan je wipe bi mo se je omo ilesha mi o mo ede yen so daada.
Eyin omo kaaro ojire,se ewa pa? Mo sorry pe oti pe ti mo ti contribute si thread yi,nitori ati da nani.
Mo sese resume fun ise titun kan si Port-hacourt,eyi to je wipe mi ki raye rara mo,ede mo pe ise banki ma gbaye pupo,idi ni yii ti mi ki fi contributi mo.
Tawa-temi, se o wapa,awon ololufe re nko?Tete dibo fun enikan ninu won nitori pe odun titun lawa yi.
Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 11:17am On Jan 17, 2008
Tawa-Temi:


Infact erin de pami titi mo fi gba oga mi ni ibi ise laya

Ede Ujesha yen dun gan lenu re to po

se wa ko mi ni ede naa?

mo si nrerin, grin. grin. grin grin grin grin



@Tawa Temi

Ni Temi o, Maa ko e ti o ba gbara duro,
sugbon ti o ko ba gbe ara duro, emi ko ni ko e
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 2:06pm On Jan 17, 2008
webdezzi:

@Tawa Temi

Ni Temi o, Maa ko e ti o ba gbara duro,
sugbon ti o ko ba gbe ara duro, emi ko ni ko e




Kilagbe kilo ju?

gbaraduro fun kinni?   shocked shocked shocked

Oya  gbe ede Ujesha ee lo si iwaju?

Tipatipa ni?

Iru oluko wo lo fe ya naa?

Se bi won se ko iwo niyen?

Infact o dissapoint mi gan !

Ko ya sun si waju pelu ede eeee

mo ma pon e le ni mo se so wipe ki oko mi   angry  angry  angry





@femadis
ose jare

adafuen gidi gan.
ki loro wipe mo le se si oro richdad ati biggerboy bayi?

eyi ti biggerboy fe fi ogun pa richdad yi o ma da ke?


@kochito

nibolo lo?
kabooooo awon ara pota (PH) nko?

ki ni oro wipe mo le se si oro richdad ati biggerboy?
talo da ju ninu awon mejeeji?
Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 5:15pm On Jan 17, 2008
de wa wo, mi o ro lo si gbo ibi ti o nro lo yen o

ohun ti mo nso ni pe ki o farabale kin ko e
mi o binu si gbo nkan to so yen, ha! nkan binti
mo si le ko e sugbon emi kii koni lofe o.
Re: Do You Speak Yoruba? by tufe(m): 5:19pm On Jan 17, 2008
omo men, all these ones pass my power
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 12:02pm On Jan 18, 2008
webdezzi:

de wa wo, mi o ro lo si gbo ibi ti o nro lo yen o

ohun ti mo nso ni pe ki o farabale kin ko e
mi o binu si gbo nkan to so yen, ha! nkan binti
mo si le ko e sugbon emi kii koni lofe o.



hmnnnn

o da ma binu

mi o mo wipe o ro lo si ibe yen

se omo wipe ede Yoruba ni itumo lorisirisi?


Oda ooo, elo lowo ee ?

elo lo fe gba lati ko mi ni ede Ijesha?  undecided  undecided

Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 2:08pm On Jan 18, 2008
egberun lona egbeegberun ni maa gba. ede ria, e sheeepu, ooooooo(money) goboi lo fi a ko,
aaaa(we) koko bere pelu hin an faweeli ede ulu ria

Faweeli kan soso la nife ju lujesha, oun ni faweeli "U"

eyi lo difa fun oluko to wa si ilesha lati ko ede yoruba, o fun awon akeko ni apeere gbogbo faweeli
nigbati o de ori "U" O so wipe "U ko po lo titi" lo ba fun won ni apeere kan soso, o ni "U- Ukuluku"

kia ni akeko kan fo dide o ni

Oluko ria, hin disigrasi ara rin loju hia omo ujesha, "U" po,

U=Ule, Ule baba mi fe ju ule baba re lo
U=Uyan, Uyan nijije hia ujesha
U=Ufe, Ufe tawa_temi mi pa mi bi oti
U=ukoko inu ukoko obe ni mo ti jeun oiro (oiro means morning pronounce [b]U[/b]mbrella)

Lati oni lo, hin mo efa so pe esi "u"
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 8:59pm On Jan 21, 2008
Infact "u" surprised me gan pelu ude Ujesha.

se mo try?
Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 11:27pm On Jan 21, 2008
Tawa-Temi:

Infact "u" surprised me gan pelu ude Ujesha.

se mo try?

Infact ti mo ba pe e ni olodo, mo ko iyan e kere ni yen
Olodo rabata lo fe ya,

Atunse:
'i' ='u'
Infact, o sopasiraisi mi gan pelu ede ujesha re.

Ise Amurele:
Tunmo awon gbolohun yi si Ijesha
1. ki lo n se e bi eleyi
2. tani yen
3. mi o mo nkan ti o nso
4. e je ka gbadura fun Tawa-Temi
5. e je ka lo.
Re: Do You Speak Yoruba? by hclacid(m): 1:42am On Jan 22, 2008
man! am just going crazy here on this thread since it's been a very long time that i've not had contact with the yoruba language. kilon happen,kosi nkon nkon. moni ké keep on rockin' o yeah orobo kibo,keep on dancin' o orobo kibo.
i remember this one

BOLUTIFE OKO FUMILAYO
OKO AYA BABA TOLULOPE
DO DO DO
MA DOMI NISO
EMI MO LOBO MI. grin grin grin grin grin grin no be me ooo! shocked

*hcl beats his hand and says 'u don spoil finish, na wa o'*
Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 4:12am On Jan 22, 2008
hcl_acid:



BOLUTIFE OKO FUMILAYO
OKO AYA BABA TOLULOPE
DO DO DO
MA DOMI NISO
EMI MO LOBO MI. grin grin grin grin grin grin no be me ooo! shocked


oro yi je kayefi, o dabi eni pe seun osewa fi ina sori orule sun
Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 4:16am On Jan 22, 2008
lol


@post
eka le. eyin omo yoruba, esi kun ka le o. . . inu dun, bi ti oyin .nitoripe mo ba awon omo ile yoruba mi ni Nairaland. . . . omo kan nan ni gbogbo wa, ese ti efi isuru ka nkan ti mo se ko grin
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 4:02pm On Jan 22, 2008
webdezzi:

oro yi je kayefi, o dabi eni pe seun osewa fi ina sori orule sun


erin npa mi ooo   grin  grin  grin  grin


[size=20pt]Use amurele[/size]


1.   Ku lo nse e bi eleyi? 

2.    tanu yen?

3.    mu o mo nkan ti o nso

4.   Uje ka gbadura fun webdezzi

5.    Uje ka lo

(After all everything in Ijesha is UUUUUUUUUUUU Ujesha)



Note:
ti 'i'  ba je  'u'

kinni  'e' ma je?

infact mo ti fe ge tongue mi je ni bi bayi ooo


Oluko, o ko mi ni gbogbo faweeli ti o wa ninu ede Ujesha oooo ati bi won nse pronounce it.
Re: Do You Speak Yoruba? by TheSly: 12:26am On Jan 23, 2008
e ma da ori mi ru pelu yoruba amu ori foni yi!

yoruba yin mu ori fo mi. . . eyin olodo wonwon yi
Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 10:54pm On Jan 23, 2008
Esi Idanwo
0/5
Atunse:
1. ko mi se o bii ye
2. yesi ere
3. me moun o mi wi
4. hin je a gbadura fun tawa-temi
5. hin je ka lo
notice> e(for elder or many)=hin

Ede naa ko easy rara, boya ti o ba gba gbogbo oro ti mo ti maa nba e so wipe koo gba temi, maa ko e ni iyoku


~Sly~(*_*):

as for you, silai abi ki loruko e nje,
teacher e ni olodo.

e ma da ori mi ru pelu yoruba amu ori foni yi!

yoruba yin mu ori fo mi. . . eyin olodo wonwon yi
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 12:35pm On Jan 24, 2008
shocked ye! so, odo ni mo gba?


infact mo ti surrender, mio ni interest mo.


eyin mi gan ti fe ka nitori ede Ijesha.

mio ko mooooo

Iwo nikan ni omo Ijesha ti mo mo papa, so 1 out of 1,000=?


AM OUT!

Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 3:00pm On Jan 30, 2008
[size=40pt]Mo ki dede yin ooooooo[/size]

Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 3:44pm On Jan 30, 2008
kilonsele sweet heart
Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 4:16pm On Jan 30, 2008
@ tawa-temi,

webdezzi tie try die, se iwo leko eyan ni ede ilu e? grin., tori wipe emi ko leko ko anyone ni ede ilu mi rara. (egba mi baaaaad!!) grin
Re: Do You Speak Yoruba? by behold(m): 4:31pm On Jan 30, 2008
Eyin temi e ti poju!!!!! Ema da awon ojowu loun. Ema mind yoruba mi, I beg keep d fire burning,
Re: Do You Speak Yoruba? by RichDad1(m): 7:52am On Jan 31, 2008
[size=8pt]Mo pada de o gbogbo ile [/size]

@Biggerboy,
Smallboi abi ki ni oruko ee? Se o ti gbagbe wipe atari ajanku ki n se eru omode ni ? erin n pa mi,

@Tawa-mi,
Ololufe mi owon,ba wo ni gbobo nkan se n lo?ma binu simi wipe mi o so fun e kin to lo fun end of the year break mi, infact mo tun lo wa owo si lohun ni (maso fun anybody ooo lipsrsealed lipsrsealed )
Mo ti de nisiyi owo ti posi,ka jo ma gbadun bi eeran inu sugar ,

@all
Bawo ni ile se mo ba yin dada ?, cool cool cool cool cool cool cool cool cool
Mo ri yin na wink wink wink wink
Re: Do You Speak Yoruba? by RichDad1(m): 8:02am On Jan 31, 2008
webdezzi:

kilonsele sweet heart

website tabi ki ni oruko ti wo?
O ba efon labata o yo obe si, hen? se o mi lo wipe o mun yo ni? For your information no vacancy in Tawa's Heart, Okay? angry angry angry
SWEETHEART KO SWEET COCONUT NI THIEF cheesy cheesy cheesy cheesy cheesy cheesy cheesy cheesy cheesy cheesy cheesy cheesy
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 9:21am On Jan 31, 2008
Infact mo wa short of words fun gbogbo yin   lipsrsealed  lipsrsealed  lipsrsealed

i.e  Richdad, Biggerboy, Ilugunboy ati webdezzi.

Sugbon mo ma ma soro later sha.

Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 10:35am On Feb 01, 2008
Mo fe ki gbogbo yin ni [size=40pt]opin ose [/size] alarinrin

Re: Do You Speak Yoruba? by Shaddey: 6:13pm On Feb 01, 2008
nice 1 jare!

emi ko ran enikankan rara, ohun to ba wu elenu ni ki o fi enu e so,

a bi ?

mo gba fun e jare , ore mi ,je ki yoruba yen maa ro beyyyyyyyyy

ma ran won rara!
Re: Do You Speak Yoruba? by Bblak(f): 6:19pm On Feb 01, 2008
Ki lon sele nibi.E gbadun weekend yin jonotin do you cool
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 10:09am On Feb 11, 2008
[size=40pt]E kaaro [/size] nile yi ooooo


Ta lo ma volunteer kin gbe ohun jade fun valentine?

Enikan pere ni mo fe oooo

Obinrin tabi Okunrin to ba ni interest.

(1) (2) (3) ... (9) (10) (11) (12) (13) (14) (15) ... (43)

Ife Queen Wuraola With Her Lebanese Husband / The Nuba Peoples Of North Sudan (warning: Tribal Nudity) / I Want To Learn Igala Language, Get In Here.

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 61
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.