Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,162,318 members, 7,850,141 topics. Date: Tuesday, 04 June 2024 at 02:59 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Do You Speak Yoruba? (102602 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (20) (21) (22) (23) (24) (25) (26) ... (43) (Go Down)
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 4:30pm On May 15, 2008 |
Why guest room? sebi ani iyara tiwa? se ofe gbe elomi wale ni?
|
Re: Do You Speak Yoruba? by kolaoloye(m): 5:06pm On May 15, 2008 |
Gbe elomiran wale ke? Mo ni eto kekere kan ti mo nse sile de e ni ibe. Atipe mo lero pe ile ma su pupo ki o to de ni. Haba! se nitori nkan ti mo so ni o se lo hire okunrin atamatase olofa-ina? Jowo tori Olorun ma pa eniyan si mi lorun o. O saa mo pe "no rival" ni e. |
Re: Do You Speak Yoruba? by kolaoloye(m): 5:30pm On May 15, 2008 |
WITH ALL MY HEART FI OKAN RE BALE. KO SI EWU |
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 5:38pm On May 15, 2008 |
ok My Love Se omo wipe iyawo no rival ni mi? ara mi ngbona gidigan ooo ti oba fi le fe iyawo lemi, acid ni ma dasi eyin mejeeji lara
|
Re: Do You Speak Yoruba? by tinakoya(f): 12:24pm On May 16, 2008 |
Mo fe ba e darugbo,mo fe ba e kale, iwo ni mofe ma ji ri lo jojumo aye mi. Cont. Olo mi |
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 1:26pm On May 16, 2008 |
tinakoya: Amin ooooooo @Kola Oloye Olomi, onitemi, ore mi, ololufe,oju kan o, sa'lada ni, lola'luwa, ko soun tio yawa, |
Re: Do You Speak Yoruba? by kolaoloye(m): 12:22pm On May 22, 2008 |
MO KI GBOGBO ILE PE E KAAASAN O. @Tawa-Temi, BAWO LO SE JE? E KU IGBAGUN ASIKO YI O |
Re: Do You Speak Yoruba? by kolaoloye(m): 11:26am On May 28, 2008 |
[size=15pt]AWON TEMI DA? [/size] Iroyin Ayo: Ayeye igbeyawo Tawa-temi ati Kola Oloye yoo waye ni aipe yi. Ojo kejidinlogun osu aga ni a o se introduction wa. Ilu Eko ni yoo ti waye. Ipalemo (preparation) ti o nlo lowo ni ko je ki e ri Tawa-temi lori apero yi. Sugbon yoo ba yin soro laipe yi. E se pupo.Nkan rere ni a o ma ba ara wa se o (amin) |
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 8:22pm On Jun 12, 2008 |
Baba oloye bawo ni? se owa pa? Ise ni o je kin raye lati ojo yi ooo. Bawo ni Abuja? Ba mi ki gbogbo awon ara ile ooo so fun won wipe ma kan si won lara laipe. |
Re: Do You Speak Yoruba? by Dojo(m): 5:39pm On Jun 13, 2008 |
O ga ju! |
Re: Do You Speak Yoruba? by holythug(m): 5:48pm On Jun 13, 2008 |
o ga gan ni o |
Re: Do You Speak Yoruba? by Moyola(f): 6:57pm On Jun 13, 2008 |
Beenii o tii ga la gaju Tongue twister nii yii, e try e tii e ba le so nii kia kia {Diz a tongue twister, try it} "Opolopo nii ko 'lopolo, tii won sii fe gba opolo lowo opolo" {Lotz of ppl don't have sense, n wants sense from a frog} |
Re: Do You Speak Yoruba? by kolaoloye(m): 2:14pm On Jun 18, 2008 |
Mo ki gbogbo ile pe e ku asan nile o.Se owo nya? |
Re: Do You Speak Yoruba? by studio43(m): 2:18pm On Jun 18, 2008 |
, uhm, are my supposed to be here? |
Re: Do You Speak Yoruba? by kolaoloye(m): 5:48pm On Jun 18, 2008 |
studio43: CAPITAL NO |
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 10:34am On Jun 19, 2008 |
Eku ise gbogbo ile oooo Mo ti pada de bayi oooo Olowo ori mi Baba Oloye, se dada laba yin oooo Epele, esi ku lasigbo ile wa yi ooo Oluwa ase rere fun gbogbo wa ooo, amin.
|
Re: Do You Speak Yoruba? by Mustay(m): 10:41am On Jun 19, 2008 |
kola oloye: No [size=16pt]NLA[/size] |
Re: Do You Speak Yoruba? by kolaoloye(m): 10:48am On Jun 19, 2008 |
@Tawa-Temi, Se o gbagbe adehun? Aya mi ti fe maa ja bayi o.Eru si ti nfe maa ba mi. |
Re: Do You Speak Yoruba? by Pamperme: 11:22am On Jun 19, 2008 |
mo nipe kin ki yin ni aro yi. Se gbogbo nkan nlo letoleto? |
Re: Do You Speak Yoruba? by tybanky(f): 3:36pm On Jun 19, 2008 |
E le ni be ye ooo gbogbo ile, ayi ba won si ni be lai bawon da si. I dey feel you and gbadun you guys ooooooo! |
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 3:39pm On Jun 24, 2008 |
Olowo Ori mi, oko mi owon, mase je ki aya re ki oja mo wa pelu e kanpe iwo naa mo bi ise se ri ni enu ojo meta yi, oga mi ni ibi ise lo fe fi ise pa mi oooo, Lana, nise lo npe Tope, loni, Tope, ni igba gbogbo Tope, Tope, Tope, Tope, afi bi wipe Tope nikan ni oruko ti owa ni ilu yi. Emi lo nma pe fun gbogbo nkan pelu (coupled with) gbogbo meetings ti mo tun nma lo fun almost everyday. Mo mo wipe, oruko mi lo ma ma pe legbe iyawo e loru ti won ba ti sun. lol Ko le se ki o ma pe Oruko yen lojumo. Anyway, by next week, ise mi a dinku die, nitori awon clients wa ni won ma ma wa si office wa ni sinyi. Mo ti miss e gidigan. ololufe mi owon, olowo ori mi, pele, se ori otutu sa? Bami so fun awon ti o mo wipe ni office mi, an wa awon Marketing Executives oooo Obinrin nikan ni won nwa sa pelu 2-3 yrs experience. Qualification: Marketing, Business Administration & Communication Arts/ Public Relations. CV's to: editorialjobs2008@yahoo.com (Its an International coy)
|
Re: Do You Speak Yoruba? by Emmaxxx(m): 5:02pm On Jun 24, 2008 |
Whats all dis? |
Re: Do You Speak Yoruba? by kenypumpin: 7:11pm On Jun 24, 2008 |
moki gbogbo yin ku le ooooooooooooo,she wapa eyin temi.shen gbadun ara yin sha.ema gbadun lo jare |
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 4:11pm On Jun 30, 2008 |
Baba Oloye Olowo Ori mi Se owa pa? O ga gan ni oooo mio de ri owo e mo? se ise lo gbomi be yen ni? yara si ise oooo |
Re: Do You Speak Yoruba? by bluehorizo(m): 10:45am On Jul 02, 2008 |
Tawa ti Kola nikan. O to jo meta. Bawo lara? Se o n toju Kola daada? A ku ipale mo oo. Ojo a ba wa laye ati alaafia. Eyin iyawo o ni meni. Omo rere lode oko.Wa finu soyun wa feyin gbomo pon loode Kola. Awon ara Egba a mo itoju aya se po. |
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 10:50am On Jul 02, 2008 |
bluehorizo: ese oooo eku ife, tin yin naa a de lori nairaland apeyin ke wa ba wa se ikomo awon omo naa ti mu oruko won wa lati orun Baba Oloye, se owa ok? pele ooo, olowo ori mi ololufe mi owon
|
Re: Do You Speak Yoruba? by kolaoloye(m): 12:17pm On Jul 02, 2008 |
@ Gbogbo afenifere, Ni aipe yi ni a o fi account number ati oruko ile ifowopamo (bank) si ori apero yi, fun anfani awon ti o ba fe fi nkan ranse si awon ibeji. E seun pupo. Ayo onikaluku wa ko ni baje. A dupe lowo yin @ bluehorizo, Se e ngburo awon ara ile. @tawa-temi, Se ko ye ki o kan sara simi , iwo na si ti ri ere gbogbo ise oru ti a ma nse. Se Kehinde ni ko je ki nsun daradara ni oru ana abi Taiwo ni? |
Re: Do You Speak Yoruba? by bluehorizo(m): 3:17pm On Jul 03, 2008 |
Kola ati Tawa Inu mi dun ti mo ba n ri nkan ayo. Nakan ayo daradara ni a ma ba ara wa se oo. Esu o ni ya iwo ati tawa oo. Olorun a toju awon ibeji.aa wo wan dagba oo. tayelolu ejire ara isokun. E jowo e fi iwe pe wa si bi ayeye ikomo/igbeyawo yin oo. Kola Mi o gburo ile oo. Ko si eni kankan ni le mo. |
Re: Do You Speak Yoruba? by kolaoloye(m): 3:22pm On Jul 03, 2008 |
bluehorizo: Nibo ni gbogbo ile lo? |
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 4:56pm On Jul 03, 2008 |
baba ibeji awon ibeji ti nwa yin ooo nibo de lo wa gbalo bayi? se yaradua nio fun e laye ni? oga gan oooo sa se kio wa sile fun weekend yi. |
Re: Do You Speak Yoruba? by rite2salas(m): 10:11pm On Jul 03, 2008 |
gbegborun |
Re: Do You Speak Yoruba? by bluehorizo(m): 11:28am On Jul 04, 2008 |
Gbogbo ile e jowo e ba wa be modirato ki o jowo gbe eto yi lo si ori iyara ede. [size=5pt]Pls beg the moderator to move this thread to culture.[/size] rite2salas Bawo ni Seattle? jowo ba mi fi eja ranse lati Pike Fish Market. Mo gbadun ibe yen, mo de ibe ni igba ti mo lo si Port Angeles. Se alaafia ni? |
(1) (2) (3) ... (20) (21) (22) (23) (24) (25) (26) ... (43)
Photos From Wema Bank Old School Day Celebration / History Of Nsibidi The Ancient Igbo Alphabets Britain Destroyed Ibo Civilization / Ooni Ogunwusi Wears Aare Crown For The First Time (photo)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 39 |