Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,165,283 members, 7,860,662 topics. Date: Friday, 14 June 2024 at 01:56 PM

Ademotech's Posts

Nairaland Forum / Ademotech's Profile / Ademotech's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by ademotech: 3:32am On Oct 22, 2017
ejor mo in lo Ogun aromolagun ati Ogun ti obirin le lo ti oju Abe baa yun ti oba SI fe ni ibalopo pelu okunrin oju Abe TUN ma ta gan
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ademotech: 3:29am On Oct 22, 2017
ejor mo in lo Ogun aromolagun ati Ogun ti obirin le lo ti oju Abe baa yun ti oba SI fe ni ibalopo pelu okunrin oju Abe TUN ma ta gan
Culture / Re: .. by ademotech: 7:43pm On Jan 06, 2017
Ifankaleluya:

E lo re wa EWE-AJABO(eku gogoro ni a n pe bayen). e gbo ninu omi ti e le fi we ni e kan soso ni aro kutukutu, ki e wa ju epo igi-nla di e sinu omi yen ki e gba omi yen si ibi ti o tile ri sanmo lati aro yen di ale. ki e wa ra AJAPE eran oruko, ki e ko sinu awo-abokadale, ki e bu epo pupa si lori, ki e wa se adura si wipe Oso lo ba fe bayin ja ni, aje lo ba fe ba yin ja ni gbogbo ajogun kajogun to ba fe koju ija si yin lati de yin mole lona kan tabi lona miran, odidi eran ni e ti pa fun won yi, ki won jowo ki won yonda yin. eo ti wa efun ati osun sile, eo lo papo, eo fi omi di e po, eo wa fi pa ese yin lati orunkun da atelese, eo wa lo gbe ipese yi si orita-meta lale ti gbogbo eniyan ba wole sun tan. pi pada ti e ba pada wo inu ile ni eo wa fi omi ti e ti gbo ewe-ajabo ninu re yen sin gbogbo ara yin ti eo si wole sun.

NB; Ti ile ba mo laro ojo-keji, e gbiyanju lati se saara fun afoju meje.

Pelu ogo-olohun, eo si ja Ajabo ninu odun yi, e ki yio ri ohun ti yio da yin gunle tabi ogun atimo(do do mi). Ase!
ESE pupo

1 Like

Culture / Re: .. by ademotech: 12:53pm On Jan 06, 2017
Ifankaleluya:

Hnmmmmmmm.........!

Baba, emi o mo bi a ti n tan(deceives) ni. Ala ti e la ko dara rara. Iseda yin o ni gba abode pelu ogo-olohun......Amin! N o ni so ju bayen lo.....!
ejor kini molese
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ademotech: 8:28pm On Jan 05, 2017
08101646045atwp:
Bi otile je wipe:- nti okoju si enikan, eyin lokoju si fun elomiran!
Sugbon gege bi eti la alayi!
Eyi ntumon bai wipe:- tobaje wipe awon Ti oyi yin kayi baje aon Ti edamon eyin tumon si wipe bi iku Ile koba pani tode kii pani
Ti osi nsalaye bai wipe olowo kan laarin otosi otosi Ni gbogbo won, Ni odunyi aseyori wa ninu afoju sun yin yen daada!
Sugbon enilati se imule ati ebe awon agba Ti ma nje Ki omo'osowo Lai jere!
Nitori wipe Oni sowo Ti Ko se ase jere ifa ohere meki wipe eran awon Iya Ni nse!
Nitori na esun Mon awon agba daada.
Ekoni ri ija kule'o
ejor imule ati ebe awon agba wo ni mo lese
Culture / Re: .. by ademotech: 7:52pm On Jan 05, 2017

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ademotech: 6:11pm On Jan 05, 2017
08101646045atwp:
Bi otile je wipe:- nti okoju si enikan, eyin lokoju si fun elomiran!
Sugbon gege bi eti la alayi!
Eyi ntumon bai wipe:- tobaje wipe awon Ti oyi yin kayi baje aon Ti edamon eyin tumon si wipe bi iku Ile koba pani tode kii pani
Ti osi nsalaye bai wipe olowo kan laarin otosi otosi Ni gbogbo won, Ni odunyi aseyori wa ninu afoju sun yin yen daada!
Sugbon enilati se imule ati ebe awon agba Ti ma nje Ki omo'osowo Lai jere!
Nitori wipe Oni sowo Ti Ko se ase jere ifa ohere meki wipe eran awon Iya Ni nse!
Nitori na esun Mon awon agba daada.
Ekoni ri ija kule'o
esee baba IMO yin amalekun pelu ase oluwa
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ademotech: 6:45pm On Jan 03, 2017
baba ejor ebami tunmo ala MI ,,mo LA ala pe mo joko ti owo (money) to PO ni gbangba ti eyan PO ti wan yi MI ka ti wan SI WO mi
Culture / Re: .. by ademotech: 6:42pm On Jan 03, 2017
Ifankaleluya:

IFA ILAYA OLODI-MEJI

1. Yangi Oju-ona

2. Ikujebu

3. Eresile ewe-idi

4. Yangi esu

Ao lo papo, ao wa te ni odu-ifa odi-meji.

ifa re; Olukimolaya, ayamudindi kimolaya, ayamu didi ni ti kujebu, ayamu didi ni tesu, yangi oju-ona kiije ji aya ona o ja, ewe-idi ni ko di emi lagbaja omo lagbaja laya. odi-meji iwo ni ko di emi lagbaja omo lagbaja laya. eewo ni, aya esu liija nigba kookan. ao ma fi fo eko tutu mu.

Aboru, Aboye, Abo-sise.
. baba ejor ebami tunmo ala MI ,,mo LA ala pe mo joko ti owo (money) to PO ni gbangba ti eyan PO ti wan yi MI ka ti wan SI WO mi

1 Like

Culture / Re: .. by ademotech: 6:41pm On Jan 03, 2017
baba ejor ebami tunmo ala MI ,,mo LA ala pe mo joko ti owo (money) to PO ni gbangba ti eyan PO ti wan yi MI ka ti wan SI WO mi
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ademotech: 6:34pm On Jan 03, 2017
baba ejor ebami tunmo ala MI ,,mo LA ala pe mo joko ti owo (money) to PO ni gbangba ti eyan PO ti wan yi MI ka ti wan SI WO mi
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ademotech: 5:30pm On Aug 15, 2016
kadunasouth:
Aseje Owo (money)
Abo adie alawo meta(3 color) ao pa ao ge kekeke si ona to ba wuwa, iru iyere ata ijosi ewe ologosese ao gun gbogbo re ao fi se adie yi lepo niyo
To ba tutu ao fi iyere osun te ifa eji ogbe ao pe ofore si ao dasi ao koje
Arin igi oko lo longosese nti de ade tie gbogbo ibi ti month badurosi ni kiwan ti ma de mi ni ade owo nla nla, eji ogbe baba ifa wa gbe alanu temi komi nibi ti mobaduro si Ase
ejor baba se ise yi koni ewo abi ipalara ni ojo iwaju
Business / Re: Bankers For Baba-Ijebu (Premier-Lotto). by ademotech: 1:53pm On Aug 11, 2016
diamond 63 64 62 83 84 46)) (83 46 64)
Business / Re: Bankers For Baba-Ijebu (Premier-Lotto). by ademotech: 12:00pm On Aug 11, 2016
international have addion 100 is it going to play
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ademotech: 11:37am On Jul 30, 2016
kadunasouth:

Beeni ese pupo fun ekunrere alaye
baba se ale se iseyi le ra wan, ati pe se ko SI ewu ni bee
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ademotech: 6:26pm On Jul 29, 2016
kadunasouth:

Leda tan fi di iyo(salt) tabi sugar eo ra tuntun inure leo fo eyinsi ati ero nja yoku tema fise
ejor sir IBO Latin le ri Leda naa ra
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ademotech: 6:25pm On Jul 29, 2016
cashkid:

Baba e dakun se pelu ewe sawerepepe ati ata ijosi ti a ti lo yi ni a o ko si nu leda ati eyin agric ni?
ejor Ibo lati le rira
Culture / Re: Ogun Awon Bàba Wa by ademotech: 5:30pm On May 23, 2016
alexdan1881:
Oogun Eyonu to daju
Eyin adiye sise kan, iyo die.aa da iyo yen sinu plate ,waa te Odu iwori meji si,waa fi eyin adiye naa lee Lori, waa gbe sinu orun di 12pm,waa lo gbe kuro ninu orun by 12pm,waa Bo ara e si ihoho ,waa gbadura,waa Bo eyin naa wa fi kan iyo naa,waa je eyin naa lodidi. Waa da iyo naa sinu omi fun wiwe.

Ejor se 12pm si 12am Ni abi 12pm to 12pm
ejor sir se lati 12pm so 12pm ni
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ademotech: 6:12pm On May 20, 2016
kadunasouth:
ASINA ATUDE
Ewe ewuro ojo, epo obo, eru alamo ao gun papo oronro malu lama fi po ose yi omin kogbodo kan ao ko sinu roba fun fun ao wa so ori niwan ba si ao gbe sinu orun toba yo ao tun po papo ma ose yi taba tipo tan idire ko gbodo kanle mon ao ma fiwe ni ojo merin larin ose sunday monday tuesday thusday ti aba lo ose yi yato si awan ojo wonyi koni sise mon, taba si fe se ose yi arin ojo mererin yi lalese tabase yato si ojo mererin yi koni sise odaju
ejor sir awure oni gbe e malu see opoo eyan le lo use yii
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ademotech: 3:13am On May 15, 2016
molala pe mo ru irin mosi so kale SI ebute ejor kini itunmo re
Culture / Re: .. by ademotech: 2:55am On May 15, 2016
eejo molala pe moru irin mosi sokale SI ebute kini itun mo re

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 30
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.