₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,324,984 members, 8,419,824 topics. Date: Thursday, 04 June 2026 at 12:11 AM

Toggle theme

Admolfemx's Posts

Nairaland ForumAdmolfemx's ProfileAdmolfemx's Posts

1 (of 1 pages)

HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by admolfemx(m): 10:20pm On Feb 28, 2016
kadunasouth:
Ewe na oloruko meji rekureku kifa kokoja ona
Ewe na common lodo awan elewe omo eko sinu pepa ewe rekureku ki efun wan, wan ofun yin
Baba kadunasouth e kale o,olorun yio ma wa pelu yin o amin.ibere mi ni wipe e jo bawo ni mo se lewo akosejaye eni ati pe iru igbese wo ni mole gbe lati wo,ejo eran mi lowo fun ibere mi yii,e se pupo.
CultureRe: .. by admolfemx(m): 10:57am On Feb 14, 2016
janle:
[FUN ANFANI ENI TON WA AYETA TO DAJU] ewe efirin, osedudu bi oni.[100]naira pelu oju olongbo kopo die. Ao gun ewe yi mo osedudu yi, ao te oju olongbo yi si lara. Ao ma fi we. Pelu kaninkan adayeba. Osi tun sise fun ada. Ao bu die sinu oti schnapes. Sugbon oni eewo o. Aye mo juba o.
E jo baba se pelu oju olongbo towa lara ose ye ni a maa fi oti lo,ekeji kini ewo re sir,e se pupo.
CultureRe: Ogun Awon Bàba Wa by admolfemx(m): 8:44am On Feb 14, 2016
ayokomi1010:
OGUN IWOSAN AYE
ewe ela,ewe alupayida odidi atare kan, ao jo po ao da sinu omori isaasun ao wa ko oruka irin si,ao wa da epo pupa si ao ro po, ao wa fa Ogun yan si enu akuko adie,ni emeta,ao ma fi oruka ni si lenu ni okokan yio ma gbemi,ti o bawa di OJO keje ao pa adie na,ao lainure ao Ba awon oruka na,ao ko ao ma fun eniti Asian ba nse yio fi bowo re,aisan re yio San ni OJO na ase eledunmare ni,iba eyin agba o aiye mojuba o,mowole mo pa igbunmo o,mofori bale fun gbogbo ajunilo.
Baba kie pe funwa ho, akoko iberemi niwipe ki ara alaisan na batiya tan se alegba orukana kuro lowore,elekeji adiye ohun se aleje abi ama junu ni, iberemi keta nipe e jo baba iru ogun woni alelo fun inurirun,tabi ki inu makanyan tabi ki inu eniyan ma gbona fun okunrin,e se pupo sir.
CultureRe: .. by admolfemx(m): 1:03pm On Jan 25, 2016
healthFirst:
27 OGUN TI OWU ALANTAKUN BA N KO ENIYAN LARA
Oku opolo kan ao ki igi bo lati enu ti yoo wole dada ti yoo ha mon ninu dada ao wa mun ao ma fi ko gbogbo jankariwo inu ile titi afi ni leri ara opolo yen mo ti aba ti se bayen tan ao gbodo fi owo kan mon, ao fi ada ge igi yen mo ao wa fi igi gbe sinu agbada ao jo pelu odidi atare kan sugbon ako gbodo fi owo kan ti oba ti jo tan na... ao wa lo epo obo ti yio kuna daada bi atike, ao wa da mo igba yen ni a to le fowo kan.

E joo e je ki ayika wa je mimo...awon kan wa to je wipe nitori idoti ayika won po ni Alantakun se ma n ta okun si ibi ti won n gba ti won le so wipe ise aye ni. Sugbon bi o ba je aarin igboro ni owu alantakun ti ma n ko wa lara nigba gbogbo, Oogun re to daju ni eleyi.
E jo baba iberemi akoko nipe se ko ba tutu ni aato mada epo obo lilo ye sinu e,elekeji bawo ni a se maa lo sir.
CultureRe: .. by admolfemx(m): 10:14pm On Jan 24, 2016
[quote author=Rosebiz post=42080406][/quote]E jo baba,bawo ni ase malo ogun yii sir
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by admolfemx(m): 11:42am On Dec 26, 2015
kadunasouth:
Ogun fun Oniwa npale ati omuti ati iwakiwa ti afe kiwan fi iwa na sile
Akara ori atan pelu odidi atare kan ao jo ao lo yio kuna ao wa lo sugar onikoro 7/9 meje fun okunrin, mesan fun obinrin yio ma la koto ba eniyan soro laro kutu, gbogbo iwa ti kodara leni na yio kosile
E jo baba kadunasouth, se akara dindin ti won da sori akitan ni e nso nipare ni baba, e se pupo sir.
CultureRe: .. by admolfemx(m): 8:38am On Dec 25, 2015
healthFirst:
Eyi ni lati kede si gbogbo Omo Oodua nile loko, lona Oja fun atejade Iwe 'Iwulo Ewe Ati Egbo' ti yio jade laipe. A gbe igbese yi lati ri wipe awon imon ijinle Baba wa ko parun, Yoruba bo, won ni A kii Juba Agboogun lo Orun' Gbogbo Omo Oodua to ba nife si Iwe yi ki o kan si wa lori e-mail tabi whatsapp eyi ti ero ibanisoro re wa loju iwe kini ikani yi.

Iwe na yio je atejade nipa awon Oogun Iwosan fun orisirisi arun ti o wa ninu ago ara wa ati eyi ti o n ja wa logun nipa ti emi. Iwe na yio ni awon oogun Akoya lorisirisi ati awon Oogun tii so omokunrin di ojulowo okunrin. Iwe aabo lowo ewu kewu. Mo gba yin niyanju ki e ni ipin ninu iwe Iwulo Ewe Ati Egbo fun itusile, igbega ati ohun amu sagbara gegebi omo Oodua.
E jo baba healthfirst, elo ni iwe na fun tita mean(price of the book) ati pe nibo ni a ti le rira, ni ipinle osun state, e se pupo.[color=#006600][quote author=healthFirst post=41238894]Eyi ni lati kede si gbogbo Omo Oodua nile loko, lona Oja fun atejade
Nairaland GeneralRe: What Is Wrong With This Christmas Tree? (picture) by admolfemx(m): 8:24am On Dec 25, 2015
scholes0:
A drunkard's christmas!
smiley
Kilo tunmo si e jo sir
PhonesRe: 7 Ways To Protect Your Phone From Been Hacked. by admolfemx(m): 8:39pm On Dec 23, 2015
Thank you 4d infrm you give us

1 (of 1 pages)