AkoduAkeem's Posts
Nairaland Forum › AkoduAkeem's Profile › AkoduAkeem's Posts
1 (of 1 pages)
OJULOWO EWE ATI EGBO FUN ARA RIRO,AWOKA ATI LAKUREGBE 1) Ororo to n jade lati ara ewe ati itakun (stem) ara igi tomato.A o ma fi wo/ pa(rub)awon ibi to n ro wa. 2)A o lo awon nkan wonyii kuna aloe vera,ginger ( eni ba ni aisan ogbe inu/ ulcer ko lo ginger ni iwonba tabi ko ma lo rara) ayu(garlic),kanafuru (clove).A o se bi ogi A o tun lo kanafuru ogun miran mo iyi ta ti se.yii A o fi sile fun wakati marun si meje. A o ma mu ife( cup) kekere kan laaro ati lale 3) Sise epo ahun ni mimu 4)A o wa egbo sapo ati egbo aidan A o maa mu ilaji ife kan laaro ati lale. 5)Sise epo ori ope oyinbo(pineapple) bi tea. 6) A o ge ayu tabi alubosa tabi ewe bomubomu si wewe, a o to won si atelese, ao wo ibose wa (socks) le lori di aaro ojo keji. 7) Ki a fi awon ororo bi olive oil (eyi ti won ko extra virgin) si lara lo dara ju, tabi adi agbon, tabi black seeds oil.Ki a fi pa awon oke ese wa ati atelese wa daada ati awon ibi to n ro wa nigbogbo igba, agaga ki a to sun lale 7)Ewe osepotu to po die, a o lo alubosa nla meta mo ,A o se daada lori ina.A o maa mu ife kan leemeji lojumo AKIYESI PATAKI A.le lo awon ti a o fi para pelu awon ti ao fi sinu ibose Sun pelu okan ninu eyikeyi awon ti a daruko wonyi. Egbo sapo ati egbo aidan dara gan fun enikeni ti aisan sangunsangun tabi awoka ti wo lara gan Ki a lo eyikeyi ti a ba ri ninu awon.nkan wonyi titi alaafia ma fi pade de sara wa .Ki a ma se lo gbogbo won papo lekan naa. Olohun Oba a lo won lati da alaafia pada si ara wa.Amin |
I like this |
1 (of 1 pages)