₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,325,252 members, 8,420,983 topics. Date: Friday, 05 June 2026 at 03:51 PM

Toggle theme

Ayanfe15's Posts

Nairaland ForumAyanfe15's ProfileAyanfe15's Posts

1 2 3 (of 3 pages)

Nairaland GeneralRe: Reviewing Dagrin~democracy Song by ayanfe15(op): 12:38am On May 12, 2016
Chorus: Shey democracy leleyii abi crazy demo? Oluwa shaanu wa dakun ma ma je ka jego. Ba'a laju awon ijoba ko to di quarter-to. Mo de pariwo titi fun yin 'pe kee ma dibo. Se democracy l'eleyi abi crazy demo? Oluwa s'aanu wa dakun ma ma je k'a je'go. Ba wa laju awon ijoba ko to di quarter-to. Mo de pariwo titi fun yin wipe k'e ma d'ibo.
Nairaland GeneralRe: Reviewing Dagrin~democracy Song by ayanfe15(op): 12:38am On May 12, 2016
E'e san owo awon osise, ranti pe awon naa
l'omo n'le.
Awa l'a ni petrol, ki lo de ti petrol 'o flow?
E n gb'owo le e l'ojoojumo, ki lo se yin o?
Ti Olorun ba binu, gbogbo yin ni petrol maa
jo. Se democracy alagbada l'eleyii tabi shimi?
E ranti 'pe most people l'o te'ka fun yin
A'a le ra Maclean(s), pako l'a maa fi n fo
eyin
Ki lo se yin? Eeyan sha l'awon Bill Clinton. O'o le ji l'ojo kan, ki o so 'pe o fe je iyan.
Lai se ojo Sunday. Garri nikan gan an ti
won.
Alagbara l'eni ti o ba ra rice De Rica kan.
O pay mi ki n kuro ni Nigeria, ki n sa lo si
Abidjan.
Nairaland GeneralRe: Reviewing Dagrin~democracy Song by ayanfe15(op): 12:37am On May 12, 2016
3.
Awon eeyan maa n ni Nigeria, Giant of
Africa,
Lo wo bi economy won se better ni South
Africa.
Ghana celebrate ten years ti won ti ni ina, ti won o tan atupa.
Ti tiyin e'e mo ju ki e s'oge, ki e tun wo
agbada. Igba kan ni won maa n ko awon were l'oju
titi,
awon were maa n rin kiri pelu awon eeyan
gidi.
Ni isinyin, awon were, won o l'identity -
Local Government kan, o le pade were fifty. Ki lo de? Awon olowo nikan lo n s'oge.
Awon omo yin, pelu awon iyawo nyin, won n
gbe gele.
E n gbe fila. Democracy alagbada.
O ga o. Owo gbogbo wa l'e fin n yi ata. National ID Card, owo l'a fi n register.
A o ri nnkan kan. E da passport wa pada.
E n waste time omode pelu agbalagba.
E se o. E ranti 'pe Olorun wa.
Igba ti a gbo National ID Card, inu wa dun.
Asee won n d'ogbon, won fe ki Oba wole. Oba ti wole, agidi l'a fi n san'wo ile.
School ma n strike, ohun yen, se iyen la fe
pe ni holiday?
Nairaland GeneralRe: Reviewing Dagrin~democracy Song by ayanfe15(op): 12:36am On May 12, 2016
Chorus: Shey democracy leleyii abi crazy demo? Oluwa shaanu wa dakun ma ma je ka jego. Ba'a laju awon ijoba ko to di quarter-to. Mo de pariwo titi fun yin 'pe kee ma dibo. Se democracy l'eleyi abi crazy demo? Oluwa s'aanu wa dakun ma ma je k'a je'go. Ba wa laju awon ijoba ko to di quarter-to. Mo de pariwo titi fun yin wipe k'e ma d'ibo.
Nairaland GeneralRe: Reviewing Dagrin~democracy Song by ayanfe15(op): 12:35am On May 12, 2016
E'e ri bi titi won pelu economy won se ri?
Eyin kan n lo si be, e kan lo n se faaji! Gbogbo nnkan l'awon ijoba yii fi ni wa l'ara.
Ko de ri bee nigba ti a koko gba ominira.
But nigba ti awon Big Bros ti take over,
Gbogbo owo wa patapata ni won fi n da
agbada. Nigeria, gbogbo wa l'a n fi ori f'aya
A t'omode a t'agbalaba, pelu t'oko t'aya,
Baba, mama, pelu awon omo mefa ma sun si
inu yara
eyo kan. Bawo ni won o se ni maa l'alakala?
Nairaland GeneralRe: Reviewing Dagrin~democracy Song by ayanfe15(op): 12:35am On May 12, 2016
2.
Awon eeyan n sise, won n gbe ninu ise,
Awon elo mii, nitori owo, won ti gb'ese.
Awon elomii n gb'owo ni ita, nitori won le ju
ese,
Nigba to je awon ijoba gan an, won o p'ese ise. Wo'a lo si university, wa se tan, waa gba
pali,
Pelu pali re, wa tun maa wa'se ka kaakiri,
Gbogbo ibi ti o ba lo, won a ni kosi
vacancies.
Gbogbo kini yen, o maa ma fun e ni headache. Awon elomii n jale tori ko si ise ni igboro.
Economically, most obinrin ti di ashewo.
O ga o! Ko de 'n se ejo elomii ti e ba ro o.
Sugbon aso yellow ti di white, l'owo o lilo. Ijoba, e wa na. (clears throat). E duro na.
O ga o. Eekan l'osu l'a ma n ni ina.
O n happen all over Nigeria, pelu Kaduna,
Minna, gbogbo yin ti e ba ilu je l'e maa
gb'ina. Aimoye titi ti o je'pe moto o le gba 'be.
Lo si under bridge l'Oshodi, gbogbo ibe ti
baje.
Ti ojo ba ro, gbogbo ibe yen maa di
kpenshen-kpenshen.
Ti o ba ya, a si maa gbe oko oju omi koja ni be. Gbogbo promise ti e make, iro l'o wa n' be
Sebi eyin naa, e ma n travel lo si Yankee.
Nairaland GeneralRe: Reviewing Dagrin~democracy Song by ayanfe15(op): 12:34am On May 12, 2016
Chorus: Shey democracy leleyii abi crazy demo? Oluwa shaanu wa dakun ma ma je ka jego. Ba'a laju awon ijoba ko to di quarter-to. Mo de pariwo titi fun yin 'pe kee ma dibo. Se democracy l'eleyi abi crazy demo? Oluwa s'aanu wa dakun ma ma je k'a je'go. Ba wa laju awon ijoba ko to di quarter-to. Mo de pariwo titi fun yin wipe k'e ma d'ibo.
Nairaland GeneralRe: Reviewing Dagrin~democracy Song by ayanfe15(op): 12:33am On May 12, 2016
1.
Nigeria ni mo ti ri t'olopa ma n toro bara
Nitori twenty naira won le fi ba e faa ya!
Agbero maa n f'agidi gba Gala lowo driver
E'e ri nnkan kan se si, eyin ijoba e n kaalara Gbogbo owo ti e ti gbe mi l'awon omo omo
yin maa bi
E'e ri bi awon ara ilu se n pariwo: Ebi!
T'oba ri life ti talika n live ni Birnin Kebbi
Gbogbo yin patapata ni Olorun maa da l'ebi. A'a ran omo lo si school, ko ni si textbook
E de promise pe e maa fun wa ni free
education
Ki l'on je bee? Owo nla ma l'a fi n
s'admission.
E de ti ko gbogbo awon omo ti yin kuro ninu nation. A ti igba ti mo ti n ko'rin, mi o ni money
E'e tie ki n soro rara nipa music industry
Economically, agidi l'a fi n ra bread
Ta lo so wipe President o ki n fine ninu telly? E'e mo ju ki e so'ro petrol, pelu football
A ti igba ti a de ti n gba World Cup, a'a gba
cup.
O ga o! Boya gan an l'atie gba second.
Awon yen naa, won a maa play ball bi
alakan. Graduate maa maa wa'se, gbogbo bata e a
je,
a'a ye s'egbe, everywhere ko si
employment,
Eni ti o ti n kole tele, ko le ra cement,
Increase ni rent, decrease ni salary payment.
Nairaland GeneralReviewing Dagrin~democracy Song by ayanfe15(op): 12:33am On May 12, 2016
Intro: Corruption ti hit nation Gbogbo wa la n live in desperation Tori 'e n'mo se n drink medication Fun protection against starvation pelu corruption Tori generation yii, a need salvation Through a strong constitution Ninu studio, owo naa l'afi n book session E joo e stop sensation A need action ko n se prosecution Free/Fair pelu alaafia ninu nation E gbo nnkan ti mo fe so eleyii 'o nse body vibration (Clear throat)
PoliticsRe: NLC To Resist Fuel Subsidy Removal And Increase In Petrol Price by ayanfe15(m): 12:22am On May 12, 2016
abeg, where my ghanamustgo, who carryam.
PoliticsRe: List Of Salaries Earned By World Leaders by ayanfe15(m): 12:14am On May 12, 2016
hmmm
PhonesHelp Me Out~tecno R7 by ayanfe15(op): 7:45pm On May 07, 2016
My phone TECNO R7(andriod), if i want to rename record file, the file do corrupt.
PoliticsRe: Every Child In Kaduna MUST Go To School - El-rufai by ayanfe15(m): 7:47am On May 07, 2016
education is the best legacy every child can have~

1 2 3 (of 3 pages)