absoluteSuccess: To God be the glory,
Yoruba d'araba t'apa ota ko ka,
Adi apaadi feregede tii siwaju onifonna.
Adi eye odidere, tii ye igi gbogbo loko.
Odoniran Iran, Iran baba wa nii j'oba.
Oriwa nii d'ade owo,
Orun wa asi maa w'ejigbara ileke.
Arawa a maa wo mosaaji,
Aso oba tii kanna yanranyanran.
Mosumo'ba ni'won egbeje,
Mo jina s'oba ni'won egbefa.
Obafemi ni'won egberindinlogun,
Aroba fin l'oba pa. Iwo gagan la ba ma peni omo odua ilu yi a gbe gbo gbo wa  absoluteSuccess: To God be the glory,
Yoruba d'araba t'apa ota ko ka,
Adi apaadi feregede tii siwaju onifonna.
Adi eye odidere, tii ye igi gbogbo loko.
Odoniran Iran, Iran baba wa nii j'oba.
Oriwa nii d'ade owo,
Orun wa asi maa w'ejigbara ileke.
Arawa a maa wo mosaaji,
Aso oba tii kanna yanranyanran.
Mosumo'ba ni'won egbeje,
Mo jina s'oba ni'won egbefa.
Obafemi ni'won egberindinlogun,
Aroba fin l'oba pa. Iwo gagan la ba ma peni omo odua ilu yi a gbe gbo gbo wa |