₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,326,496 members, 8,426,814 topics. Date: Sunday, 14 June 2026 at 11:15 PM

Toggle theme

Ewaraike's Posts

Nairaland ForumEwaraike's ProfileEwaraike's Posts

1 (of 1 pages)

PoliticsRe: PDP Sacks 50 Percent Of National Secretariat Workers by ewaraike(f): 7:31am On Mar 07, 2020
Ki lo kan mi ti aye PDP babaje
Ko si nkan to kan mi ti aye APC gan ba dojuru, wahala ti gbogbo won niyen.
Sebi won joun pin oogun Nigeria larin ara won ni.
Ki olorun gbe mi de ibi giga ninu Ijoba
Ki olorun si fi awon eniyan gidi ti mi ti ama jo tun orile ede yii se
Lobatan
TravelRe: Keke, Okada Back On Lagos Roads, One Month After Ban by ewaraike(f): 7:22am On Mar 07, 2020
Rythm���
Alakara Oni moin moin
Alamala Oni guguru
Night ti ko ta logbegba kale
E wa wo ija ni lafiaji
Mama mi ti so fun mi teletele wipe
EKO AKETE, ILU OGBON
TOBA DURO KOSORA ONIYANGI
EKO O GBA GBERE
EKO O GBA GBERE RARA O
HealthRe: Coronavirus: Research Reveals Where It Lingers, How To Kill It by ewaraike(f): 2:37pm On Mar 05, 2020
ARUN ti ko gbo oogun oloun maje ko mu emi ati ebi mi.
Maje won o pe okiki aburu Lori mi
Dakun maje n ku iku ojiji

1 (of 1 pages)