Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,416 members, 7,815,937 topics. Date: Thursday, 02 May 2024 at 09:29 PM

IBAAGBA1's Posts

Nairaland Forum / IBAAGBA1's Profile / IBAAGBA1's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by IBAAGBA1: 4:39pm On Jun 02, 2017
Wolad:


Ewe Agogo-igun, Eso Iwerejeje (oju ologbo), ako kanhun, ao gun po sinu OTI, mimu...
E se pupo,mo dupe ooo,lagbara Olorun ao ni wa gbogbo eyin agbagba wonyi ti AMIN ASE!!!

1 Like

Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by IBAAGBA1: 1:01pm On Apr 26, 2017
08101646045atwp:
[img][/img]

OGUN IDI YIYO TABI IGBE EJE
A o Jo agbarin pelu odidi atare kan,a o da sinu adin eyan a o gun papo Dada a o ma fi mu eko gbigbon ni sibi meji meji.

IDI YIYO Aopo capsule red&yellow mefa mo sibi oyin meji, aoro po, aoma fipa idi tio yo lemeji fun ojo merin




E se mo dupe sir,awon to laye o ni kohun siyin lenu ASE
E jowo se red and yellow capsule lefe ko ni tabi bawo sir.
Culture / Re: .. by IBAAGBA1: 12:51pm On Apr 26, 2017
E jowo e fun mi ni ogun ti idi eniyan ba nyo jade to ba nyagbe
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by IBAAGBA1: 6:33pm On Apr 24, 2017
E ku ise takuntakun,e jowo eyin agbagba e fun mi ni ogun idi yiyo to daju tori o ti pe lara,e se.
Culture / Re: .. by IBAAGBA1: 5:06pm On Apr 24, 2017
E jowo mo need ogun orobo to nyo nidi,o siti pe lara bakanna,e jowo e sanu mi
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by IBAAGBA1: 5:33pm On Apr 17, 2017
bukkylove:
Atude/Asina/Apa Asasi
Iru pete ao gun po mon ose dudu tale we lekan soso to badi ni idaji kutu ao to sibikan ao fi ose sinu kehin kehin tun tun ao wa ma kibo inu ito yi ao fiwe gbogbo arawa ao wa fi opolopo omin sin arawa iseyi dara gbo gbo asasi aifojuri ni yio ba omilo ao ju kehi kehin yi sori atan nio




Baba ejowo se kankan Hausa ni o lo abi ale lo kankan to ba wu wa.


Baba mi agbalagba yo ma ju yin se o ase,e jowo ti koba si akitan nitosi eniyan,se a le dana sun kaninkanin na,e se
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by IBAAGBA1: 2:05pm On Feb 28, 2017
kadunasouth:
Turare Jalabi, Itaja, Afa orewole Odara Fun Onile ati Onirin Ajo
Ori Agiliti, ori aparo, ori musu eyi toni irun, Ewe ajade, eru alamo, koro owu kopo die, oyin bi sibi meji ao gun gbogbo re sakasaka ao mafi lararo Danwo oje bi idan

E jowo sir baba ewe wo ni ewe ajade,e se pupo sir a ma juyin se o
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by IBAAGBA1: 10:28pm On Feb 26, 2017
kadunasouth:
OGUN AWURE TI NSI ONA TIPATIPA
odindi alangba ako gbigbe kan,ewe firiganmu,girija ti ko lomo ninu ,imi orun-(imi ojo) ao gun gbogbo re po,aofi ase joo dada ,igbati aba joo tan ,ao gbon eyi ti oba kunna yen ao po mo ose dudu,sawasawa toku ni ,ao fi ma fi turari ni ale ojo monday ,ao ma we ose yen ni ojo monday ati alamisi ,ao ma sope ki ona si fun mi lona kona o tan.
E jowo sir,ewe wo ni won npe ni ewe firiganmu,atipe kilo nje girija ti o lomo ninu,e se sir

3 Likes

Culture / Re: .. by IBAAGBA1: 12:52am On Feb 24, 2017
08101646045atwp:
OSOLE GBEWA PAJAWIRI
Omo yahoo na lelo daada kosi ewu
Ori kanakana 3, alangba 3 atare aja 3, pelu pelu biscuit okin ati opolopo ewe ola ao jo papo ao ma fi omi alujannu lo ebu na.........

N.B:- owo Ni afi ma nlo ebu na'o
Iru owo ewo Ni ao maafi lo?

=****
Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045
OR
https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o


Iba re baba mi agbalagba,e jowo sir iru omi wo ni eyin agbalagba npe ni omi alujonnu,atipe iru owo wo la ma fi lo ebu yi,e se pupo sir.
Culture / Re: .. by IBAAGBA1: 12:37am On Feb 24, 2017
Iba Olorun,iba eniyan,iba esu lapa kan,kesu ma sewa ko ma se enikankan to sun mowa o.
Iba omode,iba agba,iba gbogbo onimimo to nfi imo won tu awon eniyan sile ninu ide aye.
Omode ni mo je,eyin agba onilakaye e dakun dabo e damimo omo to.
Lagbara Eledua a ma ju yin se o AMIN ASE EDUMARE.

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 14
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.