Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,904 members, 7,821,145 topics. Date: Wednesday, 08 May 2024 at 08:56 AM

.. - Culture (92) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1829562 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (89) (90) (91) (92) (93) (94) (95) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by akingbemi(m): 9:07am On May 21, 2017
Eseun
Re: .. by ifadamilola: 4:07pm On May 21, 2017
ejowo gbogbo ile moni lo Ogun ti obinrin ba fiyan sile tio si pada ni KIA KIA edakun esaanu Mi aboru aboye
Re: .. by ADABA25: 10:28pm On May 24, 2017
Lero70:

ejowo baba iru oga wo ni oga-oko?
Kinni iyato towa laarin oga ati alagemo? Eseepupo.
Baba, e Jo bawo ni eniyan se le mo boya Ogun dudu ba eladare sise?? E Jo number me ni eyi boya e le ba mi beere lowo IFA olokun asoro dayo, fun ibere ,e jowo I try Lati flash number yi ma si pe pade pelu ogo olorun....07060404998
Re: .. by Ifakorode: 3:28am On May 26, 2017
e jowo baba e fun wa ni ogun gbetugbetu
Re: .. by danjeze(m): 7:58am On May 28, 2017
Éjó kini eyàn lelo fun eniti nkàn ómö kunrin é o bà tobi?
Re: .. by shakuna(m): 5:58pm On May 28, 2017
Zaudi:
BABA OGUN IFERAN OBINRIN TI O DAJU TI O LE MUYE OBINRIN TI WON BA TI FOJU KO YAN....EMI NA NI OWO TI ODAMI LOJU DEBI PE TI WON BA FE FI OWO KAN YAN WON MAA YAGBE ore tobadaju jekin jan faani re
moni ogun iferan to damiloju
Re: .. by Obaf1(m): 11:35am On May 31, 2017
[/quote];;;;;;;;;;ejowo sir kini oruko ti a tun pe igi nla, i mean oruko miran fun IGI NLA. Ama juyin se oooh asee
Re: .. by Obaf1(m): 11:37am On May 31, 2017
KolaBELIEVE:
se ise yi kolewu ninu? Mo gbo pe nkan bayi ma n ni repercurssion
;;;;;;;;;ejo se emo oruko miran fun igi nla. Another name for IGI NLA plz
Re: .. by IBAAGBA1: 4:39pm On Jun 02, 2017
Wolad:


Ewe Agogo-igun, Eso Iwerejeje (oju ologbo), ako kanhun, ao gun po sinu OTI, mimu...
E se pupo,mo dupe ooo,lagbara Olorun ao ni wa gbogbo eyin agbagba wonyi ti AMIN ASE!!!

1 Like

Re: .. by Wolad(m): 1:46am On Jun 05, 2017
Obaf1:
;;;;;;;;;;ejowo sir kini oruko ti a tun pe igi nla, i mean oruko miran fun IGI NLA. Ama juyin se oooh asee

Asorin ni oruko miran fun Igi nla
Re: .. by Obaf1(m): 10:35am On Jun 05, 2017
Wolad:

Asorin ni oruko miran fun Igi nla
;;;;;;;;;;;;;;;thanks
Re: .. by Adewunmis(m): 2:13am On Jun 08, 2017
Baba lfa mo ki yin eku ifomoniyan se ajinde ara yio ma je yin o ejowo mo fe ki e fun mi number WhatsApp yin mo ni oro to important lati ba yin so
Re: .. by Adewunmis(m): 2:23am On Jun 08, 2017
Ejowo Eko mi ise yi boya mari ise agba mi ko si ise kan kan lowo mi


Ose Ebe Awon Agba yi ni mo nlo lowo,
Apere ti mo ti ri so far ni wipe,
1. Awon olopa nle mi ni oju orun, mo si ri iya kan ni ojiji( sudenly) oni ki ntele owun wipe awon olopa(police) na ko le fi mi se nkan kan,
2. Awon omo iya mi ti won ti nbami ja lati ojo pipe nfi owo ranse simi wipe ki ebi o mo pami nitori ipe mio ni ise lowo(hand).
TESTEDD CONFITMED, Ifankaleluya iba re oo.[/quote]
Re: .. by Adewunmis(m): 2:47am On Jun 08, 2017
Ogun yi ope kilo de ti e fi oruko awon ewe
Yen si ti ba fe se anfani ki e se oluwa lo nsan esan fun ni OBINRIN MALE KO ENIA SILE

Iyimi yimi,
Ewe ...........
Iye igun,
Eyo Atare 7,

Aolopo
Ao fi sin gbere meta si iwaju ori.


Confirm![/quote]
Re: .. by Adewunmis(m): 2:52am On Jun 08, 2017
dominicson:


Ko si idani loju pe ti eniyan ba se ikan kan ninu Ogun eye kole sise biti ifankaleluya

Oworinmiki/owonrinirete/oworin-irete


Two-two-one-one at the first side, and one-one-two-one at the second side. But remember, odu ifa, just like arabic, starts from the right side.


So, two-two-one-one is at the right side, the first ese. And then one-one-two-one at the left side. Ese kan owonrin and ese kan irete is Owonrinmiki or Owonrinnirete.

Regards.

1 Like

Re: .. by realherb: 12:51am On Jun 11, 2017
Mo ki gbogbo Ile, ewe a maa je fun wa o. Eledua yoo maa fun wa se o. Iwaju lopa ebiti wa yoo maa resi lola alawurabi. E dakun e gbami kale, eniyan mi Kan loni aisan idi yiyo gbogbo agbo ati agunmu ti mo mo Pata ni moti lo fun ti ko si iyato. Laipe yi lowa salaye fun mi pe o tito bi odun marun to tin yo oun lenu. E dakun e fun mi ni oogun to daju ti mo tun le lo fun ki abiku re maa so oloogun mi deke. E seun modupe.
Re: .. by lambvard: 5:59pm On Jun 23, 2017


Ise yi ki se ise eyo kan...o si sowon pupo...e kan si mi lori e-mail...ao le fi ise yi sita lofe rara.
.
Re: .. by Midumighty(m): 11:09pm On Jul 02, 2017
shakuna:
moni ogun iferan to damiloju

motini iferan todaju lorisirisi.mo nilo re mo
Re: .. by Midumighty(m): 11:11pm On Jul 02, 2017
Obaf1:
;;;;;;;;;;ejowo sir kini oruko ti a tun pe igi nla, i mean oruko miran fun IGI NLA. Ama juyin se oooh asee
se ko si loja ni igi nla na ni wo pe.
Re: .. by Midumighty(m): 11:17pm On Jul 02, 2017
shakuna:
moni ogun iferan to damiloju


ogun owo/ibon todaju.mi koro agbalumo kan tio oba di ojo keta wa ya mo igbe,wa yo sita.ti o ba ni fe si te ate ranse sori numba yii.
Re: .. by Obaf1(m): 9:18am On Jul 03, 2017
Midumighty:
se ko si loja ni igi nla na ni wo pe.
, i don buy am thanks, bt plz can u give me iferan to sure and beat and run, plz i really need it
Re: .. by Obaf1(m): 9:24am On Jul 03, 2017
shakuna:
moni ogun iferan to damiloju


tiyin a da baba, motise ai moye ogun ti ko sise, o si je kin ma siye meji lori gbogbo ogun toku patapata, ejoor e funmi ni ogun iferan obinrin to daju lati clear dought me, nipa ogun ile karo o jire, ise se agbe wa oooh, asee
Re: .. by Obaf1(m): 9:32am On Jul 03, 2017
Adewunmis:
Ogun yi ope kilo de ti e fi oruko awon ewe
Yen si ti ba fe se anfani ki e se oluwa lo nsan esan fun ni OBINRIN MALE KO ENIA SILE

Iyimi yimi,
Ewe ...........
Iye igun,
Eyo Atare 7,

Aolopo
Ao fi sin gbere meta si iwaju ori.


Confirm!
ewe kinni baba ejoor mo need e gaaaaaannnnn ejooor sir
Re: .. by KolaBELIEVE: 7:59pm On Jul 04, 2017
kadunasouth:
Owo (respect)
OROGBO KAN EYO ATARE META AFOLA META
OJU OLOGBO META
Ao jo gbogbo re, ao maa la die die
Otun sise fun irin ajo
. baba Kaduna south ejowo monilo ose arisiki owo

1 Like

Re: .. by Oladimeji120(m): 8:06pm On Jul 04, 2017
Baba ejo efunmi ni isoye orin kiko todaju gan ejo baba oju konitiyin sir
Re: .. by Oladimeji120(m): 9:53pm On Jul 04, 2017
Ejo baba sebi ewe areyinkosun noni olosanku abi
Re: .. by mercysamuelson(m): 6:55am On Jul 05, 2017
KolaBELIEVE:
. baba Kaduna south ejowo monilo ose arisiki owo

@Kadunasouth: Baba, e jowo, Ki ni Afola?
Re: .. by Midumighty(m): 11:53am On Jul 05, 2017
mercysamuelson:
@Kadunasouth: Baba, e jowo, Ki ni Afola?
bere ni oja
Re: .. by Midumighty(m): 12:00pm On Jul 05, 2017
....Ogun iferan todaju fun enikeni...,awo ewure dudu,irun abe,ewe amunimuye,odidi atare kan,ekanna owo mewewa ati ti ese mewewa,irun ipenpeju die,irun ori die a o jo po a o fi sinu ounje fun eni naa.die ninu ebu yen ni o.
Re: .. by Midumighty(m): 12:06pm On Jul 05, 2017
tani o ni ogun'ibukun oluwa ni muni la'.ko jowo mo nilo re, eni tio ba ni ki so isori ogun ti o ba fe ma fun.eyiti odaju ni ma fun(tested ok)
Re: .. by ajobi1(m): 10:29am On Jul 06, 2017
@ kaduna south and others ejowo kini Ogun eje riru
Re: .. by Nobody: 10:12pm On Jul 12, 2017
kini itumo isuke! kii eeyan maasonu.. kini oogun e. o ti n se eeyan mikan lati ojo meta seyin........ ki ni a le lo.

e seun gan.

(1) (2) (3) ... (89) (90) (91) (92) (93) (94) (95) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 25
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.