KEHINDE633's Posts
Nairaland Forum › KEHINDE633's Profile › KEHINDE633's Posts
1 (of 1 pages)
fortune game is going |
fairchance is going on pls banker |
enugu banker ooo pl |
midweek is going now any body with banker |
anyone with VAG forecast please give me |
please any body give me banker vag |
OFORE. MAYEHUN YEN NIYI ogbo loni kiogbo mi. ogba loni kiogba. abamoda kan onida tie kio mase. ase ti okete baba ile so nigba ..iwo LXL oya se nukan bayi |
ifura logun agba |
MAYEHUN TODAJU awon okete meje. irudi okete meje. ewe ogbo. ewe ogba. ewe abamoda. atare odidi kan jijopo fisin gbere meta isale enu wa OFORE= |
[color=#990000][/color] OGUN MARAN OGUN oku elena mesan pelu eyo atare mesan ati oju olongbo mesan ao lo papo ao fisingbere mate meta si rikerke ara wa ..joint of body |
[color=#000099][/color]ejowo nilo ogun ada ati obe to confamd pls |
[color=#990000][/color]IBA saki loni oro. awo ijale loni epe. ijebu loni ase.ati oro saki ati awo ijale apa kankan otu kawa mo iyen madi eworisa..ayi ile aiye ka loruko tanpe aro. etu loruko tanpe osan. okuku birimu loruko tanpe oru. igba nla loruko tanpe aye.majedun loruko tanpe ile. ife omo jeje ki iku ma to e pami . ohun lo difa ile. eni gori ile oba gori eni ade go ri oba esinsin gori ade. esinsin to gori ade lojo kinin ano yen won dariji. Iya lode o iya lode o iya lode o .. otun. otunba. osi. gbogbo won dariji mi .kehinde. aro nimi mio lorukun ejo. aafin nimi mio lese eya go lona........COMING SOON MORE |
IBA EYIN IYA MI LORITA META ONA ARA EGBO OHUN MI LONI O ogbo loni kie gbohun loni, alupiada loni kie ma pahun mi da loni. ogba loni kie gba oro mi loni. abamoda kan oni da tie kio mase . gbogbo obirin ilu okunrin ilu egbo hun me sire loni |
Iba akoda aiye..iba aseda aiye,. iba agbagba merindinlogun lotu ife..iba oja tokun tio lero.iba obinrin arin ihoho woja..awon loni akiki odidi made kuro ju ano. ojo ti akerejupon ba fenu kanle ojo na ni kanlepa.ojo ti keregbe batenu bo omi ololo ni fohun....,... |
[color=#000099][/color] IBON TODAJU ewe ailu to po die pelu eyo owo (15) ati omi osan wewe ao gun pomo rawon ao da si inu omi osan yen ao ma mu die die.. |
[color=#000099][/color] MARAN..ADA,OBE,IBON .AIKE.AYETA..ATI FORI FOGO ...IS COMING SOON .........it me your boy kenny shitta.a.k.a senior kay. respect |
[center][/center][color=#000000][/color][color=#000099][/color] OFO OWO(RESPECT) ao ko atere mesan si enu ao ma pe ofo yi bayi pe...iwaju ori ohun ni gbayi lowo ori (3x) Atele ese ohun ni gbayi lowo ese (3x) aso funfun ohun ni gbayi lara oku (3x) emi lagbaja omo lagbaja gbogbo ibi to moba de loni kin gbayi ao tusi iwaju |
MARAN ADA obi lakiriboto kan pelu eyo atare mesan ao lo je lori igi ti ese wa ko ni kanle MARAN IBON ASASI ewe irosu kan ao fisi abe wa moju tio ba di ni ojo keji ao lo jo pelu odidi atare kan ao fi singbere yida inu wa ikun wa IBA AGBA ILU |
[color=#000099][/color] OGUN ANU obi ifin kan ao gesi 201, obi pupa kan ao gesi 201, eyo atare 201, ao fi omi amu po papo ao ro si inu ado ijamo kekere kan ao fi awo ijimere ran ao ma fisapo..ODAJU . |
[color=#000099][/color] GENERAL LOVE ewe amunimuye ewe alupaida, eyo atare meta ao jo po ao pomo ose dudu ao fimawe ...eniyan kan nioo |
OGUN IKORIRA ati ITUSILE Ao wa eyin ororo adie wa bora si ihoho omo luabi wa ma fi nu gbogbo arare pelu adua sise gbogbo isoro igbese ayere wase fun bi iseju marun wawa wo ewure pada walojusi ori akitan tabi orita meta tobati ju okogbodo soro siyan tabi koboju weyin toma fi wole re pada danwo okere sugbon olagbara pupo Adurawa yio gba o! |
[color=#000099][/color]
|
[color=#000099][/color] Iba akoda, iba aseda, iba omode ile, iba agba ile, iba oja to kun tio lero, iba |
1 (of 1 pages)