Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,446 members, 7,816,028 topics. Date: Thursday, 02 May 2024 at 11:57 PM

.. - Culture (13) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1828608 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (10) (11) (12) (13) (14) (15) (16) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by KEHINDE633(m): 10:26pm On Jul 03, 2015
[color=#000099][/color] GENERAL LOVE
ewe amunimuye ewe alupaida, eyo atare meta ao jo po ao pomo ose dudu ao fimawe ...eniyan kan nioo

1 Like

Re: .. by KEHINDE633(m): 10:32pm On Jul 03, 2015
[color=#000099][/color] OGUN ANU
obi ifin kan ao gesi 201, obi pupa kan ao gesi 201, eyo atare 201, ao fi omi amu po papo ao ro si inu ado ijamo kekere kan ao fi awo ijimere ran ao ma fisapo..ODAJU .

2 Likes

Re: .. by Nobody: 11:33pm On Jul 03, 2015
KEHINDE633:
OGUN IKORIRA ati ITUSILE Ao wa eyin ororo adie wa bora si ihoho omo luabi wa ma fi nu gbogbo arare pelu adua sise gbogbo isoro igbese ayere wase fun bi iseju marun wawa wo ewure pada walojusi ori akitan tabi orita meta tobati ju okogbodo soro siyan tabi koboju weyin toma fi wole re pada danwo okere sugbon olagbara pupo Adurawa yio gba o!

O kare omo odo agba....Oogun itusile to je bi idan ni sugbon lehin ti a ba fi nu ara pelu iwure tan, ao fi eyin na sinu apaadi kekere kan, ao bu epo ojeere le lori ao gbe sori aatan tabi orita meta...beeni, a kii wo ehin tabi ba eeyan kankan soro titi ao fi pada de ile.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 2:46am On Jul 04, 2015
x

1 Like 1 Share

Re: .. by avsnet: 8:49pm On Jul 04, 2015
healthFirst:
52
Ẹyọnu ṣe pataki pupọ ninu igbesi ayé ẹda tori ẹni ti aye ko yọnu si bi o ṣiṣẹ̀-ṣiṣẹ̀, a da gẹgẹ bi aimo ṣe, bi o sowo ko ni jere, bi o n wa isẹ ko ni ri..
Fun idi eyi, mo fẹ ki onikaluku wa gbiyanju lati se iṣẹ yi ki a si duni mọ lilo rẹ dada....

EYONU
Afara oyin ao fi si inu agbada, fi ikodẹ kan ha ẹyẹ Ẹga kan lẹnu ki o fi le lori, pẹlu atare odidi kan, ao pa epo ọbọ le lori ao ko ewé orijin pupọ,, Ewé ewédu pupọ le lori, ao jo. Ao lọ sugar (St. Loiuse) onikoro mo.

Lilorẹ... Ao ma fi oyin la, tabi ki a ma fi fọ ẹkọ tutù mu, tabi ki a ma fi Ọti lo, tabi epo pupa... Lalẹ, ati owurọ kutu.....
‪‎IBA AGBA‬.

('Inu agbada' (re mi mi) cloth wear or inu agbada (re re re) big earthen pot).

2 Likes

Re: .. by kadunasouth(m): 9:36am On Jul 05, 2015
£
Re: .. by kadunasouth(m): 1:56pm On Jul 05, 2015
OGUN ISOYE
Ewe akoko 16 ori akuko adie togbo dada odidi atare kan aojo ao ma fi oyin la

4 Likes 3 Shares

Re: .. by kadunasouth(m): 2:35pm On Jul 05, 2015
ISOYE TA NFI RANTI GBOGBO NKAN
Akuko to batobi dada ao tu iye abiya re ti apa otun ao lomo eyo atare meta tapa osi eyo atare meta ao fi tapa otun sin gbere meta si abiya otun tapa osi si abiya osi ti aba gbagbe nkan kan ao fi apa lu apawa lemeta bi adie pelu ofore ao ranti nkan nan lese kese odaju
OFORE
Bi adie bafi apalu apa pipi iyere aso 3times kin ranti nkan bayi bayi opari.
Fun ibere kansimi lori email mi

4 Likes 2 Shares

Re: .. by iahmed(m): 3:55pm On Jul 05, 2015
Ba ba o!
Edakun kini ema nipa ifa owo at pei kini awon ewo to so po mon ifa owo ni bibo
Re: .. by Nobody: 6:36pm On Jul 05, 2015
avsnet:


('Inu agbada' (re mi mi) cloth wear or inu agbada (re re re) big earthen pot).

earthen pot...ko je dandan ko tobi...iwonba ti a le fi jo Oogun na

2 Likes

Re: .. by Nobody: 6:43pm On Jul 05, 2015
x

3 Likes 2 Shares

Re: .. by KEHINDE633(m): 10:51pm On Jul 05, 2015
MARAN ADA
obi lakiriboto kan pelu eyo atare mesan ao lo je lori igi ti ese wa ko ni kanle

MARAN IBON ASASI
ewe irosu kan ao fisi abe wa moju tio ba di ni ojo keji ao lo jo pelu odidi atare kan ao fi singbere yida inu wa ikun wa
IBA AGBA ILU

1 Like

Re: .. by KEHINDE633(m): 11:00pm On Jul 05, 2015
[center][/center][/color][color=#000099] OFO OWO(RESPECT)
ao ko atere mesan si enu ao ma pe ofo yi bayi pe...iwaju ori ohun ni gbayi lowo ori (3x) Atele ese ohun ni gbayi lowo ese (3x) aso funfun ohun ni gbayi lara oku (3x) emi lagbaja omo lagbaja gbogbo ibi to moba de loni kin gbayi ao tusi iwaju

3 Likes

Re: .. by kadunasouth(m): 11:39pm On Jul 05, 2015
Ogun iyonu ati aranse
Koro owu akese topo eyin ororo ati atare ao jo ao lo kuna ao ma fi miliki olope lo die die

4 Likes 2 Shares

Re: .. by jades5050(m): 9:52am On Jul 06, 2015
Inu mi dun gan ni nigbati mo ba irufe eto yii pade. Ise takuntakun le nse oooo ewe a ma je egbo a ma je fun yin ni ase EDUMARE

1 Like

Re: .. by kadunasouth(m): 1:06am On Jul 07, 2015
jades5050:
Inu mi dun gan ni nigbati mo ba irufe eto yii pade. Ise takuntakun le nse oooo ewe a ma je egbo a ma je fun yin ni ase EDUMARE
Amin pupo
Re: .. by KEHINDE633(m): 2:02pm On Jul 07, 2015
[color=#000099][/color] MARAN..ADA,OBE,IBON .AIKE.AYETA..ATI FORI FOGO ...IS COMING SOON .........it me your boy kenny shitta.a.k.a senior kay. respect
Re: .. by Nobody: 5:08pm On Jul 07, 2015
Oju Okun ko ni buru
ki o mo lee fe ilele ilele
awalawulu oju orun
o ni wu koriko
awon lo difa fun olokun seniade
lojo ti gbogbo omi so pe
awon ko niba se mo
won ni ki o rubo
ki gbogbo awon ti won lawon
o ni ba se le maa ba se
won yan lebo o rubo
laipe laijina gbogbo awon omi
ti won lawon o ni base yi ohun pada
won wa nba olokun se
wo si fi joba won won teriba fun un
olokun seniade njo, o ni yo ooo
ni bee lawon babalawo to se fa fun oun wi
awon oju okun ko ni buru ki o mo lee fe ilele ilele
awalawulu oju orun ko ni wu koriko
awon lo difa fun Olokun Seniade
lojo gbogbo omi so pe
awon o niba se mo
nje e ba mi se loni atewe atagba
ewe asesere loni ki e ba mi se
eku olose loni ki e ba mi se
ogbo loni ki e maa gbo te mi
ewe apada loni ki e padi ire gbogbo da si odo mi loni
nitori ti moriwo ope ba yo a koju si Olodunmare
Atewe Atagba e maa ba mi se

5 Likes 1 Share

Re: .. by jades5050(m): 7:37pm On Jul 07, 2015
healthFirst:
Oju Okun ko ni buru
ki o mo lee fe ilele ilele
awalawulu oju orun
o ni wu koriko
awon lo difa fun olokun seniade
lojo ti gbogbo omi so pe
awon ko niba se mo
won ni ki o rubo
ki gbogbo awon ti won lawon
o ni ba se le maa ba se
won yan lebo o rubo
laipe laijina gbogbo awon omi
ti won lawon o ni base yi ohun pada
won wa nba olokun se
wo si fi joba won won teriba fun un
olokun seniade njo, o ni yo ooo
ni bee lawon babalawo to se fa fun oun wi
awon oju okun ko ni buru ki o mo lee fe ilele ilele
awalawulu oju orun ko ni wu koriko
awon lo difa fun Olokun Seniade
lojo gbogbo omi so pe
awon o niba se mo
nje e ba mi se loni atewe atagba
ewe asesere loni ki e ba mi se
eku olose loni ki e ba mi se
ogbo loni ki e maa gbo te mi
ewe apada loni ki e padi ire gbogbo da si odo mi loni
nitori ti moriwo ope ba yo a koju si Olodunmare
Atewe Atagba e maa ba mi se
. Mo se iba eyin Agba ooooooo
Re: .. by KEHINDE633(m): 8:07pm On Jul 07, 2015
[color=#000099][/color] IBON TODAJU
ewe ailu to po die pelu eyo owo (15) ati omi osan wewe ao gun pomo rawon ao da si inu omi osan yen ao ma mu die die..

1 Like

Re: .. by KEHINDE633(m): 8:13pm On Jul 07, 2015
Iba akoda aiye..iba aseda aiye,. iba agbagba merindinlogun lotu ife..iba oja tokun tio lero.iba obinrin arin ihoho woja..awon loni akiki odidi made kuro ju ano. ojo ti akerejupon ba fenu kanle ojo na ni kanlepa.ojo ti keregbe batenu bo omi ololo ni fohun....,...

2 Likes

Re: .. by KEHINDE633(m): 11:36pm On Jul 07, 2015
IBA EYIN IYA MI LORITA META ONA ARA EGBO OHUN MI LONI O
ogbo loni kie gbohun loni, alupiada loni kie ma pahun mi da loni. ogba loni kie gba oro mi loni. abamoda kan oni da tie kio mase . gbogbo obirin ilu okunrin ilu egbo hun me sire loni

4 Likes 1 Share

Re: .. by Nobody: 4:56am On Jul 08, 2015
E ku ise, egbogi wo lo da fun eyin didun ati ara riro
Re: .. by Nobody: 5:00am On Jul 08, 2015
KEHINDE633:
[color=#000099][/color] IBON TODAJU
ewe ailu to po die pelu eyo owo (15) ati omi osan wewe ao gun pomo rawon ao da si inu omi osan yen ao ma mu die die..

Se ko ni gbolohun tabi ofo kankan fun. E se
Re: .. by Kulrunner: 2:12pm On Jul 08, 2015
Ejo ogun awure obinrin nimofe ejo efunmi
Re: .. by kadunasouth(m): 9:32pm On Jul 08, 2015
Mode lobi ile ile lobi mode ogere afoko yeri afoko yeri lobi atepe atepe lobi arososile ife Arososile ife lobi Ajomisara Ajomisara lobi Agbanmiregun nje emi di Agbanmiregun gbogbo eni tobagun ori ile tofe sasimi abi semi laburu ile baja kodalamu tikobajawo ile lanu kogbemi kodi ero ORUN

2 Likes

Re: .. by bosrote: 4:32pm On Jul 10, 2015
Aboru aboye ejo ki ale lo fun HOMONAL INBALANCE BI OMU OBIRIN BA NSE OMI LAI LOYUN TABI OMO LOWO? TE BA NO EJO EFUN WA . EWE AMA JE
Re: .. by sammyjay76(m): 10:58pm On Jul 10, 2015
healthFirst:
Oju Okun ko ni buru
ki o mo lee fe ilele ilele
awalawulu oju orun
o ni wu koriko
awon lo difa fun olokun seniade
lojo ti gbogbo omi so pe
awon ko niba se mo
won ni ki o rubo
ki gbogbo awon ti won lawon
o ni ba se le maa ba se
won yan lebo o rubo
laipe laijina gbogbo awon omi
ti won lawon o ni base yi ohun pada
won wa nba olokun se
wo si fi joba won won teriba fun un
olokun seniade njo, o ni yo ooo
ni bee lawon babalawo to se fa fun oun wi
awon oju okun ko ni buru ki o mo lee fe ilele ilele
awalawulu oju orun ko ni wu koriko
awon lo difa fun Olokun Seniade
lojo gbogbo omi so pe
awon o niba se mo
nje e ba mi se loni atewe atagba
ewe asesere loni ki e ba mi se
eku olose loni ki e ba mi se
ogbo loni ki e maa gbo te mi
ewe apada loni ki e padi ire gbogbo da si odo mi loni
nitori ti moriwo ope ba yo a koju si Olodunmare
Atewe Atagba e maa ba mi se
GBOGBO AWON NKAN TI MO BERE KO SI ESI TE FUN MI, E JOWO MA SE BE O, OGUN AE OBNRIN TO LO TI AFE KO PADA WA, ATI ogun gbo temi to daju.
Re: .. by KEHINDE633(m): 12:00am On Jul 12, 2015
[color=#990000][/color]IBA saki loni oro. awo ijale loni epe. ijebu loni ase.ati oro saki ati awo ijale apa kankan otu kawa mo iyen madi eworisa..ayi ile aiye ka loruko tanpe aro. etu loruko tanpe osan. okuku birimu loruko tanpe oru. igba nla loruko tanpe aye.majedun loruko tanpe ile. ife omo jeje ki iku ma to e pami . ohun lo difa ile. eni gori ile oba gori eni ade go ri oba esinsin gori ade. esinsin to gori ade lojo kinin ano yen won dariji. Iya lode o iya lode o iya lode o .. otun. otunba. osi. gbogbo won dariji mi .kehinde. aro nimi mio lorukun ejo. aafin nimi mio lese eya go lona........COMING SOON MORE

1 Like

Re: .. by sammyjay76(m): 7:51pm On Jul 12, 2015
healthFirst:
53 IRINA MAJELE TODAJU:-
Aye oga kan, atare aja kan, ape olomori kan, ao si epo atare na kuro, yio ku aso oko funfun si ara atare naa, ao wa ki senu oga aye na lai tiku, ao fi nkan bi owu tabi okun we enu re po mo atare na ko ma ba po kale, ao gbe ju si ape, ao de pa, ao jo, ao lo, gbere kokan is isale oju wa, opo eyan lelo.....ti majele ba wa ninu ounje tabi oti, ao ri oga ti yio se ma sere layika yida eti ounje na tabi mimu, eyi tumo si pe. Olewu o

GBOGBO AWON NKAN TI MO BERE KO SI ESI TE FUN MI, E JOWO MA SE BE O, OGUN APE OBNRIN TO LO TI AFE KO PADA WA, ATI ogun gbo temi to daju.

1 Like

Re: .. by Nobody: 4:16am On Jul 13, 2015
sammyjay76:


GBOGBO AWON NKAN TI MO BERE KO SI ESI TE FUN MI, E JOWO MA SE BE O, OGUN APE OBNRIN TO LO TI AFE KO PADA WA, ATI ogun gbo temi to daju.

Mo da yin lohun awon ibeere yin, to ba ni awon eyi to ku; Suuru loba iwa. E se suuru, Ikookan la n yo ese le'ku.

(1) (2) (3) ... (10) (11) (12) (13) (14) (15) (16) ... (99) (Reply)

Viewing this topic: 1 guest(s)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 37
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.