Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,163,365 members, 7,853,634 topics. Date: Friday, 07 June 2024 at 08:31 PM

MIRACH's Posts

Nairaland Forum / MIRACH's Profile / MIRACH's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MIRACH(m): 7:58pm On Jul 03, 2007
MIRACH:

oro na dun o fe ke,se ti olutomiwa leri ti e pariwo,temi ma le ju ti tie lo,wa gba.
howu risi lost panu de esinsin nbo,abi o tun fe pa ketekete ni,keke aburo re leyi nse
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MIRACH(m): 7:47pm On Jul 03, 2007
richylaw:

Oponu eniyan gba ni o fun ohun ti o n se yi, ko si si iwa laakaye kan ni opolo re. Mo lero wipe o ni opolo ati oju lati ka iwe sha, se ibi je abala okun 'romance' ni? Abaniloju je eda. Itiju gba ni iru iwo yi je fun iran yoruba, ti o ba je okan ni o. Ki lode ti o fi je wipe awa omo adarihurun ko ni owo fun erohungba inu omo lakeji won, paapaa julo omo yoruba ode oni?. Bi o ba je wipe o ni onimoran ti o dara , mo mo wipe iru iwa alasise yi ko ni ti owo re se.
Mo mo gbangba gbangba wipe iwo na ni olutomiwa o kan pa oruko re da ni.
Joko ki o ronu ara re wo, iwa obo, eranko gbaa ni eleyi.

Koda o ti fihan gbangbagbangba wipe okobo ni o , iru awon aworan yi ni o si yan laayo lati mu ironu ailedide olomokunrin re kuro.
Iba san ki o lo si gbagede ibi ti won yio ti gba o towo tese pelu iwa palapala re.
Awa ko ni fi aye gba iru eleyi ni ibi o.
oro na dun o fe ke,se ti olutomiwa leri ti e pariwo,temi ma le ju ti tie lo,wa gba.

Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MIRACH(m): 6:49pm On Jul 03, 2007
segoye2:

Ogbenni MIRACH,

Ki ni itumo rada rada yi? se ko n se wipe wo n tele e sha oooo, why are u messing up this thread hummm? Abi o fe ki won begi fun oooo,
Ki de ni itumo aworan ti o gbe si ibeyen, Ohun ti a ba awe ti o koja lo so ni yen , ti a si baawi, ode gbo iba wi, sugbon, ire ti fi ye gbogbo ile yi wipe eyan randapri ni o.

Ma se be mo oooo, is not good at all.
aja la jenu iwo omugo yi,kete kete le si ri,kata kata nbo lona,e gbadun mi ni abule wa yi,ajo nilu yi ni,awon osi kan o le ma pase fun wa,talo fi yin se olori ilu gan na?eyin iranu yi,e jo e lo wabi wo si.
Religion / Re: 60 Questions For The Christians by MIRACH(m): 6:33pm On Jul 03, 2007
jayon:

Let us stop diz arguments diz people have been blindfolded can't u see, THAT ISLAM IS FALLING
abeg TOLD dem o,d religion is falling every second of d day.
Culture / Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MIRACH(m): 6:09pm On Jul 03, 2007
richylaw:

E seun o, eyin ara ilu,
Awon agba bo , won ni adan dorikodo o n wo se eye. E je ki a tun wo owo ti awe ti won n pe ni Olutomiwa yi , yio gbe ki a to da seria fun.
Mishoo nkankan grin
o ku atileyin o

Segoye, bi a ba ti so pe o ya , o ti ya na nu, yara ki o se kanmokanmo. E o ri owo alaago oba bi o ba ti di ale. Mo se ileri wipe iwuye yio ona kan pato leti jeki awon omo kaaro ojiire ti wo ti fe sonu si igberi okun ranti ile ki won si tun mo nipa awon asa ataye baye ti asa oyinbo ti fe bo mole

Tafari, lati ran o lowo, dahun eyokan soso ninu ibeere re. A o si fun o loye. Oni lati se ohun kan pato ti a o fi ri wipe ogidi omo yoruba ni o.

ARA NA RE O,O DARO,OKAN KAN LA JI O,A NI SARE RIRA O grin

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 30
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.