Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,145 members, 7,815,014 topics. Date: Thursday, 02 May 2024 at 04:45 AM

OBAONIMOLE's Posts

Nairaland Forum / OBAONIMOLE's Profile / OBAONIMOLE's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Ifa Divination For The Month Of April 2012 by OBAONIMOLE(m): 9:38am On Apr 04, 2012
OSE OTURA

Akuree akuree oregbe nikurekure kaka komo awo oku iroke adaa ipese afaya ,omo awo koni ku iroke konida ipese konifaya difa oluogirika omo afebo tiku orun gbonyin gbonyin mare,won npe oluogirika lorun koje ebo lofinsowo siwon ,kini oluogirika fijepe ebo ni oluogirika fijepe ebo agogo idée kiyun nimaro,ajaa tikoni omo ninu kijepe orisa lagidigbo kibawon yun morun,oluogirika pele o.omo afebo tikuu orun gbonyin gbonyin mare.

IFA ni osu ti awayi,osu Kerin odun wipe osu ibukun,ilosiwaju ati isegun aiku ni fun gbogbo wa ,wipe ki akun fun adura,ki asi safun ese towun ipani lara ,ki amasi peri omo lakeji wa nibi,IFA ni ki amarubo dada ki asima se adura ,ki asima bo eleda wa dede ki asimani emii idarijin

IFA DIVINATION FOR THE MONTH OF APRIL 2012
OSE OTURA
IFA says this month we are is a month of greatness,succes,overcome death for all
IFA says we should all be prayerful and should not bad bite
IFA says we should not say a bad curse on our fellow human beings
IFA says will should be very prayerful and worship our ORI (DESTINY)
IFA OLODUMARE WILL BE WITH ALL.ASE O
Religion / Ifa Divination For The Month Of April 2012 by OBAONIMOLE(m): 9:36am On Apr 04, 2012

Religion / Iwaa(attitude/behavoir) by OBAONIMOLE(m): 5:02pm On Mar 01, 2012
IWAA

Aja sunwon sunwon leyin lode oroo makin,Agbo sunwon sunwon niroro ,Aja mi o niroro karele remun agbo wa,kamun bo baba dudu kere kere tinje olofin wa,difa fun iwaa tinse abileyin ori ,won niki okara nle eboni ki ose ,Iwaa nikan losoro ori kan koniburu tofide ile ife iwaa nikan losoro.

Tewe tagba,toba tijoye,teleshin lekan ejeki atoju iwa nitiori iwaa ni ngbe ni de ajale kokoo.Iwaa lesin

ATTITUDE/BEHAVIOR

Youth,adult,kings,chiefs,rich and poor your attitude is your life ,because this is the only thing that can lead you to greatness ,so we should all keep good attitude so as to be great, your attitude/behavior is your life, don’t loose it

WWW.obaonimoleoluifaagbaiye.com
Culture / Iwaa(attitude/behavoir) by OBAONIMOLE(m): 4:41pm On Mar 01, 2012
IWAA

Aja sunwon sunwon leyin lode oroo makin,Agbo sunwon sunwon niroro ,Aja mi o niroro karele remun agbo wa,kamun bo baba dudu kere kere tinje olofin wa,difa fun iwaa tinse abileyin ori ,won niki okara nle eboni ki ose ,Iwaa nikan losoro ori kan koniburu tofide ile ife iwaa nikan losoro.

Tewe tagba,toba tijoye,teleshin lekan ejeki atoju iwa nitiori iwaa ni ngbe ni de ajale kokoo.Iwaa lesin

ATTITUDE/BEHAVIOR

Youth,adult,kings,chiefs,rich and poor your attitude is your life ,because this is the only thing that can lead you to greatness ,so we should all keep good attitude so as to be great, your attitude/behavior is your life, don’t loose it
Religion / Ifa Divination For The Year 2012 by OBAONIMOLE(m): 4:21pm On Jan 17, 2012
OSE OROGBE

Sogiso Koje keni gbeyin loju ,ipee koje keni oki eree mole, ote nio jekiwon mo oju ororii yeye won difa fun olowu kangun ere aminwo ajaa,Kaje nikere kamun nikere kamafi oro kerekere bi ira eni difa fun odun tinse iya olowu kangun eree.Atoko modun wale difa fun oyagbe onlo soko ailere odun won mo kara nle eboni kose ,Epee ki odun rere bo wale o.odun iwo niya oba eniyan rere kigbe seyin ekuu.

IFA DIVINATION FOR THE YEAR 2012

IFA says this year is a year of blessings and greatness for everyone

IFA says this year is a year of comfort for all

IFA says this year will be a year of survival for everyone in our varoius endeavors

IFA says this year shall be a year of great resolution for everyone

IFA says this year ,we shall see the truth of all evil&bad deeds that his been planned against someone by enemy or bad peoples
Culture / Ifa Divination For The Year 2012 by OBAONIMOLE(m): 4:18pm On Jan 17, 2012
OSE OROGBE
Sogiso Koje keni gbeyin loju ,ipee koje keni oki eree mole, ote nio jekiwon mo oju ororii yeye won difa fun olowu kangun ere aminwo ajaa,Kaje nikere kamun nikere kamafi oro kerekere bi ira eni difa fun odun tinse iya olowu kangun eree.Atoko modun wale difa fun oyagbe onlo soko ailere odun won mo kara nle eboni kose ,Epee ki odun rere bo wale o.odun iwo niya oba eniyan rere kigbe seyin ekuu.

IFA DIVINATION FOR THE YEAR 2012

IFA says this year is a year of blessings and greatness for everyone

IFA says this year is a year of comfort for all

IFA says this year will be a year of survival for everyone in our varoius endeavors

IFA says this year shall be a year of great resolution for everyone

IFA says this year ,we shall see the truth of all evil&bad deeds that his been planned against someone by enemy or bad peoples
Culture / Re: Ifa Divination For The Month Of Septemper by OBAONIMOLE(m): 10:42am On Sep 06, 2011
yes,it is possible to make a divination and that pattern to everybody,

becos this is a divination that is been made for the betterment of our life in that particular month ,and this is not made indivitually is made with the name massess/everybody
Religion / Ifa Divination For The Month Of Septemper 2011 by OBAONIMOLE(m): 10:35am On Sep 03, 2011
IDIN ASINPELU NIFA ADA FUN OSU IKESAN YI ODUN 2011

IFA ni gbogbo oun ti abafe se ninu osu yi ,ki akoko bere lowo eleda wa no,ki ato da owo le ki ama bale ko abamo ,gbogbo wa koni ko abamo .ASE

IFA DIVINATION FOR THE MONTH SEPTEMBER 2011

IFA ,say anything we want to do this month we should first ask our head(creator),so as to not to see danger or bad things happening to us,we will never see danger ooo .ASE
Culture / Ifa Divination For The Month Of Septemper by OBAONIMOLE(m): 1:57pm On Sep 02, 2011
IDIN ASINPELU NIFA ADA FUN OSU IKESAN YI ODUN 2011

IFA ni gbogbo oun ti abafe se ninu osu yi ,ki akoko bere lowo eleda wa no,ki ato da owo le ki ama bale ko abamo ,gbogbo wa koni ko abamo .ASE

         IFA DIVINATION FOR THE MONTH OF SEPTEMBER 2011

     IFA ,say anything we want to do this month we should first ask our head(creator),so as to not to see danger or bad things happening to us,we will never    see danger ooo .ASE
Religion / One Year On The Throne As Hrh Oba Onimole Olu Ifa Agbaye Woldwide by OBAONIMOLE(m): 1:15pm On May 29, 2011
I HRH OBA ONIMOLE OLU IFA AGBAYE ,Apata shiaba kinni,Awo Ooni olodumerindinlogun,IS ONE YEAR ON THE THRONE AS THE KING OF IFA WORLD-WIDE ,ICON&SYMBOL OF AFRICAN TRADITION WORLD - WIDE,on this day 29th of may 2011.MAY IFA OLODUMARE WILL BE WITH EVERY ONE OF US.
Religion / One Year On The Throne As Hrh Oba Onimole Olu Ifa Agabye Woldwide by OBAONIMOLE(m): 12:06pm On May 29, 2011
I HRH OBA ONIMOLE OLU IFA AGBAYE ,Apata shiaba kinni,Awo Ooni olodumerindinlogun,IS ONE YEAR ON THE THRONE AS THE KING OF IFA WORLD-WIDE ,ICON&SYMBOL OF AFRICAN TRADITION WORLD - WIDE,on this day 29th of may 2011.MAY IFA OLODUMARE BE WITH EVERY ONE OF US
Religion / Ifa Divination For The Month Of May by OBAONIMOLE(m): 6:41pm On May 15, 2011
FROM THE DESK OF ICON OF AFRICAN TRADITION & SYMBOL OF IFA WORLDWIDE
HRH OBA ONIMOLE OLU IFA AGBAYE
Apata shiaba kinni
Awo Ooni olodumerindinlogun

IFA DIVINATION FOR THE MONTH OF MAY.

• IFA says this month is a month of paving way to all the good things of life
• IFA say that we should all embark on perseverance
• IFA says that we shouldn’t be in a haste more than our creator.
• IFA says everything we are looking for will surely come to us with patience,in this month,but we shouldn’t disstabilize things with hastiness.
• IFA says every good things will be within our reached and we should pray fervently and we shouldn’t indulge our selves in a fight over things,and we shouldn’t let our soul to be killed in cold blooded because of a post or property.
• IFA says good things we surely be our portion this month.

WWW.obaonimoleifaagbaye.com obaonimoleifaagbaye@yahoo.com
Religion / Re: Introduction To Ifa Religoin by OBAONIMOLE(m): 12:05pm On Apr 20, 2011
Just Email your Request(questions) ,your name,your mother name to obaonimoleifaagbaye@yahoo.com.

and your request will be treated privately as you want it.
Religion / Re: Introduction To Ifa Religoin by OBAONIMOLE(m): 12:00pm On Apr 20, 2011
yes, can make a divination for you on any thing you want to ask IFA OLODUMARE,

IFA OLOKUN A SORO DI AYO ASORO WA DI AYO OOOOO
Religion / Ifa Divination For The Month Of April by OBAONIMOLE(m): 4:07pm On Apr 12, 2011
FROM THE DESK OF ICON OF AFRICAN TRADITION
HRH OBA ONIMOLE OLU IFA AGBAYE
Apata shiaba kinni
Awo Ooni olodumerindinlogun
ODU IFA OSU KERIN ODUN TI AWAYI
OGUNDA EFUN
IFA niki amadale wipe ki amasi fibisu olore ,wipe ki ase otito pelu are wa,Ki ire gbogbo wale tete towa lowo nitori osu ilano ni osu yi fun wa ki asitoju ori wa.
Ore lore otito ore lore ododo ore lore kabara eni mule kama ma dara eni difa fun saraa osunkun alaibimo obi eiyele sile,obi adaba si ijuu won ni kokara nle eboni kose ati eiyele ile o,ati adaba ijuu ki eiye mamaba eiye ja.

IFA DIVINATION FOR THE MONTH OF APRIL
• IFA says we should not betray.
• IFA says we shouldn’t pay good deeds with evil.
• IFA says we should be truthful to each other so that we can attain our glory in a short while.
• IFA says that this month is a blessed month for us all and we should worship our head.

SAYINGS FROM IFA
IFA says a good friend is a truthful friends, that goes into covenant without betraying each other, consulting IFA for saraa ,weeping of barreness,she gave birth to a pigeon at abode and more so gave birth to a finch in the dungeon ,she was asked to stood up and prepare a sacrifice, house pigeon and dungeon finch shouldn’t fight each other.
Religion / Re: Ifa Divination For The Month Of April by OBAONIMOLE(m): 8:58pm On Apr 09, 2011
INBOX

Anything you want to ask OR say to our inbox

obaonimoleifaagbaye@yahoo.com

your mails are welcome
Culture / Re: Ifa Divination For The Month Of April by OBAONIMOLE(m): 9:46am On Apr 08, 2011
mistake been made

we should not betray.

sorry for that
Religion / Re: Ifa Divination For The Month Of April by OBAONIMOLE(m): 7:36pm On Apr 07, 2011
ASE OOO.

OLODUMARE ATI WA LEYIN OOOOO

ASE WA
Religion / Re: Ifa Divination For The Month Of April by OBAONIMOLE(m): 7:34pm On Apr 07, 2011
The correct translation;

-Ifa says that we should not betray.

it was a mistake
Culture / Ifa Divination For The Month Of April by OBAONIMOLE(m): 10:56am On Apr 07, 2011
FROM THE DESK OF ICON OF AFRICAN TRADITION
HRH OBA ONIMOLE OLU IFA AGBAYE
Apata shiaba kinni
Awo Ooni olodumerindinlogun
ODU IFA OSU KERIN ODUN TI AWAYI
OGUNDA EFUN
IFA niki amadale wipe ki amasi fibisu olore ,wipe ki ase otito pelu are wa,Ki ire gbogbo wale tete towa lowo nitori osu ilano ni osu yi fun wa ki asitoju ori wa.
Ore lore otito ore lore ododo ore lore kabara eni mule kama ma dara eni difa fun saraa osunkun alaibimo obi eiyele sile,obi adaba si ijuu won ni kokara nle eboni kose ati eiyele ile o,ati adaba ijuu ki eiye mamaba eiye ja.
FROM THE DESK OF ICON OF AFRICAN TRADITION
HRH OBA ONIMOLE OLU IFA AGBAYE
Apata shiaba kinni
Awo Ooni olodumerindinlogun
IFA DIVINATION FOR THE MONTH OF APRIL
• IFA says we should betray.
• IFA says we shouldn’t pay good deeds with evil.
• IFA says we should be truthful to each other so that we can attain our glory in a short while.
• IFA says that this month is a blessed month for us all and we should worship our head.

SAYINGS FROM IFA
IFA says a good friend is a truthful friends, that goes into covenant without betraying each other, consulting IFA for saraa ,weeping of barreness,she gave birth to a pigeon at abode and more so gave birth to a finch in the dungeon ,she was asked to stood up and prepare a sacrifice, house pigeon and dungeon finch shouldn’t fight each other.
Religion / Ifa Divination For The Month Of April by OBAONIMOLE(m): 10:11am On Apr 07, 2011

Culture / Introduction To Ifa by OBAONIMOLE(m): 4:05pm On Mar 21, 2011
Introduction To Ifa Religoin
« on: March 18, 2011, 04:55 PM »

FROM THE DESK OF THE ICON OF AFRICAN TRADITION
HRH OBA ONIMOLE IFA AGBAYE
IFADAMILARE ENIOLA ALADE
(ADENIJI APATA SHIABA IKINNI)
AWO OONI OLODUMERINDINLOGUN
INTRODUCTION TO IFA
IFA is the way of life and everlasting .IFA is the truth of life.IFA will lead you to a straight path not astray. IFA is the truth sayer for those that believe in it,IFA is a good leader that will never lead you astray . IFA is a destiny instructor that will tell you your do and don’ts that is what your destiny forbid.
IFA is a good counsellor of life,IFA is a good reformer of well being,IFA is a great provider in times of need,the armour that protects one from untimely death and negativities,IFA is the one who has come to bring succour into the life of every man ,IFA is the one who protect the head of elemere (destined to die young )so that his head is not broken into pieces.
If we truly follow IFA we will surely live long, and they will be blessed with all the opportunity to attain and achieve their fervent desires in life .
IFA is a defender,IFA will never allow your good deed to turn to sorrow.IFA is a soothe sayer that will never allow you to be mocked by your foe . IFA is a good refurbisher .IFA is not a evil doer but a religion of the world that reshape someone destiny but human being turn light into darkness but how truthful are you to your creator so therefore believe and accept IFA as a good leader and you must not doubt it because anything ifa says is from the ALMIGHTY GOD(OLODUMARE).poet is the rider of word and word is the rider of poet as well,if there is light darkness has no place to stay.if there is anything bothering us we consult IFA and anything he says is from ALMIGHTY GOD (OLODUMARE).
IFA is inevitable.IFA is not a wizard nor witches,IFA is not charm, IFA is not a money bowl that we pick money inside but lead you to a straight path of your life ,if only you can be patience and be perseverance .so therefore you have to stick to it because is a religion of wealth, IFA says in his word,says that, a strong man is the one that go to the war front and an elder that does’nt stand firm will definitely turn to a farmer.It is only the wise one that worship IFA. consulting IFA for the elder of AKOWAJO EGBA weeping of all good things of life, and he was asked to stood up and prepare a sacrifice, who is going to collate my good deed ,the good speaker, it is IFA that will collate my deed the good speaker.

OBAONIMOLE (m) Re: Introduction To Ifa Religoin
« #1 on: March 19, 2011, 03:38 PM »

FROM THE DESK OF ICON OF AFRICAN TRADITION
HRH OBA ONIMOLE IFA AGBAYE
ADENIJI APATA SHIABA 1
THE AWO OONI OLODU MERINDINLOGUN.
ITUNMO IJINLE ORO IFA
IFA ni ona iye aini ipekun .ifa ni otito aiye.ifa ni afini mona aiye laini ikose .ifa ni afinse aiye gege bi eniyan tio gbagbo .ifa ni nfini mona tiki dari eni sigboo,ifa ni afinbere akose jaiye eni ti afinmo bi irin ajoo aiye eda tise mari ,ifa ni fini mo irin ajoo aiye eni ti afin mo oun totoo tabi oun tio too gege bi ewoo aiye eni ifa ni abalaye se aiye .

IFA ni aba oniwa tun iwa se ifa ni ajeri oran ifa kije kiwa eda obaje ifa ni odudu tio du ori elemere ti kije kii ori elemere ojafo atun ori eniti kosun won se .ifa ki se ikaa esin otito aiye ti anfi to aiye ni sugbon awon eniyan ni won sogba di oogbun nje iwo lese otito pelu eleda re bi tio ba ribe gba ifa gbo gegebi afinimona kiwo masi se iyee meji nitori oro olodumare ni ifa je .

Owe leshin oro oro leshin owe bi okunkun bakun imole ni ao fiwa bi oro baruju ifa ni ao fi wa oro ti obasi so odi oroti akuwarapa baso ode orun lotiwa .ifa kise oso ifa kise aje ifa kise ogun ti a fi nlu ori ,

IFA kise eesun ti anko owo ninu re sugbon yio too sona aiye re bi obale nisuru re .nitori be mun ni okunkun dun esin asinla ni .owun ni ifa fisoro ninu odu mimo re wipe alagbara ni njagun agbaa tio lese nle asowo agbe eni yo gbon ni sin ifa difa fun olori akowajo egba ekun ire gbogbo niwon nsun won niki won kara nle eboni kanse ,tani yio bami kowa temi jo afede feyo ifa ni yio bami kowa temi jo afede feyo ….tani yio bami kowa temi jo afede feyo ifa ni yio bami kowa temi jo afede feyo

www.obaonimoleifaagbaye.com
Religion / Re: Introduction To Ifa Religoin by OBAONIMOLE(m): 3:38pm On Mar 19, 2011

Religion / Introduction To Ifa Religoin by OBAONIMOLE(m): 4:55pm On Mar 18, 2011
FROM THE DESK OF THE ICON OF AFRICAN TRADITION
HRH OBA ONIMOLE IFA AGBAYE
IFADAMILARE ENIOLA ALADE
(ADENIJI APATA SHIABA IKINNI)
AWO OONI OLODUMERINDINLOGUN
INTRODUCTION TO IFA
IFA is the way of life and everlasting .IFA is the truth of life.IFA will lead you to a straight path not astray. IFA is the truth sayer for those that believe in it,IFA is a good leader that will never lead you astray .                                                                                                                                                                                   IFA is a destiny instructor that will tell you your do and don’ts that is what your destiny forbid.                                                                                         
IFA  is a good counsellor of life,IFA is a good reformer of well being,IFA is a great provider in times of need,the armour that protects one from untimely death and negativities,IFA is the one who has come to bring succour into the life of every man ,IFA is the one who protect the head of elemere (destined to die young )so that his head is not broken into pieces.     
If we truly follow IFA we will surely live long, and they will be blessed with all the opportunity  to attain and achieve their fervent desires in life .   
IFA is a defender,IFA will never allow your good deed to turn to sorrow.IFA is a soothe sayer that will never allow you to be mocked by your foe . IFA is a good refurbisher .IFA is not a evil doer but a religion of the world that reshape someone destiny but human being turn light into darkness  but how truthful are you to your creator so therefore believe and accept IFA as a good leader and you must not doubt it because anything ifa says is from the ALMIGHTY GOD(OLODUMARE).poet is the rider of word and word is the rider of poet as well,if there is light darkness has no place to stay.if there is anything bothering us we consult IFA and anything he says is from ALMIGHTY GOD (OLODUMARE).
IFA is inevitable.IFA is not a wizard nor witches,IFA is not charm, IFA is not a money bowl  that we pick money inside but lead you to a straight path of your life ,if only you can be patience and be perseverance .so therefore you have to stick to it because is a religion of wealth, IFA says in his word,says  that, a strong man is the one that go to the war front and an elder that does’nt stand firm will definitely turn to a farmer.It is only the wise one that worship IFA. consulting IFA for the elder of AKOWAJO EGBA weeping of all good things of life, and he was asked to stood up and prepare a sacrifice, who is going to collate my good deed ,the good speaker, it is IFA that will collate my deed the good speaker.
Culture / Ifa Consultation For The Month Of March by OBAONIMOLE(m): 5:02pm On Mar 02, 2011
IFA CONSULTATION FOR THE MONTH OF MARCH
IFA ni ki asora,ninu osu yi,ki amase aigboran,ki amasi se oju kokoro,ki amasi ri irinkurin nitori,arinfese si.nitori bi ire se nbe losu yi ni ewu nbe .Ayo lao filaja ire ibe lao ri ao niri ibi .ASE

         IBAWI OLODODO
Eni awi fun kogboooo agbalagba ti akoloro togba ,ire gbogbo lonse fun ni difa fun orunmila ifa nlo fi okun ko iwe lodo awon oparun kerekese ado ewii,imoo segi segi ,orunope ipemuren lawo ipemuren,ipemuren lawo ipemuren,Eniyan kise ore alakan koberii lo ,erii nkuno akan nwe kikun erii kipa akan igere kiba kun omo akan awe erii kikun kopa akan alaja mani ,erii kikun kopa akan.
                     
                              FROM
                     HRH OBA ONIMOLE
                        (IFA AGBAYE)

1 Like

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 57
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.