₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,329,037 members, 8,438,552 topics. Date: Friday, 03 July 2026 at 03:29 PM

Toggle theme

Omoalade144's Posts

Nairaland ForumOmoalade144's ProfileOmoalade144's Posts

1 2 (of 2 pages)

CultureRe: .. by omoalade144(m): 8:37pm On May 04, 2016
Eku dede asiko yio gbogbo ile.Ejowo moni ibere kekere kan ti mofe bere ni.Enikan so fun mi pe, ti okunrin toni ogun lara bani ibalopo pelu obirin ton se nkan osu lowo,ogun towa lara okunrin na yio dinku,ejowo se ooto ni atipe kini eyan lese to ba ti sele si eyan.ODURO-GOGO lan ba osun awo!.Ao ni se aisan ooo.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 4:45pm On Apr 24, 2016
mokiyin lopolopo sir eyin baba wa,ejowo sir se loto ni pe Ogun dudu,Ogun pupa ati Ogun funfun lo wa.Bawo lasele dawon mo atipe kini iyato towa larin won.Orunmila Agbewa.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 6:39pm On Apr 15, 2016
Moki gbogbo ile o.Ejoo se baba Heltfirst kosi nile ni
CultureRe: .. by omoalade144(m): 10:46pm On Mar 11, 2016
ekaale o baba ifankaleluya ati gbogbo ile o
CultureRe: .. by omoalade144(m): 9:52pm On Jan 17, 2016
Ejowo sir moni ibere kekere kan torumi loju,ejowo ti obirin balo ogun adodun fifo abe re,ti okunrin balo CONDOM ba obirin na sun se ogun na yio sise.Eseun sir, agba yin adale o
CultureRe: .. by omoalade144(m): 2:47pm On Jan 17, 2016
Ekasan o baba,ejowo baba efunmi ogun eyonu togbona ti ale fi si ara ti aba fe jade
CultureRe: .. by omoalade144(m): 6:15pm On Jan 15, 2016
Inu mi dun gidigidi si iwe tie gbe jade yi, nitori pe, iwe yi wa gege bi agbara fun omo yoruba tooto,
nitori idi eyi, moro
gbogbo wa pe kia nipin ninu iwe yi.
Emi gan papa n tiraka lati nipin ninu
iwe yi .mosi mope lagbara OLORUN ELEDUMARE emi na ani iwe yi lowo.ASE.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 9:37pm On Jan 11, 2016
Eseun lopolopo,eo ni gbosun yile.Ase.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 7:10pm On Jan 11, 2016
Se ti aba fe sin gbere yen lao pe ofo yi ni.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 2:36pm On Jan 11, 2016
AWURE. 121.Ejowo se eyele funfun lama lo ni tabi dudu.Odun ayo ni 2016 yio je fun gbogbo wa o .Ase.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 4:56pm On Dec 31, 2015
ejowo edakun kini oruko miran ti an pe ewe igbagbe.Ao ni sise o.Ase.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 5:24am On Dec 24, 2015
ejoo sir baba HELTFIRST,owo malumi towa ni page 1.No 9, se ao we lowu dudu ati funfun pelu eyo atare kan ni abi ti aba fe ran lawo funfun lao fi atare eyokan si legbe ao wa ran po.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 5:14am On Dec 24, 2015
w
CultureRe: .. by omoalade144(m): 10:27pm On Dec 23, 2015
Baba HELTFIRST ati Baba KADUNASOUTH,ejowo lasiko ti awa yi,ejowo afe kee fun wa ni iwure odun toni ese ifa ninu.Odun a yabo ooooo!
CultureRe: .. by omoalade144(m): 7:34pm On Dec 22, 2015
Eleyi dara pupo!.ejowo ilu eko ni mowa, ti iwe na ba jade bawo ni mo sele rira atipe elo gan ni yio je.Opolo yin koni ku o.Ase.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 10:15am On Dec 21, 2015
Ejowo baba heltfirst mofe ba ifa ni gbolohun lori oro kan.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 11:37pm On Dec 19, 2015
Moki gbogbowa pe aku ipalemo odun o, yio bawa layo ati alafia lagbara ELEDUMARE.Ejowo bi oludasile ikanni yi ban se atunse toto ati eyi toye,ejowo mo rowa pe ki ama fise ibinu bikose pe ki ase atunse, nitoripe opolopo awa ti awa lori ikanni yi looto ogberi niwa,nitorina moro eyin awo ki emase siwa lona o.Isese a gbewa o.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 10:06pm On Dec 14, 2015
Eku asale o baba kadunasouth ati baba Heltfirst ejoo,edakun,e funwa ni ogun Atepa\Isana todaju.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 8:57pm On Dec 13, 2015
Aboru boye o, baba.
CultureRe: .. by omoalade144(m):
Hunnnn...Ase bao ni akan agba bi ewe laari.Bi omode o ba mo ewe ti kosi mo owe afi kori awon agba ki won to sonan.
Too! adupee lowo eyin
agbagba lori ikanni yi
fun itoni sonan lori
ohun gbogbo,
nipa ewe ati egbo,ELEDUMARE yio
ma gbo adura wa,ao si ni seru aye lagbara OLORUN ELEDUMARE
ati loruko orunmila alagbawi wa ase.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 3:28pm On Dec 11, 2015
Ejoo gbogbo awo moni ibere pataki kan ti mofe bi eyin awo.Ti eyan ba pe odu ifa irete lati oju orun wa si oju aye, kini eleyi tumo si o!!, gbogbo eyin majeo baje lori ikanni yi?
CultureRe: .. by omoalade144(m): 6:47pm On Dec 09, 2015
Ago onile o,ejowo moni ibere pataki kan,se ti eyan ba fi ogun owo tabi any ogun si apo ti obirin ton se nkan osu bafi owo kan yan se ole ba ogun na je.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 2:28pm On Dec 09, 2015
Moki gbogbo wa patapata pe aku dede asiko yi, ayo lao fi se odun tuntun lagbara eledumare.Ejowo moni ibere kan ti mo fe bere.Ibere mi na ni pe,ti eyan ba lala pe ohun ya igbe loju orun ejowo ki lo tumo si.koni baje o
CultureRe: .. by omoalade144(m): 9:50pm On Dec 08, 2015
ise onje oju ala yi se eyan meji lelo.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 8:28am On Dec 08, 2015
IMULE FUN EYONU AYE 109 ni ipese ti mon so nipare o
CultureRe: .. by omoalade144(m): 10:34pm On Dec 07, 2015
ejoo nibo ni a o gbe ipese na lo,atipe sebi woni ti eyan ban je okete,awon agbalagba yio ma ri ifun re,yio si rorun funwon lati baja??.Koni baje o
CultureRe: .. by omoalade144(m):
Emi OMOALADE144 gege bi member lori aaye yi fi asiko yi ki olorii aaye yi ati gbogbo omo egbe patapata lapapo pe aku imurasile odun tuntun, yio ba walayo ati alafia, amin aseeee.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 9:04pm On Dec 06, 2015
Egbayi baba!!.Ese modupe.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 9:01pm On Dec 06, 2015
Egbayi baba,yio dara fun yin.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 5:47pm On Dec 06, 2015
Ese lopolopo, e o ni seku.ejoo se amin oke ni egbo udi yen ni abi amin isale. Ese lopolopo.
CultureRe: .. by omoalade144(m): 10:31pm On Dec 05, 2015
ejoo sir baba helthfirst e funmi ni ogun ako jedi
CultureRe: .. by omoalade144(m): 10:26pm On Nov 29, 2015
Ese lopolopo, odua a gbewa o.

1 2 (of 2 pages)