Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,862 members, 7,810,291 topics. Date: Saturday, 27 April 2024 at 05:51 AM

.. - Culture (64) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1827442 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (61) (62) (63) (64) (65) (66) (67) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Oluokunoluwole: 11:15pm On Mar 10, 2016
Ifankaleluya:

ERO-ABILU PE ORISI-RISI.....ADURA MI NI WIPE KI OLORUN MA JE KI E BO SI OWO(HAND) BABALAWO TI O NI EKO(KNOWLEDGE) DAADA. TORI KIN-NI KAN WA TI A N PE NI AKOFA(NEUTRALISES OF CHARMS OR MEDICINE IN SOMEONE's BODY), KINNI YI NI BABALAWO TO BA LEKO DAADA MA N KOKO SE LATI FI BA OGUN TO WA LARA ENIYAN JE TO BA FE BA ENIYAN JA. AASAN(gbolohun) RE WA, WON SI MA N SA OMIRAN LORI ESU PELU AWON EWE-IFA KAN.

SUGBON JU GBOGBO E LO, TI E BA TI RI OMO-OWU KI E KAN SI MI.
Baba eku ise opolo ejowo efunmi ni oogun yi lori email/oluokunoluwole4@gmail.com.eseun

KIISE OGUN TI MO LE FI SILE LORI FANRAN YI.

1 Like

Re: .. by sammyjay76(m): 4:44pm On Mar 11, 2016
Ifankaleluya:

ERO-ABILU PE ORISI-RISI.....ADURA MI NI WIPE KI OLORUN MA JE KI E BO SI OWO(HAND) BABALAWO TI O NI EKO(KNOWLEDGE) DAADA. TORI KIN-NI KAN WA TI A N PE NI AKOFA(NEUTRALISES OF CHARMS OR MEDICINE IN SOMEONE's BODY), KINNI YI NI BABALAWO TO BA LEKO DAADA MA N KOKO SE LATI FI BA OGUN TO WA LARA ENIYAN JE TO BA FE BA ENIYAN JA. AASAN(gbolohun) RE WA, WON SI MA N SA OMIRAN LORI ESU PELU AWON EWE-IFA KAN.

SUGBON JU GBOGBO E LO, TI E BA TI RI OMO-OWU KI E KAN SI MI.

KIISE OGUN TI MO LE FI SILE LORI FANRAN YI.
Edakun e se alaye omo owu yen Dada, se owu lagbede ni abi ewo?
Eseun.

1 Like

Re: .. by alqosimiy: 7:00pm On Mar 11, 2016
Moji tokitoki morin tokitoki iroko ojiya
Re: .. by Nobody: 7:39pm On Mar 11, 2016
..........
Re: .. by Ifankaleluya: 10:12pm On Mar 11, 2016
sammyjay76:

Edakun e se alaye omo owu yen Dada, se owu lagbede ni abi ewo?
Eseun.

Beeni...e o lo re be won ni omo-owu yen lagbade ni. Ki esi so fun won wipe omo-owu yen o gbodo wo omi ooo.

2 Likes

Re: .. by dominicson: 10:14pm On Mar 11, 2016
alqosimiy:
Moji tokitoki morin tokitoki iroko ojiya

Mo ji tokintokin, mo rin tokintokin, mo s'awo de'le Olutokin, irokojiya ma ma j'owo eleya o ba mi irokojiya...
Re: .. by dominicson: 10:17pm On Mar 11, 2016
skypeme:

ni bi odun melo kan seyin mo se alaba pade alfa kan fun iran lowo ati se aseyori, alfa ti mon so oro e yi si se jamba fun mi, gbo gbo aje sara ati iso to wa lara mi ni alfa yi baje. mo wa di eni ti ogun tete ran lese kese.

Fi okan re bale...
Re: .. by Nobody: 10:20pm On Mar 11, 2016
@Healthfirst are you sure if i try this Ogun Okigbe and i ask someone to cut off my head it won't cut? because i want to try it tomorrow, i have many ewe ewuro in my compound, if my head cut off i will hold you responsible

1 Like 1 Share

Re: .. by Nobody: 10:25pm On Mar 11, 2016
Dominicson se o fe ran mi lowo ni?
Re: .. by omoalade144(m): 10:46pm On Mar 11, 2016
ekaale o baba ifankaleluya ati gbogbo ile o
Re: .. by jbabas: 3:31am On Mar 12, 2016
Ekaale Baba,

E jowo, Oogun wo la ma fi nko ifa oore tabi oro ti a o ko moni?

jbabas
Re: .. by dominicson: 1:56pm On Mar 12, 2016
skypeme:
Dominicson se o fe ran mi lowo ni?

Emi ke? Emi aayan lasan! Only God/Light/Knowledge can help you.

You can whatsapp me nonetheless: 08145802864 or 08121751389

1 Like

Re: .. by skamo74: 3:59pm On Mar 12, 2016
[
Alfa eke,pastor eke, babalawo eke,adahunse oniro,even fake ore ti. po pupo lasiko ti awa you.

e ni lati bere Lori AJEGUN. eo ri opolopo ni ori ate yii

quote author=skypeme post=43686849]

ni bi odun melo kan seyin mo se alaba pade alfa kan fun iran lowo ati se aseyori, alfa ti mon so oro e yi si se jamba fun mi, gbo gbo aje sara ati iso to wa lara mi ni alfa yi baje. mo wa di eni ti ogun tete ran lese kese.[/quote]
Re: .. by Glory82: 4:37pm On Mar 12, 2016
E KU DEDE IWOYI,E JO TA LO NI OGUN TI A FI NLE GBOGBO NEGATIVE ENERGY DANU KURO NINU ILE.MO SE IBA O!
Re: .. by sammyjay76(m): 5:12pm On Mar 12, 2016
Ifankaleluya:

Beeni...e o lo re be won ni omo-owu yen lagbade ni. Ki esi so fun won wipe omo-owu yen o gbodo wo omi ooo.
ESEUN GAN NI MA KAN SI YIN LAIPE.
Re: .. by kuddus: 5:34pm On Mar 12, 2016
ejo e fun wa ni ogun aluwo to ni ewo to je wipe bi eniyan ba fi se ika to je wipe ko ni je
Re: .. by kuddus: 5:36pm On Mar 12, 2016
eyi ti eronja re ko po
Re: .. by Ifankaleluya: 8:43pm On Mar 12, 2016
jbabas:
Ekaale Baba,
E jowo, Oogun wo la ma fi nko ifa oore tabi oro ti a o ko moni?
jbabas
Ibere yin yen o fi gbogbo ara ye wa. E tun ibere yen ko lona ti yio gba ye wa.
Re: .. by Ifankaleluya: 8:46pm On Mar 12, 2016
skypeme:

ni bi odun melo kan seyin mo se alaba pade alfa kan fun iran lowo ati se aseyori, alfa ti mon so oro e yi si se jamba fun mi, gbo gbo aje sara ati iso to wa lara mi ni alfa yi baje. mo wa di eni ti ogun tete ran lese kese.

E ma fi se ibinu baba. Alfa yen fe ki e wa holy ni jawe.

1 Like

Re: .. by wale259(m): 11:51pm On Mar 12, 2016
Baba health,e jo se gbogbo igba lose na ni wiwe...
healthFirst:
141

IFA IWE ISE ATI OSI DANU
I I
II II
I. II
II. II OBARA DAGISE NU
Egbo akoko ewe re, epo re gbogbo re lara igi kan ao gun pelu ikode kan ao pomo ose dudu ti a ba fe lo ao te nifa OBARA DAGISE NU sori iwon ba ti a fe lo, ap wa pe ofore si.
OFO RE: Mo da sasa awo ile ogbo, mo wewe, mo we osi danu, awo eriki odan. O difa fun Orunmila ni ojo ti awon oso ati aje ngbero wipe awon yio di oran si orunmila lorun orunmila ni e kole di oran simi lorun Woni iwo orunmila jeka wo ohun ti awon kofi ni ledi oran si o lorun, orunmila ni ojo ti omode bati ja ewe pegunrun tosi wa egbo pegunrun ni gbogbo ohun ti o ba n se ni buburu yio pada leyin re emi__omo_moti jawe pegunrun mosi wa egbo re loni gbogbo ohun buruku ti o ba n se mi ko pa da leyin mi....ao wa fi we ao si sun kehikehin
re nina
Re: .. by wale259(m): 1:23am On Mar 13, 2016
Baba kaduna,ki ni a ma fi sa Ayajo yi,e salaye fun wa.
wale259:
Sir,kini a ma fi sa ayajo yii ati wipe ni gba wo la le ma sa?
Re: .. by jbabas: 3:12am On Mar 13, 2016
Ema binu, ibere mi ni wipe, se oogun wa ti eniyan fi npade orire tabi ola lai se osole?

jbabas
Re: .. by Ifankaleluya: 10:08am On Mar 13, 2016
@jbabas.

IFA(OGUN) WA TI ENIYAN FI MA N SE ORIRE, ORU NI A MA N WE OSE YEN. KODA TI A BA N WE OSE YEN LOWO, ENIKENI TO BA FI OJU KAN WA NI AKOKO YEN NA TUN MA SE ORIRE. ENIYAN MERINDINLOGUN(16) LO TUN MA SE ORIRE LEYIN YIN.

SUGBON BAWO NI A SE LE RI OKU-IMI~OSUMARE TI O JE ORIGINAL? ORI-ERANKO KAN TI WON N PE NI IRU. ANYWAY....KIISE OGUN TI MO LE FISILE LORI FANRAN YI RARA. SUGBON TI E BA RI OHUN TI MO SO YEN, E JE KA RIRA(lets see).
Re: .. by Ifankaleluya: 10:17am On Mar 13, 2016
Ifa ni,

Eni a ba ba wa ode la ba rele

Eni aja ba wa ni aja ma n ba lo

A difa fun orunmila

Ifa ni ohun o koju si akapo

Ifa koju si mi wo mi ire

Eji-koko iwori.

Eledumare yio koju rere si wa.

Ase-orisa lenu mi,eyi ti mo ba wi ni irunmonle yio gba,ase-orisa lenu mi.

Ela-boru,Ela-boye,Ela-bosise.

2 Likes

Re: .. by dominicson: 12:19pm On Mar 13, 2016
Ifankaleluya:
Ifa ni,

Eni a ba ba wa ode la ba rele

Eni aja ba wa ni aja ma n ba lo

A difa fun orunmila

Ifa ni ohun o koju si akapo

Ifa koju si mi wo mi ire

Eji-koko iwori.

Eledumare yio koju rere si wa.

Ase-orisa lenu mi,eyi ti mo ba wi ni irunmonle yio gba,ase-orisa lenu mi.

Ela-boru,Ela-boye,Ela-bosise.

Ope (do do) te ju mo mi, ko wo mi re

Ela te ju mo mi, ko wo mi re

Ori te ju mo mi, ko wo mi re

Eni t'o ba te ju mo, iru won ni l'aje

Eni t'o ba te ju mo, iru won ni l'aya

Eni t'o ba te ju mo, iru won ni di ogbo

Ope te ju mo mi, ki o wo mi re...

Ela boru, Ela boye, Ela bosise!

2 Likes

Re: .. by Ifankaleluya: 1:57pm On Mar 13, 2016
dominicson:

Ope (do do) te ju mo mi, ko wo mi re
Ela te ju mo mi, ko wo mi re
Ori te ju mo mi, ko wo mi re
Eni t'o ba te ju mo, iru won ni l'aje
Eni t'o ba te ju mo, iru won ni l'aya
Eni t'o ba te ju mo, iru won ni di ogbo
Ope te ju mo mi, ki o wo mi re...

Ela boru, Ela boye, Ela bosise!

O kare jare....iwo nikan loro mi ye.
Ori a gbo, Ori a to ooo.

3 Likes

Re: .. by dominicson: 2:34pm On Mar 13, 2016
Ifankaleluya:

O kare jare....iwo nikan loro mi ye.
Ori a gbo, Ori a to ooo.

Ogbo Edan
Ogbo Akokoniko
Ogbo Alawori!
Re: .. by Nobody: 3:20pm On Mar 13, 2016
Mo fe gba gbo gbo wa ni moran lori afefe yi, Gbo gbo awa ta ba ni asiri ogun to le, ogun bi AYETA, AMUDO, ati be be lo, mo gba wa ni moran pe ki a ma fi si ori afefe yi mo, to ri pe awon eni e ke ati eni bi won le ma lo fun ise ibi ta bi lati se jamba fun eniyan

I would like to advice everyone of us with very powerful charm, charms like BULLET PROOF, TOUCH AND FOLLOW ETC not to leave such on this trend again, it should be kept secret and save against the people who would like to abuse the charm, i saw some group of young boys age 16, 18 & 20 buying rings to be used for AMUDO / TOUCH & FOLLOW, They were even saying in yoruba that: ma doo omo birin yen laye, iya re a ba bebe

Meaning, I will Bleep that young girl and her mum will come begging. please kindly yield to my advice let us protect our loving yoruba charm not to fall into the wroung hands

2 Likes

Re: .. by kuddus: 3:58pm On Mar 13, 2016
e jo e fun wa ni ero eniti won ba na logun
Re: .. by MJAhmed(m): 4:39pm On Mar 13, 2016
skypeme:
Mo fe gba gbo gbo wa ni moran lori afefe yi, Gbo gbo awa ta ba ni asiri ogun to le, ogun bi AYETA, AMUDO, ati be be lo, mo gba wa ni moran pe ki a ma fi si ori afefe yi mo, to ri pe awon eni e ke ati eni bi won le ma lo fun ise ibi ta bi lati se jamba fun eniyan

I would like to advice everyone of us with very powerful charm, charms like BULLET PROOF, TOUCH AND FOLLOW ETC not to leave such on this trend again, it should be kept secret and save against the people who would like to abuse the charm, i saw some group of young boys age 16, 18 & 20 buying rings to be used for AMUDO / TOUCH & FOLLOW, They were even saying in yoruba that: ma doo omo birin yen laye, iya re a ba bebe

Meaning, I will Bleep that young girl and her mum will come begging. please kindly yield to my advice let us protect our loving yoruba charm not to fall into the wroung hands
I like this guy really made point thank you for this God bless you
Re: .. by Zenlife: 3:12am On Mar 14, 2016
Ifankaleluya:
Ifa ni,

Eni a ba ba wa ode la ba rele

Eni aja ba wa ni aja ma n ba lo

A difa fun orunmila

Ifa ni ohun o koju si akapo

Ifa koju si mi wo mi ire

Eji-koko iwori.

Eledumare yio koju rere si wa.

Ase-orisa lenu mi,eyi ti mo ba wi ni irunmonle yio gba,ase-orisa lenu mi.

Ela-boru,Ela-boye,Ela-bosise.

Baba Ifankaleluya, ejowo e fun wa no oogun obinrin ti ko kin yan ale re (to make a disrespectful wife always respect and honor the husband) to daju. E se sir.

(1) (2) (3) ... (61) (62) (63) (64) (65) (66) (67) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 50
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.