₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,325,413 members, 8,421,801 topics. Date: Sunday, 07 June 2026 at 04:46 AM

Toggle theme

ONILEIFA's Posts

Nairaland ForumONILEIFA's ProfileONILEIFA's Posts

1 2 (of 2 pages)

CultureRe: .. by ONILEIFA: 7:05pm On Feb 28, 2016
Ìbà o, Obatala, Oba taasa,
Oba patapata lode Iranje,
Ìbà Iranje’le Iba Iranje oko,
Ìbà Ifon-Osun,
Ìbà Igbin, Iba Igbin-Oosa,
Ìbà Alágemo-téérekangé,
Je a gbo Je a to;
Ìbà Abamoda omo Oosa-Agbowujin,
Mo daba ire aje, ire aya/oko, ire omo, ire gbogbo,
Aba ti Alagemo bada lOosa-Oke n gba,
Ìbà Gunyan gunyan ile Ido,
Ìbà rokaroka obinrin Ibadan,
Ìbà Aje tii n somo Olu-Ibini,
Ìbà Okun tii n somo Ode-Irada,
Ìbà Orò, òròpòtò pómùpómù,
Tobi ‘mo léweléwe ti kan kan o sofun,
Ìbà Osanyin –mògbòráyè, To gba opa lowo olókùnrùn sanu.
Aye mo juba é jé ki o ju mi sé
CultureRe: .. by ONILEIFA: 7:03pm On Feb 28, 2016
[quote author=Ifankaleluya post=43334982][/quote]Eyi owun e wi mi o ni lo lati ba yin jiyan rara to ri wipe eyin ni aroni lale odo
RomanceRe: Guy With No Car At 26 Irresponsible? Some Girls Still Think Like This In 2016? by ONILEIFA: 3:57pm On Feb 28, 2016
oluwasegun007:
I wish to give that lady who replied her a big kiss...
You say it all bro
CultureRe: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA(op):
Ìbà Orí-eni,
Ìbà Ikin-eni,
Ìbà Baba,
Ìbà Yeye,
Ìbà Oluwo,
Ìbà Ojùgbònà,
Ìbà Ipárípá adáso-mámùró
Ìbà èyin ìsòrò-Òrun
Ìbà ará Ilè.
European Football (EPL, UEFA, La Liga)Re: Manchester United Vs Arsenal (3 - 2) On 28th February 2016 by ONILEIFA: 3:46pm On Feb 28, 2016
God Nooooo
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ONILEIFA:
[AGADAGODO TI KIIJE KENU ENU ENIYAN KO

Iye igun, iye agbe, ...Ekan si mi ..., etu ibon die[not original one], atare odindin kan, ao jo po, ao waabu sinu efe owu. ao fi owu dudu ati funfun we. ao waa so mo agadagodo.
*OFORE*
Moda ofa meta mo mu ikan mofita igun, igun ni enu won koni gun, modafa meta mo mu ...efi number sile fun iyoku....., modafa meta mo mu ikan mofita agbe lenu, agbe loni odi igbo rere, etu loni kiwon tuka.




Aye wa fun ibere tabi so unkan ti oba ru yin ni oju.
CultureRe: .. by ONILEIFA:
[AGADAGODO TI KIIJE KENU ENU ENIYAN KO

Iye igun, iye agbe, ...Ekan si mi ..., etu ibon die[not original one], atare odindin kan, ao jo po, ao waabu sinu efe owu. ao fi owu dudu ati funfun we. ao waa so mo agadagodo.
*OFORE*
Moda ofa meta mo mu ikan mofita igun, igun ni enu won koni gun, modafa meta mo mu ...efi number sile fun iyoku....., modafa meta mo mu ikan mofita agbe lenu, agbe loni odi igbo rere, etu loni kiwon tuka.



Aye wa fun ibere tabi so unkan ti oba ru yin ni oju.
CultureRe: .. by ONILEIFA: 3:36pm On Feb 28, 2016
*OGUN ARUNMOLEEGUN*
ANY OF THESE:-
1. eku aisan, Aidan, ipeta, iroyin,epo igi boni, ao gun won papo mo ose dudu, wiwe nio.
2. Egbo owo, ata dudu, alubosa jije, ao gun papo, ao wa sagbe, ao mafi mu eko.
3. epo igi Omo, ewe ekanse adie, ao se, mimu ati wiwe.


Fun Alaye Kikun Ekan si mi
HealthRe: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ONILEIFA: 3:35pm On Feb 28, 2016
*OGUN ARUNMOLEEGUN*
ANY OF THESE:-
1. eku aisan, Aidan, ipeta, iroyin,epo igi boni, ao gun won papo mo ose dudu, wiwe nio.
2. Egbo owo, ata dudu, alubosa jije, ao gun papo, ao wa sagbe, ao mafi mu eko.
3. epo igi Omo, ewe ekanse adie, ao se, mimu ati wiwe.


Fun Alaye Kikun Ekan si mi
CultureRe: .. by ONILEIFA: 3:33pm On Feb 28, 2016
Ogbe ate
| |
| |
| ||
| |
Kadiju kase bii eni ku,
Kawo eni tio sunkun eni....
CultureRe: .. by ONILEIFA: 3:19pm On Feb 28, 2016
#1

EBO AYE TODAJU*
Eyin meje,
Odidi Okete,
Orogbo meje,
Eyin Open meje,
Oti ati epo,
Awo sobi kan,
Ao fi Ifa osa meji koru,
Otan.


#2
OOgun Atepa
ESE pepeye mejeeji, ao pelu odidi atare kan, ao wafi sin ESE mejeeji yika.

#3

Owo(respect) fun ole:-
Igi Abo, ao fi nu idi, ao fi aso funfun di ni ikobere, ao wafiko ibi ti aba nso.
Ole koni wo ibi ile ti aba fiko laelae.
NB:- (for vengeance) Atun leefi gba esan, eni to fe fi GBA esan korimi
CultureRe: LILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA(op): 3:17pm On Feb 28, 2016
#4

OGUN IRISE
Epo Obo, ewe sawerepepe, so gun papo, so po no ose, ao po iyo die mo,ao mafi obe(knife) by ose na diedie, so mafi we.


#5
Ogun ti ibale fin pada Sara obinrin( to regain virginity>
Ewe ege were, owu Elena, lilopo, ao fipa ara eyin adie, ao fi owu Elena yi eyin adie na, ao fi aso osu ti obinrin na lo lowolowo we lawetan, ao mulo sinu okiti ogan, ti okiti ogan yi babo, ibale(virginity) yio padabo Sibe.

#6
<OGUN KI OBINRIN MABI ABIKU MO>
Egbo sapo, egbo peregun, ako eyele, ose, igba olomori, ao ha ara awon egbo yen, ao gun mo ose dudu, ao la eyele yen laya, a ko ose yen sinu aya eyele yen, ao wa gbe sinu igba olomori yen, obinrin tabi omo tobi naa yio mafiwe.
Ofore :- Ododun ni sapo nwu ewe, ososo ni peregun nse ofo iyare, ako eyele kini isimi, gbogbo eni toba nse oun buburu simi koma ni isimi.


#7
<Ogun ki ole mawole>
Ori ako alangba, ao la enu ako alangba, ao ti odidi atare aja kan bo lenu, ao fi owu dundun ati funfun we, ao fiko si enu ona.
CultureLILO OGUN IBILE FUN ITOJU,IWOSAN ATI ASEYORI by ONILEIFA(op):
The name of the founder of this great page is Eniola Onileifa . Am very jovial and caring person but highly disciplined.
Email: tomiwag@gmail.com Phone: 08179322228

Oro ikilo: Ako fi aye gba enikeni lati fi ogun jade lori ikani yi lai gba ase..

*AIMS OF THIS POWERFUL PAGE*
(1) TO PROMOTE AFRICAN CULTURE AND TRADITION
(2) TO HELP PEOPLE WHO NEED SPIRITUAL ATTENTION
(3) TO ALLEVIATE POVERTY AND PENURY BY SPIRITUAL MEANS
(4) TO PRESERVE AND CONSERVE THE SACRED POWERS OF OUR FOREFATHERS
(5) TO SERVE AS PLATFORM FOR INDIVIDUAL WHO HAS SPIRITUAL KNOWLEDGE SHARE WITH THE WORLD




#1

EBO AYE TODAJU*
Eyin meje,
Odidi Okete,
Orogbo meje,
Eyin Open meje,
Oti ati epo,
Awo sobi kan,
Ao fi Ifa osa meji koru,
Otan.


#2
OOgun Atepa
ESE pepeye mejeeji, ao pelu odidi atare kan, ao wafi sin ESE mejeeji yika.

#3

Owo(respect) fun ole:-
Igi Abo, ao fi nu idi, ao fi aso funfun di ni ikobere, ao wafiko ibi ti aba nso.
Ole koni wo ibi ile ti aba fiko laelae.
NB:- (for vengeance) Atun leefi gba esan, eni to fe fi GBA esan korimi

1 2 (of 2 pages)